Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,227,625 members, 8,071,014 topics. Date: Wednesday, 05 February 2025 at 01:46 PM |
Nairaland Forum / Kadunasouth's Profile / Kadunasouth's Posts
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 17 pages)
Health / Re: Dream Says Lot About Your Life Knows Yours Interpretation by kadunasouth(m): 3:56pm On Feb 16, 2016 |
Complement of season to all the fans on NL There were series of calls day to day asking question about seeing vagina or male organ in a dream, for the benefit of questioners, I decided to put together dream related to vagina or penis 1. Vagina in a dream means relief for person who is facing challenge, sorrow,pressure, difficulty,or hardship, 2 It could also signify satisfaction and fulfilment of one's desire marriage or relationship or exposing of a secrete. 3 If a man look at woman vagina in a dream it represented the high standard woman has achieved in his eyes, it hawever atime could mean his wicked state of mind. 4 If a woman look at a man's sexual organ in a dream it represent her strength and manlike drive. 5 If a prisoner or a man in bondage find himself having a vagina in a dream it means his release from prison or loose from bondage or someone Who is depressed it means relif from his depression. If one has to appear in court of law, means he will win his case, or is facing an opponent it means that he will conquer him. 6 But seeing the vagina of an elderly woman in a dream means loss of business. 7 If one re enters the womb of a woman through her vagina in a dream it means his death. 8 A man with a vagina in a dream: He is not faring well and is being humiliated orthe reverse. But if he has worries or in jail he will be freed 9 Sucking or licking the wife vagina: Is a minor relief 10 Biting the vagina of an unknow woman in a dream it mean relief and joy 11 If a woman dream that fire is coming out of her vagina, means she will give birth to a king For enquiry call 09090305775 3 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 1:24pm On Feb 16, 2016 |
belatoxx:Imi gbigbe(igbe ti wan ya sori atan toti gbe dada) 3 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:54am On Feb 16, 2016 |
aktab:Eyin adie ibile (adie tiwan sin nile) to sese ye ti koti baje niwan peni eyin ororo 2 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:11pm On Feb 15, 2016 |
belatoxx: Ogun fun Oniwa npale ati omuti ati iwakiwa ti afe kiwan fi iwa na sile Akara ori atan pelu odidi atare kan ao jo ao lo yio kuna ao wa lo sugar onikoro 7/9 meje fun okunrin, mesan fun obinrin yio ma la koto ba eniyan soro laro kutu, gbogbo iwa ti kodara leni na yio kosile 5 Likes 3 Shares |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 3:12pm On Feb 15, 2016 |
Eyonu Asina Kowe kan, eye kanakana kan, eye elulu, okete oojo eyin adie ororo mewa, epo obo, ewe ewuro oojo, ao jo po ao ma fi ogere epo pupa la ni aro ati ale 5 Likes 2 Shares |
Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 11:35pm On Feb 13, 2016 |
Beeni lepo niyo [quote author=gbengaeba007 post=42895587][/quote] 3 Likes |
Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 11:32pm On Feb 13, 2016 |
[quote author=gbengaeba007 post=42895489][/quote] Beeni lepo niyo 1 Like |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:07pm On Feb 12, 2016 |
Bosville:Awure ati Arisiki wan jo arawon sugbon iyato die wa nibe gbo gbo eniyan lole se ogun arisiki sugbon kokin se gbogbo eyan lole se awure, awure wa fun onise owo ki ise re le gboro ki opolopo awan eyan ma wa be nise, ati onisowo ati oludasile ile eko ki awan omo akeko le po dada ati bebelo oluko ilewe kolese awure yio kan man sise fun onise ni sugbon olese arisiki yio mari anu gba lodo awan eyan osise ijoba kolese awure sugbon olese arisiki yio ri anu ati igbega lenu ise laifa orogun gbogbo eniyan lolese arisiki sugbon ki ise gbogbo eyan lolese awure, sugbon gbogbo eniyan tulese awure ti akoba bikita lati gbe oriyin fun ilese ti ki se tiwa bi apejuwe sale girl tolose awure oun gba egberun mewa losu sugbon oun wata oja million fun ogare pelu awure tose seriwipe oga nilosiwaju oun faseyin, sugbon tobase arisiki yio pade alanu, Sugbon awure na tun pe lorisi risi, awure owo itaja okiki pebelo otun depend ti kobaye ole pemi fun ekunrere alaye, abi kio kan simi lori ero aye lujara 7 Likes 4 Shares |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:31am On Feb 11, 2016 |
Gbere Ebe Awon Agba Igo ngori ewe Agogo igun ao ja 99 odidid atare kan ao jo papo ao fi sin gbere si igbaya otun gbere meta, eyin meta, igbaya osi meta eyin igbaya osi na meta opari odaju 6 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:57pm On Feb 10, 2016 |
Ogun Arisiki Aidan meji Epo obo Atare odidi kan ao jo papo ao ma to sowo pelu adua ao ma fi omin lo lararo 7 Likes 2 Shares |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:47am On Feb 10, 2016 |
Eyonu todaju Epo obo, igi Asorin, Ewe ola ao lo gbogbo re papo ao da sinu lonfida ao ma fi ra owo ati oju die die A W U R E Eyonu odara pupo Ewe ewuro taja lojo eru alamo, epo obo ao gun gbogbore papo ma ose ao fi ororo malu ati ori po, ao ma fi we lararo pelu adua nkan to ba fe 7 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:27pm On Feb 09, 2016 |
aktab:Ojo meta lao filo 2 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:23pm On Feb 09, 2016 |
Ogun ta nfi gbe Aburu kuro lara tabi inu ile Isu gbegbe odidi atare kan ao jo papo ao fi ro ekuru je opari 7 Likes 2 Shares |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 3:32pm On Feb 09, 2016 |
Ogun Agbana ati Anabo todaju reo! Ati ki owo le duro lowo wa odaju Egbo ako ati abo rere ao lore wu lagokan osan alubosa elewe odidi atare kan ao jo ao fi sin gbere yipo orun owo wa mejeji Opo eniyan lolelo ninu iseyi Ti oba ri gbere yi sin kosiye meji nibe oti segun agbana niye o Ibare olodumare Iba agbagba 6 Likes 2 Shares |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 2:15pm On Feb 09, 2016 |
Atude ati Asina kia kia Egbo tude ako eye iga, odidi atare ao jo ao lo yio kuna ao ma fi ogede omini je ebu na die die ise yi daju dada 5 Likes 2 Shares |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:21am On Feb 09, 2016 |
Ogun itaja Ajesi adie ati oko atare kan ao lo papo month epo obo ao gun month ose dudu taba gun tan ao fi epo obo gun ose na lori leyin ojo keta tati se ogun yi lao wa bere si nilo ao ma fi we opari 5 Likes 2 Shares |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:13pm On Feb 08, 2016 |
Ogun isoye Ewe eran die kuluso 7/9 (obinrib/okunrin) eja abori ao jo ao mafi fo eko tutu mu die die lalale 4 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:06pm On Feb 08, 2016 |
Ose itaja Egbo tude ata pupa ati ata dudu ao gun ao pomo ose dudu ao ma fiwe Ikilo ata die die lama lo bi eyo meta meta kogbodo poju koma ba ma tawa lara ale fi epo rara kato mawe odaju 6 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 4:43am On Feb 08, 2016 |
Awise Ewe ogbo ewe alupaida eyo atare kan ao lo ao fi sin gbere si isale ete wa, gbere eyokan lago kan oru lojo sunday, ebu toba ku ao fe sinu ategun 7 Likes 3 Shares |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:30pm On Feb 07, 2016 |
Awure ati Asiri bibo Epo obo ao lo kuna dada ao fi omin agban po month ose dudu ao ko sinu awo ipese awo dudu ao ma fiwe 4 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 5:26am On Feb 07, 2016 |
Atude Asina todaju Ewe tude Egbo tude Epo obo ao gun gbogbo re month ose ti aba ti fe sun ni ale ojo alakoko ao fi epo rara ojo keji ao fi ori rara ojo keta ao fi oyin rara kato lore mawe odaju 5 Likes 2 Shares |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 4:55am On Feb 07, 2016 |
Turare Jalabi, Itaja, Afa orewole Odara Fun Onile ati Onirin Ajo Ori Agiliti, ori aparo, ori musu eyi toni irun, Ewe ajade, eru alamo, koro owu kopo die, oyin bi sibi meji ao gun gbogbo re sakasaka ao mafi lararo Danwo oje bi idan 5 Likes 3 Shares |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:49pm On Feb 06, 2016 |
Ogun Itaja 1 Egugun agbari aja ao lo po ma ewe ola ao lo yio kuna dada ao da si inu ipara ao popo dada ao tun wa da turare to balorun si ao ma fi para losi ibi ojawa ata jere lao ma ta o amin Ase iba fun gbogbo eyin agbagba oju anu ni kie mafi womi omo yin ni month nse mojuba o! Itaja 2 Opolopo ewe sawerepepe ati opolopo ibose adie odidi atare kan ao jo papo ao ma da sinu omin fi wan le lararo eleyi daju, tabati fi wan le bayi ero abere si mawa raja nio iba eyin ajunilo ti ekolo bajuba ile ile alanu nio efi oju ire womi 7 Likes 3 Shares |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:03pm On Feb 02, 2016 |
Asiri Ola (ki ona owo le lakanwa) Ako ati Abo eye ega owo eyo mesan ewe ola ati ewe sawerepepe odidi atare kan ao ko gbogbore sinu fitila oloju merindinlogun inure lao tijo ao lo ao mafi miliki lo lararo iseyi daju fun owo ati okiki and connection 7 Likes 2 Shares |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 12:10am On Feb 02, 2016 |
Notice! Notice!! Notice!!! Read and ask not side effect of my post OSO... also called money rituals or blood money. Some people don't know the differences between oshole and awure.. oso is what they use human being for the preparation of the wealth... and some of the results of oso it's. . E.g.. to see money inside big pot by chanting the name of the person you used. The money will dissappear inside the pot within some hours. And also can be used by sending ghost or spirit of such person to goto the bank or anywhere to bring u huge money.. or carried calabash on top of such person head and be picking money And it has big repercussions like. E.g.. not live long. Suddenly death. .earing ghost voices anywhere you go. And some people's got mad immediately they did it. Because it's not compatible with his star...... beware of wicked people they will told you that it's basiri ( good fortune ) or oshole ( wealth booster ) what u have to notice from their talk. It's to know how it will work for you. Once u detect how it will works. So try and run for your life.... OSHOLE or AWURE NLA or AKO AWURE or OSHOLE TUTU ( wealth booster) this is the best thing to do it has no repercussions and powerful than AWURE.. any OSHOLE it's require ANIMALS AND SOME LEAFS OR BARKS no human blood shed.. it's good for those who is looking for progress especially the person that has the particular job that his doing. Oshole can not drop money in front of you oo.. it's not a magic or miracle it will just boost you work and your progress. AWURE ALSO CALLED APEDE. ... Awure it's good it's also work for progress of anything human being his doing.. it's has no blood shed of HUMAN BEING or ANIMALS. It's only has some leafs , barks .. and anything that has no blood.. though some required Ants.insect..e.t.c no repercussions N:B... my advice for people's that is reading this blog. Is to be careful of all those uselss people that need you to run business. Everybody need money. Why can't he did it for himself.. so be careful thanks..... 9 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:01pm On Jan 29, 2016 |
ATUDE Ewe akoko ati ewe ewuro ao gbo ao mu die ao fi iyoku we opari 4 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:17pm On Jan 25, 2016 |
Atude Asina Omundun ewe akoko 9 ata ijosi eyokan ao gun papo ma ose talewe tan lekan soso ao fiwe 5 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 1:47pm On Jan 25, 2016 |
Ifadamilola30:Beeni. Ao fi ha lapa mejeji ikan lapa otun ikan lapa osi 4 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 12:31pm On Jan 24, 2016 |
ẸYỌNU AWỌN AGBA Ifunni ekete kan, egbo akerejupon , ati ewe ajẹọbale, ao jo papọ̀, ao po ma ọṣẹ dudu oni apo nkan, ao ma fiwẹ leralera. 5 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:25pm On Jan 23, 2016 |
Iferan (General love) Itun ati ifa, abere, ewe ola, itanna tanapowo ao lo gbogbo re papo ao pomo ipara ao fi turare toba lorun to dara si ao popo ao ma fi para, opo eniyan lelo 3 Likes 1 Share |
Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 10:46pm On Jan 22, 2016 |
gbengaeba007:Ninu nkan ti eka se wan daruko atare miran ni, atare kan oga kan Lemajo, eleyi onidi ibere rara ati rara |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 17 pages)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2025 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 38 |