Stats: 3,250,710 members, 8,143,937 topics. Date: Thursday, 24 April 2025 at 08:13 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1860709 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by Nobody: 9:46pm On Apr 30, 2015 |
E seun gan fun idaun yin. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 7:44am On May 02, 2015 |
... 1 Like 1 Share |
Re: .. by Nobody: 10:36am On May 02, 2015 |
... 3 Likes |
Re: .. by Nobody: 12:27pm On May 02, 2015 |
Ewe ati egbo yi o ma je. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 12:54pm On May 02, 2015 |
walexy30: Ase Wa! |
Re: .. by absoluteSuccess: 7:34pm On May 02, 2015 |
healthFirst: awon eniyan buburu ti ba eniyan rere je, o se. |
Re: .. by Nobody: 11:29am On May 03, 2015 |
Ejoor, seh e ni oogun afose? |
Re: .. by Nobody: 7:20pm On May 03, 2015 |
Re: .. by Nobody: 3:19pm On May 04, 2015 |
... 3 Likes 1 Share |
Re: .. by Nobody: 6:14pm On May 04, 2015 |
healthFirst: Mo kan leero pe oye kamoo nooni oo. Sugbon tie ba lero pe koye ke fi sori afefe, ema fisi ooo |
Re: .. by Nobody: 9:00pm On May 04, 2015 |
Jadonjack: O da...a ma fi sita laipe |
Re: .. by Nobody: 4:28pm On May 06, 2015 |
Ejowo, mo nilo ogun ikiya.. Aya mi man tete jah ju |
Re: .. by Nobody: 10:35am On May 07, 2015 |
E JOWO, TI OWU ALANTAKUN BA NKO ENIYAN LOJU ATI OWO NI GBAGEDE, IRU IPA WO LO NKO NI IGBESI AIYE ENIYAN ATI WIPE KINI ONA ABAYO. NITORI MO GBO WIPE O NI NKAN TI AWON BABA WA MA NSE LAIYE IJOUN SI IRU NKAN BAYI. E JOWO , E BA WA SE IWADI LORI RE, NITORI EYI NFA IFASEYIN FUN OPOLOPO ENIYAN. E SE. |
Re: .. by Nobody: 10:03pm On May 07, 2015 |
... 1 Like |
Re: .. by Nobody: 10:56pm On May 07, 2015 |
... 3 Likes |
Re: .. by kadunasouth(m): 8:04am On May 08, 2015 |
[quote author=healthFirst post=33411411]19 IFUNPA YI SISE FUN OWO O TUN SISE FUN TI OPO ENIYAN BA FE BA WA JA Ipe Oore meje ori ikun nla kan akisa. Ori ataan odidi ataare kan. Ao so akisan na si inu omi ao jo awon eroja yoku ti o ba ti fe jo tan, ao yo akisa na, ao ju si inu ogun na... ti o ba wa jo tan ao bu si inu aso funfun, ao di ni owu dudu ati funfun ao wa lo ran ni odi awo funfun ni ifunpa... ogun yi sise fun owo, amo ti won ba fe ba wa ja ao ma fi owo yi ifunpa yi ao ma pe ofore si.... ikun loni ki apa okun yin. Oore loni ki oore yin wesi. Bi akisa ba bo somi wesi nire. Won a kan ma wo booo ni, won koni le se ikankan fun wa titi ao fi koja !!! [/edakun se gbo gbo ebuyi lamalo fun iyokan abi abu die nibe ni 6 Likes 1 Share |
Re: .. by kadunasouth(m): 8:17am On May 08, 2015 |
Mokiyin pupo Edakun se gbogbo ebuyi lamalotan lekan soso abi ale budie ninure tamafi ebu kan se si bi ona meta |
Re: .. by Nobody: 2:15pm On May 08, 2015 |
healthFirst: Ese pupo. Ejoor, bi odun melo ni o ma lo lara eeyan ko to baje, ati pe kin tun ni ohun to le ba oogun yi je lara eeyan? Atipe, bawo ni mo sele ri okuta sango? Emi gangan ni mo fee lo oogun yi. Ejoor e ran mi lowo. ESE GAN!!! 3 Likes |
Re: .. by Nobody: 9:03pm On May 08, 2015 |
healthFirst: E SE PUPO 3 Likes 1 Share |
Re: .. by Nobody: 12:08pm On May 09, 2015 |
Jadonjack: A le ri Okuta Sango ni leele a si tun le ri ra lodo awon elewe omo. E le maa se Oogun yi ni bi Odun meta meta. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 12:09pm On May 09, 2015 |
kadunasouth: Beeni, gbogbo e la nilati lo leekan 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 11:08pm On May 09, 2015 |
kadunasouth: Rara o, ao fe aago lori ibi o. e jowo e yo ero ibanisoro yen kuro kiakia. 3 Likes |
Re: .. by Nobody: 6:28am On May 11, 2015 |
healthFirst: Eseun gan |
Re: .. by Nobody: 9:41am On May 11, 2015 |
[quote author=kadunasouth post=33578685]Iyonu Odaju Enu opiye alubosa elewe eru alamo oko atare kan ao gun po aso egun ori adi epo ao fi orun yo ao fi aso egun tele konjo (idi konjo na kogbodo kanle alegbesi inu roba ao mafi para). OFORE Ojoti adi bafi oju kan orun ojona ni oro inure yo, ojoti epo ori bafi ojukan orun ojona ni oro inure yo Atewe Atagba ni teriba fun Egun ki omode ati Agbalagba ki wan o ma teriba fun emi (L omo L). Contact [/quo E joo e ba wa yo ero ibanisoro yi kuro tabi ki n fi ejo yin sun awon oludari 3 Likes |
Re: .. by Lionhearted: 4:30pm On May 11, 2015 |
Eku ise o. Ki le yan le lo toba ni yeast infection/candida to tipe lara? |
Re: .. by OROSUNBOLB(m): 10:27pm On May 11, 2015 |
Mo gbadun abala yi gan ni o! Odua afewonro yio gbe wa o! E da kun e ma je ki o re yin o. Opolopo anfani ni a ti ri je ninun e. Yi o si tun je ki imon ewe ati egbo ki o kun si. Aboru,boye o Baba! |
Re: .. by Nobody: 12:33am On May 12, 2015 |
... 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 12:35am On May 12, 2015 |
OROSUNBOLB: Aboru Bo sise. E seun o. |
Re: .. by Nobody: 12:51am On May 12, 2015 |
.. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 1:21am On May 12, 2015 |
.. 1 Like |
Re: .. by Lionhearted: 3:28am On May 12, 2015 |
healthFirst: Eseun gan ni. Ogun la le lo fun Oral thrush ati te 'yan ba ni blocked sinuses? 2 Likes |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2025 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 32 |