Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,201,388 members, 7,978,240 topics. Date: Thursday, 17 October 2024 at 11:22 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1843619 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by bright991: 8:26am On May 12, 2015 |
. |
Re: .. by Nobody: 10:10am On May 12, 2015 |
Lionhearted: Oral Trush....Ifun Enu ati Blocked Sinuses...Osi Imun ati ti Aya...A ma post won ti n ba pada de Ile. |
Re: .. by Nobody: 10:14am On May 12, 2015 |
bright991: Mo mon wipe awon kan le wa ti won ko ni le se awon Oogun yi funrawon...bi e ba fe ki n ba yin se, e e-mail mi, e joo ori abala yi kii se fun ipolowo oja. Sugbon, e gbiyanju lati se funrayin...Ipara yen dara pupo fun ebe awon agba. E lo si odo awon elewe omo, ki e beere awon eroja Oogun te ba fe se...bi e ba ra lowo won, e le be won ki won ba yin jo won papo tabi gun won po ki e to kuro nibe. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 11:03am On May 12, 2015 |
.. 3 Likes |
Re: .. by OROSUNBOLB(m): 12:03pm On May 12, 2015 |
E ku ise o Baba. E da kun ki ni ale lo si idi yiyo ti yio fi wole pada? E seun o. |
Re: .. by Nobody: 1:22pm On May 12, 2015 |
... 1 Like |
Re: .. by Nobody: 2:37pm On May 12, 2015 |
healthFirst: Ejoor, sehbi jankariwo ni owu alantakun? Atipe, seh oga to ti ku fun ojo pipe abi eleyi to sese ku ni kia lo? 3 Likes |
Re: .. by Nobody: 2:49pm On May 12, 2015 |
Jadonjack: beeni, ijakariwo ni a n pe ni owu alantakun. ko sa ti je oku Oga 1 Like |
Re: .. by Nobody: 4:10pm On May 12, 2015 |
healthFirst: Eseun 1 Like |
Re: .. by ejidewa87: 8:22pm On May 12, 2015 |
E dakun se e le ko wa ni ogun ife |
Re: .. by bright991: 9:32pm On May 12, 2015 |
. |
Re: .. by Nobody: 11:59pm On May 12, 2015 |
.. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 12:26am On May 13, 2015 |
.. 3 Likes |
Re: .. by OROSUNBOLB(m): 2:49am On May 13, 2015 |
healthFirst: E seun o baba. Ewe a ma je o. 5 Likes |
Re: .. by Lionhearted: 4:53am On May 13, 2015 |
healthFirst: Eseun gan ni. Se gbogbo awon nkan won yi la le ri ra? 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 9:27am On May 13, 2015 |
Lionhearted: Beeni...opolopo ninu awon egbogi wonyi lo wa ni agbegbe wa sugbon a le ri won ra lowo awon elewe omo. 1 Like |
Re: .. by scholes0(m): 10:48am On May 13, 2015 |
healthFirst: Tabi ni odo awon ti o ba n ta "iwoshiwoshi" ni oja..... Eni ti o ba fe ra ori tabi Iru agemo gan a ri nibe.... 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 1:06pm On May 15, 2015 |
BELEJE E teti beleje o, ke gbohun tawo o gbodo se, Awo kii paro o. Awo kii dale awo. Awo kii san bante awo egbe re o. Egbe re laake o. Eegbe re looko o. Egbe re lola. Tofi dele owa orangun olomo. Oogboye o!. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 1:14pm On May 15, 2015 |
... 1 Like |
Re: .. by Nobody: 3:40pm On May 15, 2015 |
Ejorwo, e maa so awon eewo ti awon ogun yi ni fun wa kia le ma kiyesara ti a ban se won 1 Like |
Re: .. by Nobody: 5:20pm On May 15, 2015 |
Jadonjack: Awon eewo ti o wa nidi Oogun sise wa looto...ninu re ni wipe bi Oogun ba wa lara wa, ko dara ki a sun mo Obinrin to ba n se nkan osu lowo. Omiran ni wipe bi a ba n gun tabi jo Oogun lowo, Omo Olo ti a fi nlo Oogun yi ko gbudu duro lori Oogun na tabi Omo Odo ti a fi n gun Oogun ninu Iya Odo ko gbudo duro lori Oogun ti a n gun lowo ninu Odo. Ao ma ko won sita ni bi a ba se ranti. E joo bi eyin na ba mon lara awon eewo wonyi, e ko sita fun wa. Sugbon awon eewo to ro mo oogun kookan wa loto...Oogun to ni eewo tire loto, ao ko pelu re. 4 Likes |
Re: .. by gawab: 2:12pm On May 16, 2015 |
healthFirst:E jowo asiko ni enia le lo egbogi yi? Se enia le lo losan? Se gbogbo ebu ti a jo ni a o lo lekan na? 1 Like |
Re: .. by Nobody: 2:43pm On May 16, 2015 |
healthFirst: Oda, eseun 2 Likes |
Re: .. by nisai: 3:36pm On May 17, 2015 |
Kepe baba.Ejowo se ele fun mi ni aparun ati apagun? |
Re: .. by gawab: 9:27am On May 18, 2015 |
gawab: |
Re: .. by Nobody: 10:27am On May 18, 2015 |
healthFirst: Eruwadaji! Eku ise, Olodumare a ma ro yin l'agbara. Ni afikun si awon eewo ti eti ko won yi: 1. A ko gbudo ni ibalopo rara ti a ba fe gun, jo tabi lo oogub (boya ni nkan osu tabi mimora). 2. Obinrin to ba nse nkan osu ko gbudo fi pwo kan eroja ogun kan kan tabi nkan ti a ba fe fi gun, ge tabi lor. Kosi tun gbudo fi owo or ara kan oogun taba ti pese tan. Ni tootor, oogun kankan ni eewo re ti a ban ja ewe re, ti aba fe gun, jo tabi lor, ati eewo lilo naa. Boya ki eku ma fi awon eewo si ese awon oogun ti e kor si ori ibibi. 3 Likes |
Re: .. by Nobody: 11:43am On May 18, 2015 |
gawab: Asiko to ba wun wa la le se Oogun yi sugbon bi ba se nise temi ni, Oru Oganjo ni o dara ju. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 4:05pm On May 18, 2015 |
.. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 4:13pm On May 18, 2015 |
.. 6 Likes 2 Shares |
Re: .. by mhicrotee: 5:19pm On May 18, 2015 |
E jowo mo nilo iranlowo yin,ara ile mi kan nse aare(she is sick),mo de waa funra pe ti mo ba daa ina tan yio waa mu eyin ina(hot charcoal) ti mo fi dana kuu,e jowo se ko si ewu nibe(Am I safe)? e jowo e dahun Kia kia |
Re: .. by scholes0(m): 5:56pm On May 18, 2015 |
healthFirst: Haa!! Imo ati asa Yoruba leke, O ta gbogbo awon iyoku yo. |
Re: .. by scholes0(m): 6:00pm On May 18, 2015 |
mhicrotee: 1 Like |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply)
Viewing this topic: 1 guest(s)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 39 |