Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,201,381 members, 7,978,219 topics. Date: Thursday, 17 October 2024 at 10:17 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1843610 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by Nobody: 6:23pm On May 18, 2015 |
mhicrotee: Hmmm...ko si wahala fun yin rara. |
Re: .. by Nobody: 6:25pm On May 18, 2015 |
scholes0: Beeni...ohun to daju saka ni...Imo ati Asa Yoruba kii se egbe gbogbo won. |
Re: .. by scholes0(m): 6:39pm On May 18, 2015 |
healthFirst: Ododo oro. Nigba miran ti n ba beju weyin, ti mo wo gbogbo Asa, Imo ati Ise ti awon baba nla wa fi sile fun wa, mo maa n gboriyin fun won, tori ise ribiribi won ninu okan mi. O wa ku si owo wa bayii, lati ri wipe gbogbo awon ohun asa isedale ati isenbaye wonyii, ko ni di nkan Ipadanu ni ojo iwaju. Ki a ma baa kabamo ni ojo ola wipe: "Haa!! a ba ti mo, awa nba ti se itoju gbogbo nkan asa wonyii. E ku ise ewe ati egbogi .... 2 Likes 1 Share |
Re: .. by mhicrotee: 7:12pm On May 18, 2015 |
healthFirst:Ah !!!! |
Re: .. by scholes0(m): 7:17pm On May 18, 2015 |
Re: .. by nisai: 7:30pm On May 18, 2015 |
Nko ri idahun yin si ibere mi nipa Aparun ati Ap'ogun.Mo lero pe ibere mi yen koda to? |
Re: .. by Nobody: 7:36pm On May 18, 2015 |
scholes0: Hmmm..Oro ijinle le so yi...looto alagemo ti bimo re na, ai mo jo ku sowo omo alagemo. Bi a ba ro arojinle nipa bi awon baba nla wa se se iwadi awon asa wonyi, yio je ohun iyalenu fun wa nitori wipe imon ijinle patapata ni awon Imo ati ise wonyi. Eto abala yi je ikan lara igbese lati rii wipe awon Imo ati Ise wonyi ko di ohun igbagbe laarin awa omo Yoruba. E je ki a fi owo so owo po lati te siwaju ati lati gbe asa wa laruge ni gbogbo ibi ti a ba wa. 2 Likes 1 Share |
Re: .. by Nobody: 7:37pm On May 18, 2015 |
nisai: E pada sehin die, mo ti fi Oogu Apagun ranse si ibeere yin. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 7:38pm On May 18, 2015 |
mhicrotee: Ko si iberu. |
Re: .. by nisai: 7:40pm On May 18, 2015 |
healthFirst:Oda oo,ese pupo.Ilakaka yin oni ja sasan. |
Re: .. by scholes0(m): 7:45pm On May 18, 2015 |
healthFirst: E ti so oju abe ni iko! Ejowo se e ni imo nipa Oju Iwe ero Ayelujara kankan, ti mo ti le ka nipa Asa isembaye eya Yoruba ati imo ijinle ni ekunrere? 1 Like |
Re: .. by Kulrunner: 4:36am On May 19, 2015 |
EJO MONILO OGUN ADODUN 1 Like |
Re: .. by mhicrotee: 7:44am On May 19, 2015 |
scholes0:Beeni oO |
Re: .. by mhicrotee: 7:45am On May 19, 2015 |
healthFirst:Oda oO |
Re: .. by orunmila76(m): 8:52am On May 19, 2015 |
Ara iwaju IBA! Oogun Eyonu to daju igbo die(Indian hemp),Irun Abe obirin die,aa lo po,aa daa sinu lofinda ti a BA feran. Lilo re: pipara Ni aaro Monday. Ofo re: Ojo ti omode BA mu igbo Ni igbo npaa,ojo ti agbalagba BA mu igbo Ni npaa,tomode tagba lo feran obo. 2 Likes |
Re: .. by Lionhearted: 10:06am On May 19, 2015 |
9jacrip: Ta ba lora loja nko bawo leyan se fe mo boya iru obinrin ti e so ti fi owo kan awon eroja na? |
Re: .. by Nobody: 10:16am On May 19, 2015 |
orunmila76: Ki Iba Se O. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 10:30am On May 19, 2015 |
Kulrunner: Hmmm...Ta le fe lo fun? Se e mo awon inkan to ro mo Oogun Adodun? Ikini, ko dara ki a lo fun Obinrin ti a ko ni fe se iyawo nitoripe ife wa ko ni kuro lokan re laelae, ikeji, ko dara ki a lo fun iyawo ile wa nitoripe, bi o ba pe ti a ti nlo fun, yio ma din orire Obinrin na ku diedie sugbon ko ni le fi wa sile laelae. 5 Likes |
Re: .. by Lionhearted: 10:58am On May 19, 2015 |
healthFirst: Ko boju mu ke fi si ori ategun. Btw, Ta ba lora loja nko bawo leyan se fe mo boya iru obinrin ti e so ti fi owo kan awon eroja na? 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 11:45am On May 19, 2015 |
Lionhearted: Ni opolopo igba, awon eewo yi ro mo awon Oogun ti a ba n se won lowo. Ni igba miran, won ro mo bi a ba fe ja ewe won. Awon Obinrin onisegun wa daada ti oogun won n je. A ko le so wipe gbogbo oogun ni inkan osu obinrin le baje ati wipe ona miran wa lorisirisi ti a fi le maje ki awon eewo wonyi ni agbara lori Oogun ti a ba fe se. Idi niyi ti o fi je wipe bi a ba fe se oogun, ki a sun mo awon agbalagba to ni imo kikun. Lakotan, kii se gbogbo asiri la le tu lori afefe. Abo oro laa so fo'mo 'luabi. 5 Likes |
Re: .. by Nobody: 12:49pm On May 19, 2015 |
Lionhearted: Awon l'eku l'eja o kin wa ni idi o ja ti wan ba nse nkan osu. Sugbon odo awon arugbo leku leja do dara ju lati ra eroja nitori wan o se nkan osu mo. |
Re: .. by absoluteSuccess: 2:20pm On May 19, 2015 |
scholes0:Oro yi laba fiwe opiliki, ti yoo fi tie sile, tio maa gbo teni-eleni: Orunmila nio baa gbo tie na, erigialo. Alagemo ti bimo re na... |
Re: .. by Kulrunner: 3:15pm On May 19, 2015 |
Ekuse o, yio ju yin se ooo.
ejo motin se exam weac elekerin re, kini mole seh ti mafi bolowo ajaga yi?
ifa agbeyin ooo. |
Re: .. by Nobody: 5:51pm On May 19, 2015 |
Kulrunner: Opolopo igba lo ma n je wipe iwa ole nipa kika iwe lasiko to ye lo ma n fa ti awon akeko ode oni fi ma n kuna idanwo. Sugbon bi o ba je wipe iwo kii se ole nipa kika iwe lasiko, ona abayo wa fun o. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 6:08pm On May 19, 2015 |
.. 3 Likes |
Re: .. by Kulrunner: 6:30pm On May 19, 2015 |
Edakun ebami salaye awon egbogi yen 1 Like |
Re: .. by Nobody: 6:54pm On May 19, 2015 |
Kulrunner: E lo ba awon elewe omo ki won ta fun yin tabi ki e wa awon agba ki won se alaye fun yin. |
Re: .. by Mayorz200: 6:59pm On May 19, 2015 |
Ejowo baba ti awon ika eniyan ba n le eniyan bo ti won den ti fe ba eniyen. Iru ajesara abi iru kini eniyan le se sara to fi je pe to ba bu yepe(sand) lu awon to n lebo ti won a fi subu lule |
Re: .. by Bmark: 10:50am On May 20, 2015 |
healthFirst:eku ishe opolo.kilo le faa ki eeyan maa laagun lapoju lona ti o ribee tele.awon dokita oyinbo ni ko si nkan ti o she oluwa leyin ayewo bee ara onitohun ko si yaa.o ti lo oogun eje titi sibe ara e man weak gan.ejoo iru kileleyi le je?awon kan ni ofa?ejoo elami loye. |
Re: .. by Bmark: 10:57am On May 20, 2015 |
eku ishe opolo.kilo le faa ki eeyan maa
laagun lapoju lona ti o ribee tele.awon
dokita oyinbo ni ko si nkan ti o she oluwa
leyin ayewo bee ara onitohun ko si yaa.o ti
lo oogun eje titi sibe ara e man weak
gan.ejoo iru kileleyi le je?awon kan ni ofa?
ejoo elami loye. |
Re: .. by Nobody: 12:37pm On May 20, 2015 |
Bmark: E je ki eni naa lo wa Egbo Akogun, ki o gun po daada ko kuna...ki o da omi osan wewe si fun mimun nigba gbogbo. O da mi loju wipe lehin igba die, yio bere si ri iyipada ninu ara. 3 Likes 1 Share |
Re: .. by Nobody: 12:39pm On May 20, 2015 |
Mayorz200: Asubusire tabi Aluwo oni yepe ni a le lo...Bi Subusere ba wa lara ti awon eeyan nle wa, won ko ni le le wa ba, bi o ba ku die ki won mu wa, won yio ma subu dide, subu dide ni. Bi a ba ni Oruka Aluwo oni yepe lowo, bi won ba n le wa, ao fi owo yen bu yepe, ao da lu gbogbo won, enikeni ti yepe ba ba, yio subu. sugbon ko se fi sile lori afefe nitori awon eeyan ika. 3 Likes 2 Shares |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply)
Viewing this topic: 1 guest(s)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 63 |