Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,201,378 members, 7,978,205 topics. Date: Thursday, 17 October 2024 at 09:47 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1843605 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by scholes0(m): 1:22pm On May 20, 2015 |
Bmark: Alaye aisan ti e se yii jo eleyii ti awon elede geesi maa n pe ni "Anaemia", ti o maa n waye ti eje eniyan ba dinku ninu seeli eje funfun. E je ki eni yen pada lo si odo dokita onisegun oyinbo fun ayewo ara titun. Imoran mi niyen. Ki alaare naa si tun maa fi oogun ibile tele iwosan re naa leyin. |
Re: .. by Bmark: 6:17pm On May 20, 2015 |
healthFirst:ese gan.nkan ti mo tun fe moniwipe shey ofa ni oogun yen shishe fun ni tori ati lo ogun oyinbo titi ti ko shishe rara 1 Like |
Re: .. by Nobody: 6:21pm On May 20, 2015 |
Bmark: E se alaye lekun rere bi aisan na se n se eni na. |
Re: .. by Bmark: 8:04pm On May 20, 2015 |
healthFirst:gbogbo ara e weak,,oti lo oogun eje titi ko ri iyipada ojo ti aisan yii ma a bere o ni odab ti won ju nkan lu oun laya lojiji.lati ojo naa loti bere to ba ti rin irin die a maa laaguin gidigan.aa ni okan re oun ni. |
Re: .. by sammyjay76(m): 8:13pm On May 20, 2015 |
Mo ki yin o, eku ise igbala, Asejere le o ma se o. Mo ni ibere fun aisan ti awon oloyinbo geesi npe ni SICKLE CELL ANEMIA, ejowo ki ni ona abayo si ati dekun iru fe aisan yi? Nje oni oogun bi? Ewe ma a je ooooo... |
Re: .. by sammyjay76(m): 8:16pm On May 20, 2015 |
Mo ki yin o, eku ise igbala, Asejere le o ma se o. Mo ni ibere fun aisan ti awon oloyinbo geesi npe ni SICKLE CELL ANEMIA, ejowo ki ni ona abayo si ati dekun iru fe aisan yi? Nje oni oogun bi? Ewe ma a je ooooo... 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 8:28pm On May 20, 2015 |
sammyjay76: Ibeere ti o dara ni e bere. KI a maa reti baba fun idahun. 1 Like |
Re: .. by Kulrunner: 11:31pm On May 20, 2015 |
ejo kini ale lo fun eni ti koma n se nkan osu lai loyun. 1 Like |
Re: .. by Mayorz200: 6:25am On May 21, 2015 |
Ejowo baba---se mo le salaye funyin ni bokele idi ti mo fe ti oniyepe subu. Ejowo baba |
Re: .. by scholes0(m): 8:07am On May 21, 2015 |
Mayorz200: E fe so fun wa wipe e mo awon oro Yoruba fun: Pls: ( E jòwó) Private: (Ìkòkò tàbí Gbònkélé) Month (Osù) need: (Nílò) 1 Like |
Re: .. by Lionhearted: 8:15am On May 21, 2015 |
? |
Re: .. by scholes0(m): 8:19am On May 21, 2015 |
Lionhearted: E ni suuru die, e je ki baba Onisegun ibile wa o pada de, o da mi loju wipe won ni egbogi pato, fun isoro ti eni yii n dojuko. 1 Like |
Re: .. by bolorunfem(f): 12:26pm On May 21, 2015 |
Baba, e ku ise iwosan, Olodumare a pin yin ni ere o. Ase. E jowo e fun wa ni oogun iju olojo-pipe, oogun eda ati aran latanlatan. E seun mo dupe. |
Re: .. by Nobody: 2:35pm On May 21, 2015 |
E joo...mo lo irin ajo ranpe ni o. Bi n ba pada sile lola, ng o dahun gbogbo ibeere yin. |
Re: .. by Nobody: 4:08pm On May 21, 2015 |
Bmark: E je ki eni na pada lo si Ile Iwosan alayewo, ki won se ayewo Okan eni na..Alaye yin jo ti eni to ni aisan Okan oni pajawiri...bi o se ma n bere niyen. Sugbon lehin ayewo, bi awon dokita ba tun so wipe awon o ri inkankan, ki e pada fun wa labo. |
Re: .. by Nobody: 4:46pm On May 21, 2015 |
.. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 5:00pm On May 21, 2015 |
Mayorz200: O ya, e se alaye ni bonkele. |
Re: .. by sammyjay76(m): 8:07pm On May 21, 2015 |
healthFirst: Eseun fun dahun yi....... Ejowo se dan dan ni o gbodo je. Pe eegun itan adie ni won yio ma fi mu ni? Se a o toju eegun adie naa ti a o ma fi mu ni igba de igba ni abi ekan soso naa nbi yio fi mu eko abi, ao ma pa adie ni gbogbo igba ti a ba fe fi oogun yi mu eko ni? E dakun e se alaye naa daradara fun wa. 1 Like |
Re: .. by Mayorz200: 7:07am On May 22, 2015 |
. |
Re: .. by Nobody: 9:48am On May 22, 2015 |
sammyjay76: Rara o eegun itan kan ti e ba ti fi bere na leo maa lo 1 Like |
Re: .. by Nobody: 9:50am On May 22, 2015 |
Mayorz200: E fi ranse si binaryteck@gmail.com |
Re: .. by Nobody: 10:00am On May 22, 2015 |
.. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 12:57pm On May 22, 2015 |
.. 2 Likes |
Re: .. by Lionhearted: 1:29pm On May 22, 2015 |
healthFirst: Eni na ti se ayewo. Esi re ni Sinusitis ati systemic yeast infection. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 2:27pm On May 22, 2015 |
all dis igbo fools self |
Re: .. by Nobody: 2:32pm On May 22, 2015 |
Lionhearted: E je ki eni na lo Gbogbonise yen...ng o tun fi omiran sita fun yin. |
Re: .. by bolorunfem(f): 4:23pm On May 22, 2015 |
healthFirst:Mo dupe, e seun o, baba. Ewe a maa je o. Olorun a se gbogbo ise yin ni asepe. 3 Likes |
Re: .. by Nobody: 6:12pm On May 22, 2015 |
.. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 6:47pm On May 22, 2015 |
healthFirst: E seun gan Baba fun idahun yi. Bi otileje pe ko si ogun oyinbo fun arun yi, Ogun ibile wa fun foniku-foladide (sickle cell). 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 7:15pm On May 22, 2015 |
walexy30: beeni |
Re: .. by Nobody: 7:27pm On May 22, 2015 |
walexy30: Oogun re wa daada sugbon mo fi eleyi sita nitoripe a ti lo ri to sise daada. 1 Like |
Re: .. by talktofemi: 4:46am On May 23, 2015 |
Eku ise o, Nje ogun wa fun eniti ki gboran daadaa? Eniyan mi kan ni lo re, |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 35 |