Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,206,882 members, 7,997,120 topics. Date: Thursday, 07 November 2024 at 11:29 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1845656 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by Mayorz200: 9:59am On May 23, 2015 |
E jowo baba kilo n je e, Enukopire gege bi e ti se alaye ninu oogun aran. E jowo se ewe ni sir |
Re: .. by Nobody: 10:29am On May 23, 2015 |
Mayorz200: Enukopire wa lodo awon elewe omo...eka igi ni. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 10:31am On May 23, 2015 |
talktofemi: E joo e se alaye daada...ki lo se eni na ti ko le fi gboran daada mo? se bi a se bi niyen tabi aisan to sese wa si lara ni? tabi eti yen wu ni tabi kokoro wo eti yen? Alaye ekunrere je dandan. Ki a ma ba fi oogun ori fifo wo inu rirun. 2 Likes |
Re: .. by sammyjay76(m): 12:34pm On May 23, 2015 |
healthFirst:ESEUN GAN O, AJINDE ARA YIO MA JE. O. LEKAN SI LORI OOGUN SICKLE CELL YI...... EJOWO BA MI SE ALAYE IYE IGBA TI A LE LO OOGUN NAA DA, ABI TITI LKO NI? EJEJI, ESO RERE TI E DARUKO NAA, E SE ALAYE DIDAMO DARADARA, SE RENRENni? ABiI RERE? EDAKUN TI OOGUN MIRAN TABI ONA MIRAN BAWO LATI DEERO AISAN YI PATAPATA E BA WA FI SITA. E O NI SUBU DANU O, EDA GBOGBO AWON ENIYAN TI WON RI OREOFE NIPA IWULO EWE ATI EGBO YI AFI IRE AJENJETAN FUN AYE YIN. ESEUN PUIPO. |
Re: .. by Nobody: 2:13pm On May 23, 2015 |
sammyjay76: Ao ma lo titi ti ara alaisan na yio fi ya tan patapata. Eso Rere ni Eso to wa lori Igi Rere...o yato si Renren...e beere lowo awon elewe omo Awon Oogun re miran wa sugbon se e mo wipe kii se gbogbo Oogun la le fi sori afefe. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 4:04pm On May 23, 2015 |
.. 1 Like |
Re: .. by sammyjay76(m): 4:21pm On May 23, 2015 |
E ku ise o, edumare oba oke a ma fun yin se o.... Ejowo e fun wa ni ogun ti eniyan o ni le fi ko arun lara obinrin tabi okunrin, boya magun, eroo, ati awon arun miran. Ati oogun ti a fi n so ile eni tabi ayika wa di eewo fun emi buburu tabi awon nkan aransi. A ma jhu yin se ooooo...... Amin. |
Re: .. by kadunasouth(m): 10:16pm On May 24, 2015 |
healthFirst: Thanx ese pupo 1 Like |
Re: .. by kadunasouth(m): 10:56pm On May 24, 2015 |
[quote author=healthFirst post=33648850]20 OOGUN AWOKA TABI EJE DUDU A. Egbo Orogbo at Alugbokita, Erinje, ao fi ekan ori(Omi Ogi) se won po...ao ma yo mu diedie. B. Egbo Saposapo,Ewe Dagunro,Erinje, Ose dudu die, ao se won lagbo, ao ma yo mu diedie. D. Ewe Ese Adiye, Erinje...ao se po pelu omi...ao ma fi we ibe. Edakun kilonje erinje atipe oruko miran wo lalepe fun awon elewe omo 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 12:49pm On May 25, 2015 |
[quote author=kadunasouth post=34065343][/quote] oruko ti mo mo niyen...e beere lowo awon elewe omo. |
Re: .. by Lionhearted: 1:05pm On May 25, 2015 |
healthFirst: Ejowo kini egungun ara iganna? Se igi ni? Ati pe kilon je orike rike? Kini itumo tefa eji ogbe? Se eriru na ni eeru(ash)? Ema binu awon ibere won yi baba. Mo Fe koye mi daadaa ni o kin to lo ra awon eroja wonyi loni. 1 Like |
Re: .. by Lionhearted: 2:19pm On May 25, 2015 |
healthFirst:A nduro fun omiran ti e so. |
Re: .. by Nobody: 3:12pm On May 25, 2015 |
Lionhearted: E je ki eni na lo Gbogbonise yen ki e wa fun mi labo. |
Re: .. by Nobody: 3:18pm On May 25, 2015 |
Lionhearted: Gbogbo ibeere wonyi tumo si wipe e kii se omo Yoruba. Orikerike ara ni gbogbo eya ara to sepo...awon bi Ejika, Isepo Apa, Isepo Ese, orun ese, Orun owo, Igunpa ati beebe lo. Eriru yato si Eeru...Eriru je eso ori igi, Eeru ni ajoku igi idana. Tefa Ejiogbe tumo si wipe ka fi ika te Ifa Ejiogbe sori Iyerosun tabi Ebu Oogun. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 3:20pm On May 25, 2015 |
sammyjay76: Awon Oogun to lagbara niwonyi...e kan simi lori apo ifiwe ranse binaryteck@gmail.com |
Re: .. by Lionhearted: 3:43pm On May 25, 2015 |
healthFirst: Omo bibi ile yoruba ni mi sugbon idale ni abi mi si, ibe si ni moti kawe dagba. Eseun alaye ye yin. Ni pa ti tefa ejiogbe: iyerosun tabi Ebu Oogun tumo si? 2 Likes |
Re: .. by OROSUNBOLB(m): 9:07pm On May 25, 2015 |
healthFirst: E ku ise o Baba. E jowo bawo ni ao se lo Ogun yi o ? E seun o,ewe a ma je o. 3 Likes 1 Share |
Re: .. by sammyjay76(m): 9:22pm On May 25, 2015 |
healthFirst:Mo ti fi atejse kan ranse si yin lori email yin naa, e yewo ki e le ri...... Ngo ma reti idahun yn ni ekun rere. E pe fun wa ooooo. Amin. |
Re: .. by Nobody: 2:17pm On May 26, 2015 |
.. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 2:17pm On May 26, 2015 |
sammyjay76: Mo ti fi idahun ranse. |
Re: .. by sammyjay76(m): 3:16pm On May 26, 2015 |
healthFirst:Mo kiyin o, E dakun esi awon ibere mi ti e so wipe e t f ranse naa, mi o ri nnu email mi rara. E jowo bami fi ranse si email mi naa lekan si.....sajolive6@gmail.com E jowo eseun ooooo. MO TI WA RI NI ISINYI, KO DA O SE SE WOLE LOWO LAIE NI...... ESEUN GAN MA TUN FI ESI RANSE LAIE YI..... ESEUN GAN. |
Re: .. by Nobody: 3:43pm On May 26, 2015 |
sammyjay76: O dara. |
Re: .. by scholes0(m): 4:46pm On May 26, 2015 |
E ku ise naa o... Oba eledua a maa fun yin se, Oogun yin a maa je! E jowo, nje e le so fun mi ni awon nkan elo fun ogun afose? ati awon eto ti maa fi jo won po mo ara won? Ti e ba fe gba adiresi mi lori ero ayelujara, ki a fi ranse si mi ni gbonkele, iyen naa da. |
Re: .. by powell24ay: 2:09am On May 27, 2015 |
Ejoo, ewo ni o ye ki a se ninu eyonu tabi awure bi a ba fe lowo repete lai si pe eniyan seku? |
Re: .. by Nobody: 10:07am On May 27, 2015 |
OROSUNBOLB: Ao ma fi para 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 12:02pm On May 27, 2015 |
.. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 12:04pm On May 27, 2015 |
scholes0: Afose Epe tabi Iwure? |
Re: .. by Nobody: 12:06pm On May 27, 2015 |
powell24ay: Eyonu ni agba Awure...bi awon agba ba yonu si wa ni Oogun Awure yio to sise. Mejeeji lo wulo fun nini owo ati ola sugbon Eyonu lo gbudo saaju. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 12:26pm On May 27, 2015 |
.. 1 Like |
Re: .. by powell24ay: 12:27pm On May 27, 2015 |
E se o baba. Agba yin a kale o. A oo maa ri yin ba. |
Re: .. by Nobody: 12:56pm On May 27, 2015 |
x.. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 1:57pm On May 27, 2015 |
... 3 Likes |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 31 |