Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,201,381 members, 7,978,223 topics. Date: Thursday, 17 October 2024 at 10:24 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1843612 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (6) (7) (8) (9) (10) (11) (12) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by kadunasouth(m): 3:56pm On May 31, 2015 |
kadunasouth:[/color][color=#990000] OGUN ISORA AIKU Adigbanaku mesan eyo atare mesan ao lo kuna dada ao fi sin gbere mesan sori opari [color=#006600][/color] 2 Likes |
Re: .. by kadunasouth(m): 4:09pm On May 31, 2015 |
kadunasouth: Ogun Anu ire ojo Adeyanju Awo Ajiki, Adetutu awo Aji foro rere lo eledumare, ejeki emi LxL ri eni ti yio semi lanu loni yio , Ase ni ti eji ogbe NB ao je Atare 9 kato soro ao pe ofoyi ao tu sinu omin ao gbemu laro kutukutu opari 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 4:11pm On May 31, 2015 |
sammyjay76: E seun pupo fun akiyesi ati afikun yin...e joo e fun mi ni bi Ojo melo kan lati ro oro na daada nitori akoko ko fi aye gba mi pupo. sugbon aba te mu wa yi dara pupo. 1 Like |
Re: .. by kadunasouth(m): 4:13pm On May 31, 2015 |
kadunasouth: Ogun arisiki Eye ega odidi atare kan ao fi ikode ha eye yi lenu ao fi atare si legbe ao jo ao fi foko mu lekan nan 2 Likes |
Re: .. by kadunasouth(m): 12:28pm On Jun 01, 2015 |
kadunasouth: Owo (respect) odaju Owo osi ikun ao fi horo eyo atare kan si ao fi sinu efe owu ao di ni iko bere pelu owu dudu ati funfun ao palawo dudu ao ma fi sapo odaju, asi le fi ko si nu ile ole koni wole na lai lai 3 Likes 3 Shares |
Re: .. by Nobody: 2:11pm On Jun 01, 2015 |
.. 1 Like |
Re: .. by kadunasouth(m): 7:52am On Jun 02, 2015 |
kadunasouth: Ogun ogbe inu (ulcer) odaju Aidan ao ge keke sinu roba ti owo wa lewo ao fi ose niwanba die si ao wa bu omi toma dada si bi swan water ao ma fi tele inu laro kutu yio lo pata pata 2 Likes 3 Shares |
Re: .. by Nobody: 5:43pm On Jun 03, 2015 |
.. |
Re: .. by Nobody: 5:46pm On Jun 03, 2015 |
x |
Re: .. by Nobody: 5:53pm On Jun 03, 2015 |
.. 2 Likes |
Re: .. by bolorunfem(f): 2:59pm On Jun 04, 2015 |
healthFirst: Baba, e ku ise o. Adura wa a gba. Ase. E jowo mo sakiyesi pe Ebe awon agba yen rorun lati se, nitori idi eyi, kini iwulo re ati pe igba wo ni a le loo? 1 Like 2 Shares |
Re: .. by sammyjay76(m): 5:56pm On Jun 04, 2015 |
healthFirst: E n le ni beyen, Bawo ni oro wa? Mi o tun ri esi oro email ti a so pati mo? Fun ti oogun SCD ti a so naa eso (RERE)ni ede yoruba se amin isale ti a npe ni d d ni abi amin oke ti a ne ni m m, abi amin arin ni? Nitoripe pipe re se pataki. Ejowo dahun oro asotele wa. Eseun. |
Re: .. by Nobody: 5:58pm On Jun 04, 2015 |
bolorunfem: Iwulo re ni wipe ki awon to ni aye le yonu siwa ati wipe ki gbogbo idawole wa nile aye le yori si rere. Orisirisi re lo wa sugbon e le lo eleyi ni igbakugba to ba wu yin. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 5:59pm On Jun 04, 2015 |
sammyjay76: Amin Oke ni o. |
Re: .. by bolorunfem(f): 12:08pm On Jun 05, 2015 |
. |
Re: .. by bolorunfem(f): 12:10pm On Jun 05, 2015 |
A dupe pupo, e seun. Ewe a maa je o. Amin-Ase. |
Re: .. by Nobody: 5:16pm On Jun 06, 2015 |
x |
Re: .. by Nobody: 7:16pm On Jun 08, 2015 |
.. 2 Likes 1 Share |
Re: .. by Nobody: 7:18pm On Jun 08, 2015 |
x |
Re: .. by Nobody: 7:37pm On Jun 08, 2015 |
x 3 Likes 1 Share |
Re: .. by Nobody: 12:41pm On Jun 09, 2015 |
x 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 12:43pm On Jun 09, 2015 |
Igba ko lo bi orere, Bi oni se ri, ola le ma ri bee ni babalawo se n difa ororun...hmmm. 2 Likes |
Re: .. by sammyjay76(m): 2:53pm On Jun 09, 2015 |
healthFirst:EJOWO SE NIGBA TI A BA TI TI TANNATANNA NAA BO YIO WA NINU RE TI A O FI BU IBE JE NI ABI A O YO KI A TO BU OKANKAN I BE JE? 1 Like 1 Share |
Re: .. by sammyjay76(m): 3:00pm On Jun 09, 2015 |
healthFirst:EDAHUN SI AGBEYEWO YII SE LEHIN TI ATI JO AGBADO AKOKO PELU ORUKO TI A KO SI PAPER TI A DI MO NI A O TUN DI ORUKO MIRAN MO EBU ATI ORUKO TI A O TUN KO NI? ABI A O TUN WA AGBADO MII? E DAKUN SE ALAYE KO LE YE WA DADA. ESEUN. 3 Likes |
Re: .. by Nobody: 10:12am On Jun 10, 2015 |
sammyjay76: lehin ti a ti jo agbado akoko pelu oruko tan, ao tun ko oruko miran si ara paper, ao wa di won papo. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 10:13am On Jun 10, 2015 |
sammyjay76: E tele gege bi a se se alaye re. |
Re: .. by sammyjay76(m): 2:08pm On Jun 10, 2015 |
healthFirst:GBOGBO ILE NI MO KI O..... EJOWO EFUN WA NI OOGUN TI RIRU EJE BA WA LE JU, TI A MO SI HYPOTENSION I DAKEJI HYPERTENSION.............................................................................................................................................. |
Re: .. by kadunasouth(m): 5:24pm On Jun 10, 2015 |
sammyjay76: 2 Likes |
Re: .. by fbabs(m): 9:13am On Jun 11, 2015 |
Baba, e Ku ise ribi ribi . Olorun a maa fun yin Se.
Ogun AFAKO ni awa okunrin n beere fun o. eyi ti o Maa rorun ati Se ni,
e joo o bi Maarun si mefa. charm for permanent increase in penis size,lenght,width and thickness. |
Re: .. by kadunasouth(m): 6:30pm On Jun 12, 2015 |
[quote author=kadunasouth post=34631247][/quote] OGUN Roparose(stroke ) Egun jeki alubosa ayu ati odidi atare ao jo ao fi sin gbere yipo idiwa ati owo ati esewa mejeji, 2 Likes |
Re: .. by obaede: 12:18am On Jun 13, 2015 |
WWW.olayemioniroyin.com |
Re: .. by kadunasouth(m): 11:56am On Jun 13, 2015 |
kadunasouth: ATUDE TODAJU Ewe tude egbo tude iyere ao lo ti yio kuna dada ao ra isasun tuntun ao fi se odidi igbin kan je lepo niyo lodidi ni ao se igbin yi o akoni ge ti obajina ao so kale ao je ko tutu ao wa bo gbogbo aso orun wa ati oruka ao wa ni ihoho omoluabi ao wa da aseje na si ilele ao kunle ti ao wa ka owo wa mejeji seyin wa ao wa se adua itusile ao wa fi enu gbeje lodindi iseyi daju danwo kori botiri Ike oloun ola oloun komaba alayelorun NB ori ilele cement or tiles lamada aseje yi si leyin ti ati nunu dada ao dasi ao waje Iba akoda iba aseda iba agba merindinlogun lotu ife iba baba iba mama iba omode iba agbalagba iba okunrin iba obinrin efi oju rere womin o! Ase edumare Contact me 08028358926a@gmail.com 2 Likes 1 Share |
(1) (2) (3) ... (6) (7) (8) (9) (10) (11) (12) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 41 |