Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,201,355 members, 7,978,134 topics. Date: Thursday, 17 October 2024 at 08:01 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1843598 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (8) (9) (10) (11) (12) (13) (14) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by fardolly: 5:48pm On Jun 22, 2015 |
Baba ooooo Iba agba |
Re: .. by Nobody: 5:58pm On Jun 22, 2015 |
pappykay0428: Gege bi awon agbalagba se ko wa, bi eniyan ba fe bo Ori, eni na yio to Awo lo nitoripe, eeyan funrare ko le boo Ori ara re funrare |
Re: .. by Nobody: 6:24pm On Jun 22, 2015 |
pappykay0428: Awa o ki se Awo Ika... ki lo de to fi je wipe awon oogun ija le n wa? Kini e fe fi won se? 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 6:28pm On Jun 22, 2015 |
sammyjay76: Eso Ako Rere ni mo n so. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 6:30pm On Jun 22, 2015 |
bosrote: Haha!...E fe je igbin je ikarahun pelu re! Eewo Orisa! |
Re: .. by Nobody: 6:30pm On Jun 22, 2015 |
kadunasouth: Oogun yi dara pupo. kare o Awo. 2 Likes |
Re: .. by kadunasouth(m): 5:42am On Jun 23, 2015 |
ASEJE ARISIKI todaju Ewe areyinkosun, ewe orijin, ewe sawerepepe ao lo yio kuna dada ao fi din eyin ororo meta je lepo niyo NB wase bi emeta lerawon toba fe ko daun dada 2 Likes |
Re: .. by dominicson: 8:30am On Jun 23, 2015 |
healthFirst: Eeeeeee pa 'mole! Agbo ato e! Ogbo edan Ogbo ... 2 Likes |
Re: .. by dominicson: 8:41am On Jun 23, 2015 |
healthFirst: Ni ibo ni osu tie ti le o? 1 Like |
Re: .. by Nobody: 9:56am On Jun 23, 2015 |
dominicson: Ogbo Akokoniko o Awo. 1 Like |
Re: .. by kadunasouth(m): 10:27am On Jun 23, 2015 |
. |
Re: .. by Hardetutu01(m): 10:36am On Jun 23, 2015 |
kadunasouth:mi o understand lepo niyo sir...ejowo e laa ye mi daadaa sir |
Re: .. by Hardetutu01(m): 10:49am On Jun 23, 2015 |
kadunasouth:"lepo niyo" means "pelu epo ati iyo abi"? |
Re: .. by gawab: 10:51am On Jun 23, 2015 |
E jowo e fun wa ni ogun gege ofun to daju. 1 Like |
Re: .. by gawab: 10:54am On Jun 23, 2015 |
kadunasouth:E jowo egbogi wo ni a le lo si gege ofun. |
Re: .. by Richie016: 4:21pm On Jun 23, 2015 |
iba awon ti o koko ja ewe o. E jowo baba, nje oogun ti won fi le gba eeyan si ibi ise pada leyin ti won ti le onitoun kuro nibe wa bi? E seun. Ewe a maa je o |
Re: .. by kadunasouth(m): 9:01pm On Jun 23, 2015 |
. |
Re: .. by leckxy(m): 9:39pm On Jun 23, 2015 |
kadunasouth:Ejo baba kini anpe ni iyere? |
Re: .. by gawab: 6:58am On Jun 24, 2015 |
kadunasouth: Ogun wo ni enia le lo ti gege orun/ofun yio fi lo patapata. |
Re: .. by kadunasouth(m): 9:08am On Jun 25, 2015 |
Hardetutu01:Leyin teti lo aWon ewe wonyi eo fo awon eyin na sinu abo ebu ewe die si eo fi iyo die si eo wa ro papo dada eo wa gbe epo kana eo wa fi din to ba tutu eo koje ebu tobaku elo mi na lelo 2 Likes |
Re: .. by kadunasouth(m): 9:12am On Jun 25, 2015 |
leckxy:Elosi odo awon elewe omo ebere wan ota funyin bi oni muri kan tito niwan ba die leo fisi bi eyo 16 2 Likes 1 Share |
Re: .. by Nobody: 12:54pm On Jun 25, 2015 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 12:55pm On Jun 25, 2015 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 12:57pm On Jun 25, 2015 |
ORISIRISI OOGUN Oogun funfun Oogun dudu Oogun pupa Kiyesi oogun toba romo eleda re. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 12:58pm On Jun 25, 2015 |
Ifunra loogun agba, agba loogun ifunra. E kiye sara. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 1:00pm On Jun 25, 2015 |
x 1 Like 2 Shares |
Re: .. by Nobody: 1:06pm On Jun 25, 2015 |
x |
Re: .. by idrisalomagold(m): 4:00pm On Jun 25, 2015 |
Mo gbadun yin gan ni o. Ejowo, ohun ti mo n fe ni ogun ti o ma n mu nnkan omokunrin tobi gidi gan. |
Re: .. by Nobody: 4:52pm On Jun 25, 2015 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 4:53pm On Jun 25, 2015 |
idrisalomagold: Mo n bo. |
Re: .. by bolorunfem(f): 10:56am On Jun 26, 2015 |
E jowo, oogun ibile wo ni a le lo fun omo ti pneumonia nyo lenu. A dupe pupo. |
Re: .. by sammyjay76(m): 1:57pm On Jun 26, 2015 |
[quote author=healthFirst post=35136583]ORISIRISI OOGUN Oogun funfun Oogun dudu Oogun pupa Kiyesi oogun toba romo eleda re.[/quote [color=#006600][/color] Ejowo se alaye dada nipa awon oogun ti e daruko naa, ki olukuluku le mo bo ti ye ka se si. Leekan si edakun efi oogun Sickle Cell miran ranse si bi fun anfaani awon to ni awon eniyan bee lowo to si gbagbo ninu ewe ati egbo, awa naa ni ona ewe ati egbo ti a n lo sugbon karin ka po yiyeni ye ni oooo. olorun a ma fun yin se o. |
(1) (2) (3) ... (8) (9) (10) (11) (12) (13) (14) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 30 |