Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,208,671 members, 8,003,329 topics. Date: Friday, 15 November 2024 at 11:31 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Yoruba Commonwealth and Politics (704590 Views)
OPC - Faseun & Adams Unite For Security Of Yoruba Commonwealth / SEUN - Re: Yoruba-commonwealth-politics / Goodluck Jonathan Returns From Commonwealth Assignment (photo) (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (80) (81) (82) (83) (84) (85) (86) ... (384) (Reply) (Go Down)
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 9:35pm On Oct 29, 2015 |
WIZGUY69:E jowo kinni orisun atoka ti e se afihan re yi? |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by WIZGUY69(m): 9:39pm On Oct 29, 2015 |
razid: God! Ede yooba yi lagbara ju mi lo CC : totit Modified : orisun Afihan ye je infinixX510 tabi infinix Hot 2. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by WIZGUY69(m): 9:42pm On Oct 29, 2015 |
Shymm3x: Hyde Park bawo? |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by zimoni(f): 9:42pm On Oct 29, 2015 |
Eleekeji ni eyi. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by zimoni(f): 9:42pm On Oct 29, 2015 |
modath: Ijesha lu o re? Eledumare ooooooo Edumare la a fi melody s'aye re. Paadi ni ogbon baba mi, Isida ni ogbon yeye mi. Otun mi, osi mi Ijesha lu an re. Amo, Ule-Ufe ni an bimi si ki mo se d'agba si. Oyo ni me e pein ooooo. Me ra mo wi Ijesha ni in re. Baba Re A Gbe Oooooooooo. Adojutini ni Ogbeni jakujaku ko pe ra ni Aregbe ni, e se Ijesha gidi. Ijesha a se apa, olusowo ke e s'aseyori ni a re, a a se apa. Apa ni Ogbeni jatijati Aregbe ni, adojutini gbaa ni. Hinpele Oooooooooo. 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 9:43pm On Oct 29, 2015 |
E kaale o gbogbo ile. Oro temi ni ale yi ni wipe bi o se je wipe ko fee si olori fun ile Yoruba lode oni gege be Baba Awolowo, Baba Adesanya, Baba Bola Ige, tani a lero wipe o tun le se ise takuntakun ti o lemu idagbasoke ba ile Yoruba nile loko. Ero temi ni pe, lehin iku baba Adesanya, ko fe e si eniti a le pe l'olori ile Yoruba mo. Eyi to buru jayi ni wipe awon ti a pe ni asiwaju lode oni, awon gan-an ni madaru ti won titori atije ti won se ile Oodua riboribo. Mo fe ki gbogbo wa da si oro yii nitori wipe bi awa odo se n gbiyanju lati le mu ilosiwaju ba ile kaaro ojiire naa ni awon agbalagba yii ti so ra won di igi woroko ti n da ina iru. E maa je ki n so gbogbo oro tan, mo fe ki eyin amoye ti e n be nikale ki e da si. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by zimoni(f): 9:45pm On Oct 29, 2015 |
WIZGUY69: Ko le rara. Orisun ...... Source. Afihan .... Display/Show. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by skyline123: 9:48pm On Oct 29, 2015 |
Missy89: Ikaram - Akoko |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 9:51pm On Oct 29, 2015 |
zimoni:Ki e pe baba. Emi ko fe fi gbogbo ara gba ohun ti e so nipa Ogbeni. Gbogbo wa naa lamo wipe nnkan ko fararo ni orile ede yii. O kan je wipe oro naa tete farahan ni ipinle Osun ni. Mi o mo boya e wo ero amohunmaworan AIT ni aago mejo ale yii, e o ri nibi ti gomina Fayose ti n kerora nipa owo ajumoni ti won n gba lowo ijoba apapo. Nnkan ko fararo rara. Koda, ni ipinle Ondo ti o se wipe awon ti n gba owo epo 13%, o tun nira fun wo lati san owo osu awon osise. Ise ti ogbeni d'owole po ju owo ti o n ri lo. Ohun naa lo fa to fi da bi wipe asiri tete tu l'Osun. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by WIZGUY69(m): 9:54pm On Oct 29, 2015 |
1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 9:55pm On Oct 29, 2015 |
O ma se o. N se ni awon eeyan wa n woran! Se bee ni ede Yoruba nira to ni? Mo fe ki e mo daju pe ilosiwaju ede Yoruba n be lowo emi ati eyin o. 2 Likes |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by modath(f): 9:59pm On Oct 29, 2015 |
zimoni: Ijamo ni ogbon yeye mi, Itisin ni ogbon baba mi, totun tosi emi gan Ijesa ni. Ati yeye yeye mi ati baba baba mi.. baba baba mi, osomalo ni igba odo re ni ile ijesa ati n on igberiko ilesa gbogbo... Ile-ife ni mo ti yun sukuru giga. Ilu eko ni mo ti se omode , amo be, olu ilu naijiriya ni mo mi gbe pelu baale mi ati i n omo mi... Me i so ni arin ero wi mo mo ogbeni oloriburuku adojuti ni, ebi oko Egbon momo mi ni........ Apa ara re iya maaje ooo, oje babanla iya ke to joro... be o ti gbagbe gbogbo re, lo la mi hu iwa asiere.... E si itan Aregbe kankan to sokuku si mi... 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by zimoni(f): 10:07pm On Oct 29, 2015 |
razid: Ni erongba t'emi, ko si bi a se le yo owo oselu kuro ni ipo asiwaju patapata. Ti won ba bi mi, e mi a daun wipe Gomina Ipinle Ogun Ibikunle Amosun ye lati je olori fun wa ni Ile Yoruba. Ori re pe, o si ni ife ara ilu l'okan. Ibi ti o ku die kaato si ni eto aabo. Inu mi ko dun bi awon fulani ad'eran se n yo awon agbe wa lenu ni ipile ogun ti Amosun ko si ri nkan kan se si oro na. Boya tori pe ko ma a ba se awon ara Ilu Abuja ni, emi ko mo. Ogbeni Aregbe ko muna d'oko to to ba di ti oro iselu, amo ko fi oro aabo ipinle osun sere rara. Amosun ni lati da si oro awon fulani ad'eran to won n yo awon agbe lenu ni ipinle ogun. Ni ti temi oooooo, Asofin Ibikunle Amosun ni mo yan. Mo moomo ma daruko Tinubu ni, mi o fe soro nipa re rara. O kan sepere si awon pindipi(PDP) ni, o ni l'owo o tun di s'eru. SIA ni mo yan laayo ni temi ooooo. Oodua A Gbe Wa Ooooooooo. 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by modath(f): 10:09pm On Oct 29, 2015 |
razid: Eeyan mi oluwa a fi ere si ise yin, amo nitori oluwa ki ni aregbe fe fi ibudoko baalu se ni ilu ti o ju wakati 3 si eko ti ko se si oro aje ti o ni ilo re... Iyi to dun mi ju ninu gbogbo iranu ti o n se ni ki eeyan ma ni oro rere lenu..... otun n ba awon asoju (union) ni gboloun aso lori owo won... Ose odun merin akoko daradara amon merin ikeji yi, ko ye oun gan fun ra alarare... Mi o ki n fe ma so oro Ogbeni ekiti yen, gbogbo nkan ti e eeyin lo ko oju si. 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by nisai: 10:10pm On Oct 29, 2015 |
Shymm3x:'Omo iye mi ruwo wa' literally means -you are my mother's child,but connotationally,it means-anything for u my brother. I think Remo was founded by different yoruba subgroup arriving at different times.Perhaps their former dialect had influence their Ijebu-u may search for Makun war. Any other duke is a wash;Bleep the nigga! THANKS FOR MY BELOVED ORIKI. 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by zimoni(f): 10:15pm On Oct 29, 2015 |
razid: Beeni. Otito le so. Ise t'o da'wo le ti po ju oye ti osun n gba lo ati wipe ko lero wipe owo epo robi ma tete wa sile bo se wa sile yen. Olorun a ba wa so ilu d'ero. Osun A Dara. Oodua A Gbe Wa. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 10:19pm On Oct 29, 2015 |
modath:Yoo da fun e iya mi. Ooto lo so. Ti o ba je wipe won fi temi nikan ni, n ko ba da lamoran pe won ko gbodo jeki gomina kan maa se ju saa kan lo. Oro re fe dabi Gbenga Daniel ni ipinle Ogun ni. Nigba naa o gbiyanju ni saa akoko ti e, sugbon kinni o wole eekeji si, ni gbogbo nnkan bere si polukumusu. Idi ni yi ti mo fi da lamoran pe ki won kuku je ki gbogbo awon gomina maa se odun kan pere. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Missy89(f): 10:21pm On Oct 29, 2015 |
skyline123: You mean Ikare? |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Alfaab: 10:21pm On Oct 29, 2015 |
Shymm3x:Go check this thread,uncle... https://www.nairaland.com/566282/oriki-ile-yoruba-yorubaland-praise |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by skyline123: 10:28pm On Oct 29, 2015 |
Missy89: After Ikare then Iyani, Ikaram, Ibaram and so on. Don't know in which order though. The languages change as the villages change. Thought you're from there? 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by zimoni(f): 10:29pm On Oct 29, 2015 |
modath: Eledumare ooooooo. Hin mo daradara re ni ooooo. Ikan ninu in an omo re Rashidat abi Ganiyat, akeegbe mi ni ni futa. Eko awon ke e to ilu lo ka. Owo epo robi ko ja lule lo fo Aregbe lenu ati wipe o ti d'awo le opolope ise ode leekan na. E e gba imonran. Olorun a ba yanju re. Oro abayo be e ni wipe, ipinle osun gbodo wa awon ada ile-ise s'ile ki an a na'wo si wiwa goolu lule Ijesha bi beeko ebi la a pa an ku lu'pinle osun ooooooo. Olorun a ko a yo ninu gbese k'aregbe ko a si i ooooooo. Oro Aregbe doju sunmi. Hinpele. Baba Re A Gbe Ooooooo. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 10:30pm On Oct 29, 2015 |
E gbo na eyin ara, se kosi ona ti awa ara ilu le gba lati ko fun awon ijoba wa nipa mi maa dawole awon ise ti kosi ojo ola fun ni? E wo iye owo ti Ogbeni naa si ibudoko ofurufu ni ipinle Osun ti ko yori sibi kan, ohun naa ni gomina ipinle Ekiti tun da wole bayi o. Mo n fi asiko pe awon Ekitikete ki won tete pe gomina won s'akiyesi tori wipe to ba d'ele tan ti won lo maa da o. Ti ara ile eni ba n je aayan ti a ko ba soro, hunruhenre e ko ma ni je ki awa naa gbadun o. Gbogbo wa lamo wipe kosi bi gomina naa se le pari ise naa ni saa to wa yi. Ki o ma wa di ise asepati, e je ki awon omo Ekiti tete pe si akiyesi bayi o. 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Missy89(f): 10:35pm On Oct 29, 2015 |
skyline123: I haven't heard of Ikaram honestly. So many Akoko towns it seems. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by totit: 10:36pm On Oct 29, 2015 |
WIZGUY69: Mo ki dede re wa oo Haa Gbogbo wa ni mo t'oro aforiji lówó wa o Isè t'ogbomi leni ni o fi ayesile lati darapo mooyi leni o Leekan si gbogbo re mo ki oo Baa wa oo 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by skyline123: 10:41pm On Oct 29, 2015 |
Missy89: Akungba, Irun, Okeage, Aiteju. Those I can remember now. Like the look of Ikare. Also say its the town on a rock. Akoko is just rocks everywhere. Love it. 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by zimoni(f): 10:41pm On Oct 29, 2015 |
razid: Mo gbo wipe o ti da ise na duro. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 10:45pm On Oct 29, 2015 |
zimoni:Rara o. O da ise duro ki awon agbe ti won fe lo oko won le ko ire won ni o. O ti so wipe ti o ba di osu Ope, oun yoo tesiwaju. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 10:47pm On Oct 29, 2015 |
E jeki a daraya die. Nigba ti a koni ji ero Guugu lo, tani o le so awon osu mejila ti n be ni ede Yoruba? Ogbeni Shym3x, ise ya o!!! |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by zimoni(f): 10:59pm On Oct 29, 2015 |
razid: O ga oooooooo. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by tpiah11: 11:15pm On Oct 29, 2015 |
Shymm3x: what's with nlers and hiding behind people? so far, I've been threatened with jamaica, dominican, isale eko, etc etc, but if you observe me closely, you'll notice i dont hide behind people when I have something to say to you. Your attitude typifies cowardice, tell that to your cohorts who plot secretly what they dont have the balls to say in public. oh well, by the time most of your "friends" here realize you want to see them committed to nairaland (and yourself) at a particular cost, yall will have a ball no doubt. good luck. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Shymm3x: 11:48pm On Oct 29, 2015 |
tpiah11: Looool. Scandalous and psychotic sket from Taraba, why are you always quoting me every time you miss ya meds? Why can't you find someone else to disturb? I left the culture section for family section ya crazy arse followed me there. And now I'm back to politics section but you're still following me around. Who the hell gave you a computer in ya asylum? Go play with ya fellow sanctioned psychotic people and stop following me everywhere. I don't want to know no mad heifer from Taraba or wherever the fvck ya parents are from. And get ya mouth off Yoruba's dyck. You're not Yoruba, you sociopath. Don't derail the thread, crazy slag. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by tpiah11: 11:56pm On Oct 29, 2015 |
Shymm3x: do you ever contribute anything worthwhile to a thread. you need to work on your lack of breeding. never saw any nler who rejoices in obscene vulgarity and throwing threads to the dogs as much as you. You really should be used to discourage people from travelling overseas, your case is not encouraging at all. |
(1) (2) (3) ... (80) (81) (82) (83) (84) (85) (86) ... (384) (Reply)
Kenyans Are Far Behind Nigerians In Every Aspect – Fani-Kayode / Anambra light of the nation, eastern economy power house. / Enugu, The Pride Of The East.
Viewing this topic: 1 guest(s)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 1 |