Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,206,111 members, 7,994,781 topics. Date: Tuesday, 05 November 2024 at 08:20 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1845469 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (32) (33) (34) (35) (36) (37) (38) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by ayokomi1010(m): 10:40am On Nov 26, 2015 |
E karo gbogbo Omo Awo,ejo ti nkan omokunrin enia ba kereju ti enia kosi le ba obinrin sun ju ekan lo,ejo Ogun wo lale lo fun to ma sise kiakia,ese ewe amajeo 1 Like 1 Share |
Re: .. by Ayomidegbenga1(m): 10:44am On Nov 26, 2015 |
ayokomi1010: ejoo sir,kini won n pe ni adodun ati wipe kini itumo aiyan. 1 Like 1 Share |
Re: .. by Ifadamilola30: 11:06am On Nov 26, 2015 |
E seun lopolopo, ajagunmale a duro tiyin!! |
Re: .. by Ifadamilola30: 11:18am On Nov 26, 2015 |
Ayomidegbenga1: Adodun!! Ni kukuru, ti obinrin ba nfi Ogun adodun pa oju ara, oko re yio gbadun re ju nkan miran lo. Bee gege fun okunrin to ba nfi ise yi pa nkan omokunrin re, obinrin to ba lo fun yio fe ko tun ma ba oun lopo si ni!! Aiyan ni awon oloyinbo npe ni Cockroach!! 2 Likes
|
Re: .. by ayokomi1010(m): 12:39pm On Nov 26, 2015 |
ejo ajowo lalelo bi oko ba kere,ati ti enia o le ba obinrin sun ju ekan pere lo,edakun gbogbo Omo awo |
Re: .. by Ade231(m): 1:33pm On Nov 26, 2015 |
kadunasouth: Baba kadunasouth eku ise takun takun o,eledua yio ma ran yin se o ase ni tedumare,ejowo mofe oogun ti eeyan le lo fun obinrin ti nkan osu re nle ojo ti o si je pe ki ri be tele,sogbon awon igba kan wa ti oje pe laarin osu merin si marun ole mari rara ti yio ba si ri nigba miran o le je ojo meta sugbon eleyi ti o nse lowo bayi ti nlo bi ojo meje abi mejo bayi,ejowo mofi eledua beyin ni ki e fun mi ni oogun ti a le lo si ti o ba wa,ma ma reti esi yin ojo.ese pupo ao ma ri yin ba ni agbara olorun,ase. |
Re: .. by fbabs(m): 2:31pm On Nov 26, 2015 |
healthFirst:. Se a o da tinu eyin nu ni abi ao ko ni da tinu eyin nu 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 3:25pm On Nov 26, 2015 |
fbabs: Rara o...eo re oruka yen snu e ni o pelu awon eroja to ku. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 3:30pm On Nov 26, 2015 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 3:52pm On Nov 26, 2015 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 4:28pm On Nov 26, 2015 |
x 1 Like 1 Share |
Re: .. by scholes0(m): 5:19pm On Nov 26, 2015 |
Ifadamilola30: Se Aiyan ni tabi Aayan? 1 Like |
Re: .. by lanjum(f): 8:57pm On Nov 26, 2015 |
E jowo o kinni eniyan le lo nigbati Ato omokunri ko ba le domo. |
Re: .. by kadunasouth(m): 9:50pm On Nov 26, 2015 |
Eyonu Ebe Awon Agba Igi Asorin(igi nla)) epo obo iye igun akopa eyokan ao lo gbogbore ti yio kuna ao wa dasinu adi eyan ao ma fi para odaju sugbon oni eewo eyokan ijo kijo tabati lo ise yi akogbodo lo turare yala fi para abi fi saso odaju 3 Likes |
Re: .. by bwayomide: 10:23pm On Nov 26, 2015 |
adagba yowokowo olohun o ni fi si inu oro yin baba,mo dupe fun idahun yin si ibere mi,mo dupe lowo olohun ati eyin baba mejeji ti e ntowa sonan,mo nri iyato ninu aye mi lowolowo,e jo ohun ti o ku fun mi ni alanu ati aranse,e jo baba,inu mi adun gidigidi ti e ba le fun mi ni ogun ti eeyan fi nri alanu.e sehun baba.olohun a ran yin lowo ooooooo. 1 Like |
Re: .. by BookieMan: 10:37pm On Nov 26, 2015 |
kadunasouth: . Pardon my use of English. Sir, may God bless you for the good work but kindly avail us the use of comma to separate each and every items from each other. Makes it easier to buy from the elewe omos. |
Re: .. by Ifadamilola30: 11:22pm On Nov 26, 2015 |
healthFirst: Adura yin a gba, baba!! Edumare koni fiyin sile! E jowo iru osun wo ni osun abalaye?? 1 Like |
Re: .. by Ifadamilola30: 11:28pm On Nov 26, 2015 |
scholes0: Inkankan na ni!! |
Re: .. by omoalade144(m): 1:54pm On Nov 27, 2015 |
Moki gbogbo awo ati awa ogberi lori owu yio.Ejoo moni ibere pataki kan ti mofe bere o.Ejoo se awo ifa na ni awo tangaran atipe kini oruko miran ti awo tangaran nje |
Re: .. by Nobody: 2:19pm On Nov 27, 2015 |
Ifadamilola30: E beere lowo awon elewe omo. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 2:23pm On Nov 27, 2015 |
lanjum: A ko le dahun ibeere yin pelu Oogun kan pato...stages ni aisan low sperm count lara okunrin ati wipe, o je dandan ka koko treat aisan to fa aisan low sperm count ki a to le fun iru eni bee loogun low sperm count, bi beeko, yio kan ma lo oogun lasan ni. E kan si mi lori e-mail mi(check the first page for my e-mail) 1 Like |
Re: .. by omoalade144(m): 6:15pm On Nov 27, 2015 |
ejoo se awo ifa ni awo tangaran ni |
Re: .. by Snowealth: 7:35pm On Nov 27, 2015 |
E jowo mo ni lo atuwo to lagbara fun eniyan ti aye n da laamu, to be ti ise re daru. E jowo e fi ran mi lowo. |
Re: .. by mondaylyno(m): 10:14pm On Nov 27, 2015 |
Baba ejo se mole ri ogun ti oko okunrin yho fi gborin dada yato si eyi ti efum waBaba ejo se mole ri ogun ti oko okunrin yho fi gborin dada yato si eyi ti efum waBaba ejo se mole ri ogun ti oko okunrin yho fi gborin dada yato si eyi ti efum wa |
Re: .. by Sobandemojisola: 6:44am On Nov 28, 2015 |
mi |
Re: .. by ayokomi1010(m): 10:23am On Nov 28, 2015 |
Aye mojuba o,moki gbogbo ojogbon ti olorun ni Ki won mafi tewetegbo se Omo araye lore,e Jo mobere Ogun kan tosi dunmi lokan,e si Dami loun ejowo mofi olodumare be gbogbo ile,Ogun na nipe ti nkan Omo kunrin ba kere ju OJO ori re lo,atipe oyun funfun Jade ni nu nkan omokunrin re,Ki le Ba obinrin lajosepo ju ekanlo ti a fi sunlo,kini mole lofun ejowo,baba ati gbogbo ojogbon e sanumi |
Re: .. by Nobody: 2:08pm On Nov 28, 2015 |
. |
Re: .. by Aluqman(m): 9:31pm On Nov 28, 2015 |
e dakun irufe oruka wo la le lo fun ise yi, se oruka irin ni abi eyikeyi. e seun |
Re: .. by Aluqman(m): 9:49am On Nov 29, 2015 |
healthFirst: eku owuro o baba, mo n fe alaye lori egbogi yi daa daa mo fun eni mi kan kosi ri ise re. Mo lero wipe ko se ise na daadaa ni. Iru oruka wo ni ale lo se oruka irin ni abi eyikeyi, ti eyin adie na ba fo nigba ti aba fe yo jade leyin ojo meje se ko bawi. A ma ri yin ba o. |
Re: .. by Aluqman(m): 10:32am On Nov 29, 2015 |
Iba Akoda Iba aseda. Iba Agba Iba omode Iba okunrin Iba obinrin Iba onile Iba alejo eje ko ju wa se o. ONFA RIRISE (ITAJA) A o pa omo onile kan iru re ko gbodo ge, a o so sinu ado kekere a o fi isebe die si a o fi paper di enu ado na, a o we ni owu dudu ati funfun fifi ko si enu ona shop tabi ile itaja. Egbogi yi kere amoo aje bi idan ni. Iba Agba o. |
Re: .. by Aluqman(m): 10:33am On Nov 29, 2015 |
Iba Akoda Iba aseda. Iba Agba Iba omode Iba okunrin Iba obinrin Iba onile Iba alejo eje ko ju wa se o. 1. ONFA RIRISE (ITAJA) A o pa omo onile kan iru re ko gbodo ge, a o so sinu ado kekere a o fi isebe die si a o fi paper di enu ado na, a o we ni owu dudu ati funfun fifi ko si enu ona shop tabi ile itaja. Egbogi yi kere amoo aje bi idan ni. Iba Agba o. |
Re: .. by kadunasouth(m): 11:34am On Nov 29, 2015 |
Ade231:Ogun to wa nisale yi egbiyanju kese gbogbo arun toropo ma nkan osu obinrin kia kia iwosan ati alafia yio de ba ni kia kia koda eni tiko se nkan osuri to ba ni anfani lati lo ogu yi kia kia ni yio bere si se nkan osu, nkan osu yio wa lasiko toye yio si mowo duro lasiko toye ogun Obinrin ti kori nkan osure Tabi orun tabi onse segesege Egbo paran pupa ati paran funfun ati bara nla kan ati enu opiye ose dudu bi oni 100 naira tabi 50naira babase fe kiopo si ni ati kanhun bilala epo osan wewe tabi kage osan wewe si meji meji ao jo papo yio month fi omin oronbo wewe mu ogun yi daju saka Otun sise fun atosi, Aremo ati obinrin ti inu ma nrun lasiko to nse nkan osure odaju odaju NB ta base ogun yi tan ao bu sibi meji sinu igo oronbo kan yio mamun dede cup toma nwa ninu schinap aimaye eyan lolelo ninu iseyi. 2 Likes |
(1) (2) (3) ... (32) (33) (34) (35) (36) (37) (38) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 43 |