Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,200,735 members, 7,975,812 topics. Date: Tuesday, 15 October 2024 at 01:16 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1843485 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (35) (36) (37) (38) (39) (40) (41) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by Nobody: 6:51pm On Dec 04, 2015 |
ayokomi1010: Emi o ni ba e ja iyan rara, sugbon mase post anything that has to do with Eran Nla again...to ba mo Yoruba ko tabi inu account to ti ko sita ni won ti si ko...Eran Ajiyo ni awon agba npe ni Eran Nla...so ti gbo. To ba je Eran Erin lo fe ko, ko Eran Erin sibe. inkan oto patapata gba ni Eran Nla. 6 Likes |
Re: .. by dosht(f): 8:28pm On Dec 04, 2015 |
ayokomi1010:Just modify your post and write 'eran erin' Nigbati emi gan ri eran nla Moro bi eran malu ni |
Re: .. by Aluqman(m): 8:34pm On Dec 04, 2015 |
Ekale o baba. Ejowo eni to on se egbogi fun ra re ti ko je fun iru oni ton ki lo le lo fun jije ewe ati egbo. eseun o, ewe ama je o. |
Re: .. by KolaBELIEVE: 8:38pm On Dec 04, 2015 |
healthFirst:ejowo se ori oka toni iru re lenu ni? 1 Like |
Re: .. by Aluqman(m): 8:39pm On Dec 04, 2015 |
Baba Health first ati Baba Kadunasouth
Ekale o baba. Ejowo eni to on se egbogi fun
ra re ti ko je fun iru oni ton ki lo le lo fun jije
ewe ati egbo. eseun o, ewe ama je o. |
Re: .. by KolaBELIEVE: 9:12pm On Dec 04, 2015 |
kadunasouth:ejowo sir se kosi nkan ti yo se awon omo enitoba lo ise yi? Iba ooo 1 Like |
Re: .. by KolaBELIEVE: 9:31pm On Dec 04, 2015 |
kadunasouth:pls sir kadunasouth i need something to get good job am a graduate pls God bless u. Ewe ama je ooooo |
Re: .. by Nobody: 9:58pm On Dec 04, 2015 |
Aluqman: E lo ma koko lo Ajeegun na ki e to se oogun kankan. Sugbon to ba je wipe awon agba ni o je ki oogun je fun yin, e need lati se Etutu fun won pelu Imule Agba, bi beeko, eo kan ma lo Oogun lasan ni, ko ni sise. 4 Likes |
Re: .. by Nobody: 9:58pm On Dec 04, 2015 |
KolaBELIEVE: Beeni. |
Re: .. by opeey360(m): 9:58pm On Dec 04, 2015 |
Iba |
Re: .. by Oluokunoluwole: 11:06pm On Dec 04, 2015 |
Ejowo baba healthfirst kadunasouth mo nilo bi eeyan sele se ipese etutu ebe awon agba,e ran mi lowo ooooo |
Re: .. by Nobody: 12:24am On Dec 05, 2015 |
Oluokunoluwole: Se e ti se iwadi ti won ti so fun yin pe Etutu ni ke lo se? Ni opolopo igba, o ye ki a beere lowo Ifa lati mo iru Etutu pato ti won yio gba lowo yin...opolopo igba ni o je wipe bi ao ba se iwadi ti a kan lo se Etutu, won o ni gba. Ma gba yin niyanju lati lo se iwadi ki e to soro nipa Etutu. |
Re: .. by ayokomi1010(m): 1:29am On Dec 05, 2015 |
kilode ti eyin eniyan ma tan Awon eniyan je ri,won kipe ajata ajiyo ni eran NLA ni odo Awon agba ife e ma serantipe odua o fe iro, eje Ki a se Awon eniyan lore tori ola, elowo gbogbo oun ti Mo post lori ikanni yi baba eleba ise buburu nibe,Awo ire lawa,boya keso pato pe bi won se pe ajata lodo tiyin nu,mise ota yi rara o,emi asi mako ogbon Mo ogbon ni, oruko meta ni afi pe Erin lodo tiwa ajinaku Eran NLA, oun ti Awon baba tiwa fipe ni eran NLA nipe ti eba pa Erin lodo tiwa won a ni Ki logun pa won a ni eran NLA,tori kosi iru eran Igbo teni ba lara re,emaje kama kabuku arawa kama fi ona ogbon han arawa loto ,ese ifa kan wipe okan nikun awodi okan nikun Omo ASA,kaluku lajo ni OKokan Ni kun, kabiye si o 1 Like |
Re: .. by rsedo: 8:14am On Dec 05, 2015 |
[quote author=kadunasouth post=33530358][/quote] Ese lopolopo.... I'll try it |
Re: .. by rsedo: 8:15am On Dec 05, 2015 |
ayokomi1010: Ese lopolopo.. I'll try it |
Re: .. by Ifadamilola30: 9:25am On Dec 05, 2015 |
Mo ki gbogbo ile, e dakun iru ewe wo ni won npe ni "Ewe La"?? E dakun se Ewe Lapalapa ni abi iru ewe wo ni Eyin awo E dakun e tomi sona!! Awon onile yio gbeyin!! Ewe a ma je!! |
Re: .. by Shomar: 10:55am On Dec 05, 2015 |
[color=#000099][/color] healthFirst: healthFirst: healthFirst: E seun Baba fun idahun si ibere yi toripe emi na ti bere irufe ibere yi. Siwaju si. Yoruba bo, won ni AGBATAN LA'GBO LE. E jo sir. Irufe IMULE ati EBE wo ni e ma fun wa lati se. Odua a gbe wa si rere o o o |
Re: .. by Shomar: 11:01am On Dec 05, 2015 |
[/quote][i][quote author=healthFirst post=40696185] E seun Baba fun idahun si ibere yi toripe emi na ti bere irufe ibere yi. Siwaju si. Yoruba bo, won ni AGBATAN LA'GBO LE. E jo sir. Irufe IMULE ati EBE wo ni e ma fun wa lati se. Odua a gbe wa si rere o o o |
Re: .. by Nobody: 11:14am On Dec 05, 2015 |
healthFirst: BABA MI...HEALTHFIRST...EJO WO TORI TELEDUA E FUN MI NI OGUN TO MA MUN OKO OLOMOKURIN TO KERE TI O FI TOBI?...EJO....ELEDUA KO NI JE KI IKAN AYO YIN DI IBANUJE. PLS DADDY |
Re: .. by Youceemeri: 1:07pm On Dec 05, 2015 |
WiLdFLame: |
Re: .. by Oluokunoluwole: 3:08pm On Dec 05, 2015 |
healthFirst: 1 Like |
Re: .. by omoalade144(m): 10:31pm On Dec 05, 2015 |
ejoo sir baba helthfirst e funmi ni ogun ako jedi |
Re: .. by Oluokunoluwole: 10:48pm On Dec 05, 2015 |
Baba moti se iwadi tele,ejowo eran mi lowo |
Re: .. by Oluokunoluwole: 10:51pm On Dec 05, 2015 |
Won ni ki nru ebo fun awon agba ati omo emere kan ti moferi erami lowo |
Re: .. by dotsdavidson(m): 5:40am On Dec 06, 2015 |
healthFirst: E Ku ise Baba, e jo ise wo ni eyi nse? 1 Like |
Re: .. by dotsdavidson(m): 5:47am On Dec 06, 2015 |
healthFirst: A ma ju yin se o baba, e jowo bawo ni e se le bami se ise yi? 2 Likes |
Re: .. by OPCNAIRALAND: 11:15am On Dec 06, 2015 |
Agoo o! Eku kaale o! Aki yin, eku se, eku eyan, ewe a jee o! Mo n ka ninu awon idahun ti e ti ko koja, nise ni mo nbu s'erin. . Mo gbadun imoran yin ati pe e tun fi oyaya se pelu. Aapere: ninu idahun gbehin nibi te wi pe "ihoho omoluabi". Lol, nise ni mo tun bu erin.. Ema binu si ibere mi o, n je ihoho kan tun wa ti eya re ya'to, to ba kuro ni t'omoluabi? Ooduwa agbe wa o! Ooni ma gun ori oye ni imole ola , Adimula aagbe wa nigbogbo igberigbe omo Yoruba kaakiri agbaye, Ase Edumare! 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 3:47pm On Dec 06, 2015 |
OPCNAIRALAND: Bi won se ma n so Yooba e niyen...Ihooho Omoluabi. |
Re: .. by Nobody: 3:48pm On Dec 06, 2015 |
dotsdavidson: E kan si mi lori e-mail tabi whatsaap |
Re: .. by Nobody: 3:49pm On Dec 06, 2015 |
dotsdavidson: Bi awon agba ba n binu si wa ni ise yi wa fun. |
Re: .. by Nobody: 3:49pm On Dec 06, 2015 |
Oluokunoluwole: E kan si mi lori e-mail |
Re: .. by Nobody: 3:53pm On Dec 06, 2015 |
omoalade144: JEDIJEDI Elo wa Egbo Igi Udi...ke ge keekeke sinu omi fun ojo meta, lehin ojo meta, eo ma mun laaro, losan ati lale ni ife kan. 3 Likes 1 Share |
(1) (2) (3) ... (35) (36) (37) (38) (39) (40) (41) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 55 |