Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,227,673 members, 8,071,211 topics. Date: Wednesday, 05 February 2025 at 05:06 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju (569456 Views)
Civil Servant Killed By Thunder In Oro, Kwara (Photos) / Ogun Ibile To Daju / The Bad Shape Of Oro General Hospital, Kwara State (Exclusive Photos) (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (27) (Reply) (Go Down)
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by KolaBELIEVE: 9:14pm On Jan 15, 2016 |
kadunasouth:se aro la o ma lo ni abi ale? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:22pm On Jan 15, 2016 |
KolaBELIEVE:Igba kugba |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:43pm On Jan 17, 2016 |
Ogun Awure owo Odidi eye ega kan ikode meta ao ki ikode kan bo lenu ao fi ikan si apa otun ikan ni apa osi ao jo pelu odidi atare kan ao lo ao pin si ona meje ao wa mafi foko mu lararo fun ojo meje opari 4 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:40am On Jan 18, 2016 |
Awure owo kia kia Ao wa awo lili to lori ao ki 1000 naira bo inure pelu odidi atare ao gbe si inu isasun ao majo tobati jotan ao wa da ewe ola sibi kan si ao lo yio kuna ao ma fi ro ekuru fifun je lalale lowo bade NB ao jeki ewe ola yi najo kato sokale odaju 4 Likes 3 Shares |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by KolaBELIEVE: 11:09am On Jan 18, 2016 |
kadunasouth:ejowo ema binu sa, se ale jo ise (ogun) lori stove? 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by KolaBELIEVE: 11:23am On Jan 18, 2016 |
kadunasouth:e seun sir, se ti awo Lilli yi bajotan la ma to jo ewe ola? 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 3:11pm On Jan 18, 2016 |
KolaBELIEVE:Beeni 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 3:14pm On Jan 18, 2016 |
KolaBELIEVE:Tobati fejo tan ni wada ewe ola si yio wa jo papo, so that ewe ola na koni le jo di eru, so yewa bayi? 3 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Lionhearted: 3:51pm On Jan 18, 2016 |
kadunasouth: Se ise yi koni eewo tabi ewu nijo iwaju? 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by baby124: 4:39pm On Jan 18, 2016 |
Wow... All the incantations for every kind of jazz. Where lalasticlala. Some heavy babalawo de NL o. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by baby124: 4:43pm On Jan 18, 2016 |
kadunasouth:Orisirisi 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 8:11pm On Jan 18, 2016 |
baby124:becareful with this people no be play play o! is an advise 3 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by comffy(f): 9:09am On Jan 19, 2016 |
[quote author=kadunasouth post=40596101]Ogun ito sugar Eso ewe oyo agolo kan ao gun yio kuna dada ao ma fi sibi omo arobo bu sinu lipton tea aro osan ale leyin osekan kalo se ayewo yio ti wale dada Baba E ku ise ooo. Edumare a pin yin lere. E jowo baba, se ewe oyo(ewedu ni)? E se baba 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Zenlife: 2:32pm On Jan 19, 2016 |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:28pm On Jan 19, 2016 |
[quote author=comffy post=42117227][/quote] Beeni |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:52pm On Jan 19, 2016 |
Asina/Isegun ota Eye onbe meta oko atare meta ao jo onbe eyo kan pelu oko atare kan ao lo loto bayi ni ao se se meteta ao walo fun ojo meta, taba fe fi ise yi wa owo ni kan owuro lao malo pelu miliki tabi omi tutu to base isegun ati ebe lafe lofun ao fi foko mun sun lalale fun ojo meta opari 5 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:09am On Jan 20, 2016 |
Ogun Ta nfi ba Aburuje Lago arawa Odidi agban kan ao jo omire sinu koko isasun ao wa fi ekiri eran malu kan si ao se yio jin na ao so senu lekan na ao je opari 6 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:06pm On Jan 21, 2016 |
Ogun Awure Ayigba pada sirere Imi malu(igbe malu) ao sa yio gbe ao lopo month epo obo ao po ma ose dudu ao ma fiwe pelu gbolohun re Imi nla nla ni malu su owo nlala ni kiwan oma gbewa funmi ki ona si ki ona ola fun mi, imi nlanla ni malu su, obo loni ki tomode tagba to lowo lowo wama fi owo owoyin bomi kie wa mabe mi ni ise nlanla tabi gbe ise nlala funmi bi contract etc Ao wa ma fiwe odaju 4 Likes 3 Shares |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by heritagesat: 11:28pm On Jan 21, 2016 |
Baba edakun e fun mi ni aworo ti mole lo si ile ball (view center) a wa merin ni a wa ni agbegbe na sungbon to je wi pe won maa park (car ati manchine) si odo a won iyo ku ti emi ki si ta rara |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by KolaBELIEVE: 12:33pm On Jan 22, 2016 |
kadunasouth:ejowo sir, se igbe malu die ni abi odidi igbe malu? 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 5:04pm On Jan 22, 2016 |
KolaBELIEVE:Niwanba die tabi kie wa pupo kie lopamo tori lili ni igba miran eo sa tio gbe dada ao wa lo lubulubu bi elubo ao ma bu bi sibikan gun ose pelu epo obo, ise na dara pupo 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by KolaBELIEVE: 7:50pm On Jan 22, 2016 |
kadunasouth:ema binu baba Kadunasouth, se ama so gbolohun yi si ose na ni, abi ao so ti aban we ose na lowo? 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:39pm On Jan 22, 2016 |
KolaBELIEVE:Ti anba nwe lowo lao maso atun ma wure opolopo adua 4 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ousmaf(m): 7:20pm On Jan 23, 2016 |
kadunasouth:ejo baba se dandan ni kalo ose dudu abi ale lo ose miran, eseun. 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:25pm On Jan 23, 2016 |
Iferan (General love) Itun ati ifa, abere, ewe ola, itanna tanapowo ao lo gbogbo re papo ao pomo ipara ao fi turare toba lorun to dara si ao popo ao ma fi para, opo eniyan lelo 3 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Nobody: 10:28am On Jan 24, 2016 |
kadunasouth: Baba, nje eyi le sise fun omo ile iwe ti ko ni ise lowo? 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 12:31pm On Jan 24, 2016 |
ẸYỌNU AWỌN AGBA Ifunni ekete kan, egbo akerejupon , ati ewe ajẹọbale, ao jo papọ̀, ao po ma ọṣẹ dudu oni apo nkan, ao ma fiwẹ leralera. 5 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ifadamilola30: 3:14pm On Jan 24, 2016 |
kadunasouth: Baba mi, e dakun se a ma fi ikode kookan to ku ha apa eye yi kookan ni?? Abi bawo ni sir?? 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 8:22am On Jan 25, 2016 |
Ifadamilola30:molero wipe ama fi ha lapa ni tori emigan fe bere, sugbon motise mokibo apare no,mofi ha lapa ni |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 1:47pm On Jan 25, 2016 |
Ifadamilola30:Beeni. Ao fi ha lapa mejeji ikan lapa otun ikan lapa osi 4 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:17pm On Jan 25, 2016 |
Atude Asina Omundun ewe akoko 9 ata ijosi eyokan ao gun papo ma ose talewe tan lekan soso ao fiwe 5 Likes 1 Share |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (27) (Reply)
Causes Of Seeing Menstrual Period Twice A Month / Postinor 2 - How Effective Is It? / Doctor in the House: Free Medical Advice Available
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2025 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 50 |