Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,193,302 members, 7,950,554 topics. Date: Monday, 16 September 2024 at 04:27 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju (565079 Views)
Civil Servant Killed By Thunder In Oro, Kwara (Photos) / Ogun Ibile To Daju / The Bad Shape Of Oro General Hospital, Kwara State (Exclusive Photos) (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (27) (Reply) (Go Down)
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by belatoxx: 7:21pm On Feb 20, 2016 |
@dominique se i wo le fi oyinbo pe ofo tabi ayajo to ba ri be bo ya i wo ni o ma se ayan - ogbufo fun awon oloyinbo egbe re......omo yoruba ni wa ni fonran yi 3 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Kollyk11(m): 12:45pm On Feb 21, 2016 |
ajinde ara yio maa je ooo.aye oni pa yin ti bi aso to ti gbo ooo.ejo baba kadunasouth.mo ti ni aru ulcer ati iba lati nkan bi last may.ko si nkan ti mi o ti lo amo pabo loun jasi.bi ki ori ma fomi legbe kan ati eyin ju .ara atun ma gbona laro kutu.o ma n re mi ni gbogbo igba.ejo kini ero pe oun se mi ati kini mo le lo.e seun oooo |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:52pm On Feb 21, 2016 |
Kollyk11: Ogun ulcer todaju Aidan bi meta eo wafi obe ge isu arare eo so iyoku nu eo ko si inu roba kan totobi niwan ba eo wa ko ose bi oni 50 naira eo da meji idakan oseyi eo kosi eo wa bu omisi eo gbe kale di ojo keji eo wa mafi tele inu lararo keto jehun eo tun ma mun die die teba felosun yio lo patapata tie ko ni gburo remo lase eledumare tolaye ati orun Iba eyin agbagba o! 5 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 2:51am On Feb 23, 2016 |
Ogun Atude Ituwo tiwan bade owo eniyan mejeji Odidi bara kan ao gesi 16 ao ko tele ape ao wa gbe ori musu tonirun le lori ao fi odidi atare kan si legbe ao jo ao popo ma ose ao mafi we owowa mejeji Iba akoda iba aseda iba eyin aye ewa tumi nide edi kidi bara ki gbogbo ide owomi kotu danu ki owo mi bere si ya fun owo nlala ki magba Ogorun eyan lelo oseyi Moju ba re olodumare 4 Likes 2 Shares |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by systembayo: 6:52am On Feb 23, 2016 |
baba ejo ki ni Ogun ti Omo university le se tio fi ma ri owo school san.monise lowo sugbon ko si ise ejo aranmi lowo emaje ki won le ni school.ejo ooooo. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by possible26: 10:12am On Feb 23, 2016 |
BABA e jowo mo need oogun quick expulsion |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by dominique(f): 10:38am On Feb 23, 2016 |
belatoxx: Itumo pls |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ALIUDAVID: 7:23pm On Feb 23, 2016 |
Baba kadunasouth ati gbogbo omo awo ejo oruko wo lon pe ewe 'rekureku" iba agbagba |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:38pm On Feb 23, 2016 |
systembayo:Ewe ata epo obo ao lo kuna dada ao gun po month ose dudu ao ma fi epo pupa para kato lore we oseyi asiri obo latima san owo yi pelu ase oloun 5 Likes 2 Shares |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by systembayo: 3:26pm On Feb 24, 2016 |
e se ga nio olohun aba mj dupe fun yin oooo mudupe |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by belatoxx: 4:17pm On Feb 24, 2016 |
kadunasouth: Baba ke pe fun wa e jowo se ise yi ko ni ipa lara ati wipe se ako ni ma ri alujonu ti yo ya onitoun ni were ese pupo. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 5:35pm On Feb 24, 2016 |
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye, opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ajuwase'o 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:52pm On Feb 24, 2016 |
Ogun ito sugar Iru woro ao ko tele koko ao wa ko ewe ewuro bo mole ao bu omi si ao se dada ao ma mun Ogun ito sugar odaju Ewe efirinla ewe gova ewe ejirin ao ko gbogbo re sinu koko ao bu omisi ao se dada leyin ose meji ta nba lo ogun yi dada laro ati ale ki alo se ayewo wanko ni ri sugar lara wa mo 5 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ALIUDAVID: 9:54pm On Feb 24, 2016 |
Ekale o, ejo oruko wo ni won tun pe
ewe 'rekunrekun' iba eyin ti olorun
gbe ase ile aye fun. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ALIUDAVID: 9:55pm On Feb 24, 2016 |
Ekale o, ejo oruko wo ni won tun pe
ewe 'rekunrekun' iba eyin ti olorun
gbe ase ile aye fun. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ALIUDAVID: 9:56pm On Feb 24, 2016 |
Ekale o, ejo oruko wo ni won tun pe
ewe 'rekunrekun' iba eyin ti olorun
gbe ase ile aye fun. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by belatoxx: 10:18pm On Feb 24, 2016 |
Baba ejowo ki ni a le lo si atosi ojo pipe mo ti lo orisirisi ogun e jowo e sa nu fun mi. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:31am On Feb 25, 2016 |
ALIUDAVID:Ewe na oloruko meji rekureku kifa kokoja ona Ewe na common lodo awan elewe omo eko sinu pepa ewe rekureku ki efun wan, wan ofun yin 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by belatoxx: 10:12am On Feb 25, 2016 |
Baba ejowo ki ni a le lo si atosi ojo pipe mo ti lo orisirisi ogun e jowo e sa nu fun mi. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 12:02pm On Feb 27, 2016 |
Turare Aworo Epa to ni epo lara tanti yan ewe omisimisi gogoro ao gun papo ao ma fi ni turare pelu ogunna 4 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 3:59pm On Feb 27, 2016 |
Ose Awure Ewe rere tako tabo ao gun yio kuna ito idi eni lao fi pomo ose dudu ao ma fiwe. Ofore Ojo ni oro ito mule ki oromi komu okunrin ati obinrin kiwan kowo wa funmi kiwon wa bunmi lowo . Ike ati ola olorun kolore ba eni ti oloun torire da ewe ati egbo 5 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by bgates: 6:07pm On Feb 27, 2016 |
Translate small for us Please oo |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 12:37pm On Feb 28, 2016 |
Agbo Gbogbonise Epo aganho, epo Afara, Epo igi pandoro ao wa ki gbogbore lagbo ao ma yomu diedie ao ma bu omin si ao ma gbe kana titi di bi osu kan tabi jubelo kotosa 3 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by belatoxx: 12:48pm On Feb 28, 2016 |
Babakadunasouth ejowo ki ni a le lo si atosi ojo pipe mo ti lo orisirisi ogun e jowo e sa nu fun mi. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 1:03pm On Feb 28, 2016 |
Ogun Promotion (Agbega lenu ise) Ori Asa awodi, Awo ekun odidi atare ao jo ao fi sin gbere 61 si ori iyoku ao fi oyin la tan patapata odaju osi dara pupo Iba fun alaye lorun (s.a.w)ti gbogbo aye wari fun iba fun umul li abati(aramu alai naru kolibu habahu) iba awan agbagba ti wan ti ile ife oye wasaye, iba fun gbogbo emi toma kanga kanga, iba emi keji moju bao ema pada leyin mi eje ki ojumi se. Amin 4 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by belatoxx: 1:13pm On Feb 28, 2016 |
Babakadunasouth ejowo ki ni a le lo si atosi ojo pipe mo ti lo orisirisi ogun e jowo e sa nu fun mi. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 1:18pm On Feb 28, 2016 |
belatoxx: Ewe erunyantefe pelu odidi atare kan ao jo emafi omi bore hole lo tabi omin ojo eko gbodo lo omi tap o! Eo ma lo die die leyin tati lo to kuna dada 2 Kanafuru pelu obi gidi kan ati kafura die elo kuna eo ma kanda si enu teba fesun ati kie to jeun lararo die die 3 Egbo sapo epa ikun ati eso bara eo fi omin didun se eo ma mun lojojumo 4 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by possible26: 3:33pm On Feb 28, 2016 |
kadunasouth: BABA ejowo e fun mi ogun premature ejaculation |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ONILEIFA: 3:35pm On Feb 28, 2016 |
*OGUN ARUNMOLEEGUN* ANY OF THESE:- 1. eku aisan, Aidan, ipeta, iroyin,epo igi boni, ao gun won papo mo ose dudu, wiwe nio. 2. Egbo owo, ata dudu, alubosa jije, ao gun papo, ao wa sagbe, ao mafi mu eko. 3. epo igi Omo, ewe ekanse adie, ao se, mimu ati wiwe. Fun Alaye Kikun Ekan si mi 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ONILEIFA: 3:39pm On Feb 28, 2016 |
[AGADAGODO TI KIIJE KENU ENU ENIYAN KO Iye igun, iye agbe, ...Ekan si mi ..., etu ibon die[not original one], atare odindin kan, ao jo po, ao waabu sinu efe owu. ao fi owu dudu ati funfun we. ao waa so mo agadagodo. *OFORE* Moda ofa meta mo mu ikan mofita igun, igun ni enu won koni gun, modafa meta mo mu ...efi number sile fun iyoku....., modafa meta mo mu ikan mofita agbe lenu, agbe loni odi igbo rere, etu loni kiwon tuka. Aye wa fun ibere tabi so unkan ti oba ru yin ni oju. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by geejayjax: 6:14pm On Feb 28, 2016 |
kadunasouth: Pls can you post what u wrote in English... Pls, I didn't understand it... My ulcer has reduce but the back pain it caused is still slightly there .. Thank you |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:54pm On Feb 28, 2016 |
geejayjax:Copy it out and take it to elewe omo u can't spend more than 300 give then five hundred to bust their moral they will prepare it for u and take it morning and night very effective 4 Likes 1 Share |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (27) (Reply)
Causes Of Seeing Menstrual Period Twice A Month / Postinor 2 - How Effective Is It? / Doctor in the House: Free Medical Advice Available
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 57 |