Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,193,375 members, 7,950,793 topics. Date: Monday, 16 September 2024 at 10:17 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju (565092 Views)
Civil Servant Killed By Thunder In Oro, Kwara (Photos) / Ogun Ibile To Daju / The Bad Shape Of Oro General Hospital, Kwara State (Exclusive Photos) (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) ... (27) (Reply) (Go Down)
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:58pm On Feb 28, 2016 |
possible26:Ewe lapalapa funfun ati pupa ewe egele funfun ao gbo dada ao se ao ma mun laro ati ale NB ewe egele yi kiki egun ni gbogbo arare ale ko gbogbore sinu odo kagun kia bu omi si dada ki awa se pelu ase tabi ki aki ora toba lagbara bowo kafi gbo odara 5 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by admolfemx(m): 10:20pm On Feb 28, 2016 |
kadunasouth:Baba kadunasouth e kale o,olorun yio ma wa pelu yin o amin.ibere mi ni wipe e jo bawo ni mo se lewo akosejaye eni ati pe iru igbese wo ni mole gbe lati wo,ejo eran mi lowo fun ibere mi yii,e se pupo. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Zenlife: 10:45pm On Feb 28, 2016 |
Baba, ejowo mo fe ki e bami se ise kan. Mo ni card fun yin lowo. Ago abanisoro yin o lo, se e o lo whatsapp mo ni? O se pataki gan. E jo ki e kan mi sori e-mail Ossezx@gmail.com |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by systembayo: 10:37am On Feb 29, 2016 |
baba ejo mo need Ogun eni to wa girl friend tabi iyawo.ewe amaje oooo |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by geejayjax: 2:25pm On Feb 29, 2016 |
kadunasouth:Pls, if u don't mind translate it. Thanks |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:16am On Mar 01, 2016 |
geejayjax:Translation of ogun is not allow on this thread 3 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:29am On Mar 01, 2016 |
Aseje Owo (money) Abo adie alawo meta(3 color) ao pa ao ge kekeke si ona to ba wuwa, iru iyere ata ijosi ewe ologosese ao gun gbogbo re ao fi se adie yi lepo niyo To ba tutu ao fi iyere osun te ifa eji ogbe ao pe ofore si ao dasi ao koje Arin igi oko lo longosese nti de ade tie gbogbo ibi ti month badurosi ni kiwan ti ma de mi ni ade owo nla nla, eji ogbe baba ifa wa gbe alanu temi komi nibi ti mobaduro si Ase 7 Likes 2 Shares |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by possible26: 1:08pm On Mar 01, 2016 |
BABA edakun e funwa no ogun iba jedojedo |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by systembayo: 3:36pm On Mar 01, 2016 |
baba ese fun ise ti efuwayi olorun aba wa dupe fun yi oooo |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Zenlife: 7:38am On Mar 02, 2016 |
Baba ejowo e funwa no oogun obinrin ti o yan ale pelu oogun awise. Adupe. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by wale259(m): 3:11pm On Mar 11, 2016 |
Sir,e ku atunse,olorun oba ko ni da ile ati ona yin ru,e jo month fe ki e salaye arin yi ni (toto ikuku to badi aru ao fise sara sita)ati wipe se a ma so igbin yen nu ni. kadunasouth: |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by wale259(m): 3:20pm On Mar 11, 2016 |
Baba,e jo kini itumo ki ma gba ogorun eyan lelo oseyi. kadunasouth: 1 Like 3 Shares |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 10:20am On Mar 12, 2016 |
wale259:baba Kaduna south means that ogorun eyan lelo(hundred people can use it) that many people can use the soap 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 5:40pm On Mar 12, 2016 |
Ogun iferan ki gbogbo aye le nife wa odidi eyele funfun,ao fi ori ra gbogbo arare, ewe alupayida ewe egele, ewe ewuro oojo, Odidi atare meta, a Jo gbogbo re po, a po mose ao tun fi ori die si, a maa fi we lararo. 5 Likes 3 Shares |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ousmaf(m): 12:36pm On Mar 13, 2016 |
kadunasouth: Ejo baba Agba yin a dale e o sini ri ogun akoba, oruko miran wo latule pe 'ewe ola', ese Olohun Oba to ga julo aman ran yin se, ameen. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 2:23pm On Mar 13, 2016 |
Ousmaf:Ewe oja tabi ewe igbo tiwan nmu 5 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by wale259(m): 5:12pm On Mar 13, 2016 |
Sir, e jo se inu fitila na lati ma lo kuna abi ale lo lori olo... kadunasouth: 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Seylad2009(m): 5:41pm On Mar 13, 2016 |
kadunasouth:E jo wo mo ni lati bayi soro lori ago. E Jo wo e fi numba iba araeni soro yin rese si mi lori seylad2009@gmail.com tabi 08066717262. Ese pupo |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Zenlife: 2:32am On Mar 14, 2016 |
kadunasouth: eiyele ti aye tabi to ti ku? 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:07am On Mar 14, 2016 |
Zenlife:Ao le mole ti yio ku le kanna tabi kadu sinu koko ijo nkan ao sese wa fi ori pa lara 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:38am On Mar 14, 2016 |
Seylad2009:09090305775 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by grinface98(m): 6:32am On Mar 15, 2016 |
kadunasouth:Ekaaro Baba Agba. Agba yin yio dale oo. E jowo mo nilo ILIAMU to daju gidigidi lati owo yin. Alfa ni mi ni Osun sugbon baruufu ni pupo ninu awon ILIAMU ti mo ni. Ese gaan baba. Ewe aje oo!! |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by wale259(m): 9:23am On Mar 15, 2016 |
Baba kaduna,e jo e fesi si ibeere mi yi...se inu fitila na lati ma lo kuna abi ale lo lori olo... wale259: |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:33am On Mar 15, 2016 |
wale259:Ale lo lori olo 3 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 11:39am On Mar 15, 2016 |
Ejo sir, kini oruko miran ti akopa jen? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 12:28pm On Mar 15, 2016 |
kadunasouth: Ejo sir, ki lo je igo ngori, e salaye? 1 Like 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 12:50pm On Mar 15, 2016 |
zenith329:Ododo ori re, flour to wa lori agogo igun, eo ri oun ma te condoro yio gun yio wa kako oun lema ja 99 3 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by wale259(m): 1:16pm On Mar 15, 2016 |
E jo sir,se opolopo eyan lelo. kadunasouth: |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 5:33pm On Mar 15, 2016 |
wale259:Beeni 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 9:45pm On Mar 15, 2016 |
kadunasouth:Ejowo baba kadunasouth, mo ti bere akopa lowo awon elewe omo sugbon woni awon ko mo ohun ti o jebe, ejowo sir, kini oruko miran ti akopa je? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:52pm On Mar 15, 2016 |
zenith329:Eye gunugun(eye igun) iye apare to gun dada ni wan peni akopa Eyokan ni wan ma bayin tu, wan sile ti tu kale fun tita 3 Likes 2 Shares |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Zenlife: 4:23am On Mar 16, 2016 |
kadunasouth: baba se ese mejeji ni a ma sin gbere eyokan si? Bo je okan, osi tabi otun? |
(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) ... (27) (Reply)
Causes Of Seeing Menstrual Period Twice A Month / Postinor 2 - How Effective Is It? / Doctor in the House: Free Medical Advice Available
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 42 |