Re: .. by Ifankaleluya: 1:48pm On Mar 04, 2016 |
Lero70:
alagba Olaifa atipe baba healtfirst ebajebure awoolugbebe keefi suuru gboraayin lagboye keesimaaranti oro eyinagba teewipe awooniitojuogberi dafanu laelae atipe eteawo erin ogberi nio torinaa efi suuru yanju gbogbo ohuntoba jebii ede-aiyede laarin yino isese a gbewa o. ''ki keke pa yin lenu'' eniti o kin n se babalawo,ko fo iru esi yen fun emi ti mo je babalawo,eyin o mo wipe ede abuku niyen. Idi ti mo fi fo esi niyen. I dnt av any personal issue with him. E seun modupe. |
Re: .. by Ifankaleluya: 1:54pm On Mar 04, 2016 |
[quote author=Lero70 post=43462848][/quote]
e dakun kin ni e-mail yin yen? Tori orisirisi e-mail lo wa lori e-mail mi. |
Re: .. by ONILEIFA: 2:02pm On Mar 04, 2016 |
Thank God truth will always reveal it self this man Ifankaleluya is a real devil and i know all he want to do is to spoil this page i wonder people like you still exist we called you the Destroyer cos you just come on this lovely page and spoil the good and fun of it, i know you will reply/quote me cos no words go on notice for you. But it better to create your own page and leave this alone Baba Health first use this page to help alot of people before you come here blab mouth like you are the real Orunmila. No one no it all that is why dem call it Ogun because it long and as a babalawo you call yourself you cant even recites all Odus so don't proof a King Kong. Let stop tis shit and move ahead if you have something good to share i repeat something good to share say it and stop insult no one know it all. |
Re: .. by Ifankaleluya: 2:54pm On Mar 04, 2016 |
ONILEIFA: Thank God truth will always reveal it self this man Ifankaleluya is a real devil and i know all he want to do is to spoil this page i wonder people like you still exist we called you the Destroyer cos you just come on this lovely page and spoil the good and fun of it, i know you will reply/quote me cos no words go on notice for you. But it better to create your own page and leave this alone Baba Health first use this page to help alot of people before you come here blab mouth like you are the real Orunmila. No one no it all that is why dem call it Ogun because it long and as a babalawo you call yourself you cant even recites all Odus so don't proof a King Kong. Let stop tis shit and move ahead if you have something good to share i repeat something good to share say it and stop insult no one know it all. I'l nt join any issue with you cos u'a nothing but jst a cockroach! I do not come here 2 obtained money from pple under the false pretence that am this nd that. I come here 2 shed-light. IWO-KE....IWO TI O TI E MO OJU-ODU NI MA MA BA SORO. Hiss!! |
Re: .. by Lero70: 4:26pm On Mar 04, 2016 |
Ifankaleluya:
e dakun kin ni e-mail yin yen? Tori orisirisi e-mail lo wa lori e-mail mi. ( tailadoriginal@gmail.com ) Aboruboye o baba Olaifa, esee pupo o motiri esi ti efiranse simi Eledumare yo maa tiyinleyin eesiniisaseti lagbara Olorun. Moni awon ibeere bii melo kan timofe beere, inumiosidun teeba damilohun lekunrere. 1. Iru awo wo ni anpeni ABOKADELE? 2. Kinni owa ninu alafo mejeeji teefisi isale yi IMULE AWON AJE TO DAJU ABO ADIE TO DUDU TIKO NI AMI KANKAN, IKODE KAN,OBI-IFIN,OBI-IPA,TEWE-TEGBO AJEOBALE,IGBA OLOMORI ATI ........., AO LO WA EGBO AJEOBALE YEN NI ARO KUTU-KUTU,AO WA FI EGBO YEN WON IKA-ARIN WA,AO GE SI META,AO YA AWE-KAN NIBI OBI-IPA,AO GE SI MARUN,AO YA AWE KAN NIBI OBI-IFIN AO GE SI MERIN. AO KO EGBO TI A GE SI META YEN TELE IGBA,AO DA AWON OBI TI A GE YEN SI,AO FI IKODE YEN ATI EWE........,AO WA KO. 3. Se egbo ajeofole ti ogunto ika-aarin ni a o ge meta re, abi eyokan tia bati fiwon ika-aarin yen naa ni amaa ge si meta? Eseun pupo o, unomaa reti esi yin |
Re: .. by Ifankaleluya: 5:22pm On Mar 04, 2016 |
Lero70:
( tailadoriginal@gmail.com ) Aboruboye o baba Olaifa, esee pupo o motiri esi ti efiranse simi Eledumare yo maa tiyinleyin eesiniisaseti lagbara Olorun. Moni awon ibeere bii melo kan timofe beere, inumiosidun teeba damilohun lekunrere. 1. Iru awo wo ni anpeni ABOKADELE? 2. Kinni owa ninu alafo mejeeji teefisi isale yi IMULE AWON AJE TO DAJU ABO ADIE TO DUDU TIKO NI AMI KANKAN, IKODE KAN,OBI-IFIN,OBI-IPA,TEWE-TEGBO AJEOBALE,IGBA OLOMORI ATI ........., AO LO WA EGBO AJEOBALE YEN NI ARO KUTU-KUTU,AO WA FI EGBO YEN WON IKA-ARIN WA,AO GE SI META,AO YA AWE-KAN NIBI OBI-IPA,AO GE SI MARUN,AO YA AWE KAN NIBI OBI-IFIN AO GE SI MERIN. AO KO EGBO TI A GE SI META YEN TELE IGBA,AO DA AWON OBI TI A GE YEN SI,AO FI IKODE YEN ATI EWE........,AO WA KO. 3. Se egbo ajeofole ti ogunto ika-aarin ni a o ge meta re, abi eyokan tia bati fiwon ika-aarin yen naa ni amaa ge si meta? Eseun pupo o, unomaa reti esi yin
Agbo ato baba! Ma fo esi si awon ibere yin yen via d e-mail. O wu mi lati fo esi nibi, sugbon ifa ni ise yen, mo si jiya fun kin to ni lowo ni, ko se fi sere nitori awon ti n ta iwe-ogun. |
Re: .. by Ifankaleluya: 5:51pm On Mar 04, 2016 |
Ifankaleluya:
Agbo ato baba! Ma fo esi si awon ibere yin yen via d e-mail. O wu mi lati fo esi nibi, sugbon ifa ni ise yen, mo si jiya fun kin to ni lowo ni, ko se fi sere nitori awon ti n ta iwe-ogun. mo ti fi esi ranse si e-mail yin. Bi e ba ti se, be ni o ri tori tokan-tokan ni mo fi yonda ifa yen fun yin. |
Re: .. by Ifankaleluya: 6:14pm On Mar 04, 2016 |
Humm..! |
Re: .. by Ifankaleluya: 6:22pm On Mar 04, 2016 |
Oluokunoluwole: eku ise opolo eledua a ran yin lowo,ti eba ni orisi isoye miran ebawa fi sita E seun, Babalawo lo ni isoye,so ifa-isoye po lorisi-risi daadaa,sugbon n ko fe fi ifa sile lori faran yi mo. A o ma soro lona miran! |
Re: .. by lawani: 8:21pm On Mar 04, 2016 |
Ifa is scholarship, apprenticeship and etc. Even if you have not gone for igbo odu you can still be an authourity by studying. In the olden days you had to study for years to qualify as an independent practitioner, then you continue studying till you die. If you are very brilliant and resourceful, you will be able to develop new oogun on your own. Entering igbodu is good but it is merely symbolic, scholarship is the more important quality.
If we get our acts together, there will be no fake Babalawos as there will be an institute to examine them to determine that they can recite all the 256 odus and some extensions, then know the basic etutus, by knowing like 2 or 3 thousand Ifa verses and the basics of rituals, a practitioner may be licensed but still placed under tutelage of a more experienced Awo from there through practice he will move to MSc level, Associate degree, Phd and etc. Thus fakes will be eliminated. |
Re: .. by Nobody: 9:35pm On Mar 04, 2016 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 9:42pm On Mar 04, 2016 |
x |
Re: .. by Nobody: 10:41pm On Mar 04, 2016 |
Kai walahi scammers are just every where, this is just a reminder that i should not trust any1 again, i should only trust my self, i was just scammed about 2wks ago by a young guy and someone who called him self a babalawo. Please everyone lets be very careful, deceivers are just everywhere, May Allah be with everyone of us, May he also direct us to right path, May he solve all our problems. Amen |
Re: .. by akingbemi(m): 11:39pm On Mar 04, 2016 |
kadunasouth:
Iye die die lema tu, gege bi adie mase fi apalu apare to bafeko tabi tobafe fo gege be leyin na mase niwaba, eo ka apa abiya yin soke eo tun da pada lemeta eo ranti nkanna lese kese Ejo baba gbenren melo ni ki a sin 2 Likes |
Re: .. by akingbemi(m): 12:00am On Mar 05, 2016 |
kadunasouth: Eyonu Eru oju aro epo obo ao lopo ma ose lux ao ma fiwe lalale odaju kini eru oju 1 Like |
Re: .. by akingbemi(m): 12:14am On Mar 05, 2016 |
ALIUDAVID: ERO ADAAJINA TABI TI ENIYAN BA TE OGUN MOLE. Ti o ba wu ni, ao wa igbe abo ewure ao po pelu ori, a o mafi ra ibi ti o wu. fun egbo ti ko jina, ao sa igbe ewure naa ti yio gbe ao ma ku si oju egbo naa.
MADARIKAN ao fa irun ori wa ti yio dan, ao gbe ile(ground)koto, ao da irun naa si, ao wa yaa igbe le lori, ao fi odindin atare kan le igbe naa lori ao wa yepe le lori, o kere sugbon o daju. IBA EYIN AGBAGBA, IBA EYIN TO LAYE Ejo se eniyan le bawa da irun na tabi baber 1 Like |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 12:34am On Mar 05, 2016 |
Hmmmm!haha'haa! Aaawu'ha! Sa'o saagba gbe sha!! Wipe ohun gbogbo ti an so, ati gbogbo atejise wa pata, wipe gbogbo agba yee lo nka, ki'e masi g agbe ntempe kinni yin'ohun'o, AYELUJARA, Se owa di igba ti aba nba oruko wa ninu iwe iroyin ni? Alaso funfun sini epo ma nwa kiri Oloruko kosini fe kobaje, bati mo pe onilu'o nife kotu Ibadara kase araawa ni Awo. Tori igba pele kiiya Beeni awo pele kiifo, gbogbo nti ambarawaaso, ife lowa niibe'o Aijebee, abati waara wa kan nibi tia ti le pade arawa'o Tori moti so pe awon ti won nye ikan ni yi wo, won po ju awon ti nfi atejise sibe lo, oro sipo nidi'e gan, sugbon kafi'enu kadake ni'akara osuu! Sugbon, aifele kebosi, ni ai fele bani joo! IFA NI KOKO IGI NI O BERE OJO,ADIFA FUN EJO N BE LORUN TI SE OMO-AWISUNKUN,IFA NI IRE LO BA MO SE. MA SE LOO,IKA LO BA MO SE, MA SE LO,AT'ORE AT'KA OKAN KAN KIIGBE. Fun idi eyi Oore mi MODUPE (OPE)'OTAN. AFARO'O... Gbogbo eleyi to ba se ni wa je ere re...!
ela-boru, ela-boye, ela-bosise'ooooo 1 Like |
Re: .. by auggswell: 3:44am On Mar 05, 2016 |
Ifankaleluya:
mo ti fi esi ranse si e-mail yin. Bi e ba ti se, be ni o ri tori tokan-tokan ni mo fi yonda ifa yen fun yin. baba ifankaleluya ejowo e fun emi naa ni ise yen pari, mo ti kan so yin Lori email amo mi o gbo nkankan lati odoyin. email mi ni auggswell@yahoo.com. ejowo sir mo n reti lati gbo lati odoyin e seun sir |
Re: .. by Lero70: 5:36am On Mar 05, 2016 |
healthFirst: 141
IFA IWE ISE ATI OSI DANU I I II II I. II II. II OBARA DAGISE NU Egbo akoko ewe re, epo re gbogbo re lara igi kan ao gun pelu ikode kan ao pomo ose dudu ti a ba fe lo ao te nifa OBARA DAGISE NU sori iwon ba ti a fe lo, ap wa pe ofore si. OFO RE: Mo da sasa awo ile ogbo, mo wewe, mo we osi danu, awo eriki odan. O difa fun Orunmila ni ojo ti awon oso ati aje ngbero wipe awon yio di oran si orunmila lorun orunmila ni e kole di oran simi lorun Woni iwo orunmila jeka wo ohun ti awon kofi ni ledi oran si o lorun, orunmila ni ojo ti omode bati ja ewe pegunrun tosi wa egbo pegunrun ni gbogbo ohun ti o ba n se ni buburu yio pada leyin re emi__omo_moti jawe pegunrun mosi wa egbo re loni gbogbo ohun buruku ti o ba n se mi ko pa da leyin mi....ao wa fi we ao si sun kehikehin re nina
ejowo se kosi asiko ti kole we ose yi, atipe se alemaa wee lojoojumo. Isese ogbewao 1 Like |
Re: .. by jamiu3209(m): 6:41am On Mar 05, 2016 |
Ifankaleluya: FUN ENITI KO BA SE ASEYORI LORI GBOGBO IDAWOLE RE TABI TI AWON AGBALAGBA KO JE KO RI ONA ABAYO.
IFA NI AWA NI TI A LE FUN YIN,KO KIN NSE OGUN LASAN.
IFA YI JE AKO ATI ABO.
AKOKO NI IWE(BATH) ASEYORI TI GBOGBO OGUN ATI OHUN TI O BA DAWOLE YIO FI MA SESE EKEJI NI IMULE AJE TI WON FI MA N YOJU SI ENIYAN LOJU ORUN TI WON YIO SI FI ASIRI OGUN AYE RE HAN E. IFA ELEKEJI YI, TI O BA SE BI WON TI MA N SE,OKUNRIN YIO LO FUN OJO MESAN,OBINRIN YIO LO FUN OJO MEJE. LEYIN TI O BA LO IFA YI TAN,TI ENIYAN BA LO YA X-RAY NI HOSPITAL,WON A RI IGBA NI AYA WA,IGBA(CALABASH) YEN NI AMI TI AWON AJE YIO FI SI WA LARA TO TUMO SI WIPE AWON AJE KO GBODO FI OWO KAN WA MO.
SUGBON NKO NI NI ANFANI LATI FI IFA KEJI YEN SILE LORI IKANNI YI,NITORI AWON KAN TO JE WIPE IWE OGUN NI WON N TA. AWA SI MO ASIRI WON.TORI AWON IWE KAN NI WON N DAKO FUN YIN,WON KIISE BABALAWO. IRO LASAN NI WON N PA FUN YIN.
1. IWE ASEYORI.
EWE-IYALODE TI KO JA TI KO LU 201, AKO-OKUTA MESAN, ATI EPO-OBO NI AO FI SE AGBO YEN. OMUNU EWE-IYALODE MESAN ATI EPO-OBO DIE NI AO GUN PAPO,TI AO PO MO OSE DUDU DIE TI AO FI SE OSE RE.AO KO AKO-OKUTA YEN TELE IKOKO,AO FI EPO-OBO YEN LE LORI,AO WA KO GBOGBO EWE YEN LE LORI. AO BU OMI TO PO DADA SI,AO GBEKA INA NI DEDE AGOGO-MEFA IROLE. TI AGBO YEN BA TI JINNA,A KO GBODO FI IDI RE KAN ILE OO. A LE WA AKO-OKUTA TI O TOBI DADA KI A GBELE LORI. AO WA KO GBOGBO EWE YEN KURO,AO LO DA SI ORI-AKIITAN. SUGBON,A KO NI KO AKO-OKUTA YEN KURO. FUN ENITI KO BA NI AGBARA LATI PA ODIDI ERAN,AO TI RA(BUY) ORI ORUKO ATI ESE RE MERERIN SILE,AO KO SINU AWO ABOKADELE DUDU,AO BU EPO PUPA SI LORI. TI O BA DI NI AGOGO-MOKANLA ALE,AO SE ADURA SI,AO LO GBE SI ORITA-META,A KO GBODO WEYIN TI A BA TI GBE KA LE OO. AO NI SUUURU KI O FI DI AGO-KAN ORU,TI AGO-KAN ORU BA TI LU NI AO FI AGBO YEN WE PELU KENKEHIN TITUN. TI A BA TI WE TAN,AO RI KENKENHIN YEN MOLE,AO KO AKO-OKUTA YEN LO DA SI ORITA-META LORU YEN,A KO SI GBODO WO EYIN TI AO FI WOLE PADA.
GBERE IFA YEN; ESO-LOWEREJENJE MESAN ATI OMO-IRULA MESAN NI AO LO PAPO TI AO FI SIN GBERE MERIN NI AYA APA-OTUN,META NI EYIN APA-OTUN ATI GBERE META NI AYA APA-OSI,MERIN NI EYIN APA OSI. LO BA TAN.
IKILO RE OOO OBINRIN KO GBODO WE IWE YEN OOO. TI OBINRIN BA WE,AWON IYAMI MA FUN NI EIYE NI OOO.
2 IMULE AWON AJE TO DAJU ABO ADIE TO DUDU TIKO NI AMI KANKAN, IKODE KAN,OBI-IFIN,OBI-IPA,TEWE-TEGBO AJEOBALE,IGBA OLOMORI ATI ........., AO LO WA EGBO AJEOBALE YEN NI ARO KUTU-KUTU,AO WA FI EGBO YEN WON IKA-ARIN WA,AO GE SI META,AO YA AWE-KAN NIBI OBI-IPA,AO GE SI MARUN,AO YA AWE KAN NIBI OBI-IFIN AO GE SI MERIN. AO KO EGBO TI A GE SI META YEN TELE IGBA,AO DA AWON OBI TI A GE YEN SI,AO FI IKODE YEN ATI EWE........,AO WA KO GBOGBO IFUN ADIE YEN TI A YO LATI IDI,TORI A KO GBODO PA ADIE YEN LORI,LATI IDI(OBO) NI AO TI GE,TI AO SI TIKO GBOGBO IFUN RE JADE. TI A BA TI KO TAN. AO KO SINU IGBA(CALABASH) YEN,AO WA KO EWE AJE-OBALE TO PO DADA SI LORI. AO WA DE IGBE YEN PA. AO GBE SINU IKOKO,AO GBE KA INA. AO DE KOKO YEN,A KO GBO RO PAPO TI YIO FI JO TAN. TI O BAJO TAN TI ATI LO,AO WA TE NI ODU-IFA OSA-MEJI. AO WA PE IFA RE SI. SUGBON N KO NI FI IFA YI SILE TAN TORI AWON TI WON N TA IWE-OGUN.
NOTE;; TI O BA NILO GBOGBO IFA YI TAN,FI NUMBER RE SILE LABE KIN NI YI. PELU OGO OLORUN,MA SI FI SILE FUN OOO.
ABORU,ABOYE,ABO-SISE. E jowo baba efun mi nise yitan e Seun 08138622464 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 9:32am On Mar 05, 2016 |
healthFirst: 141
IFA IWE ISE ATI OSI DANU I I II II I. II II. II OBARA DAGISE NU Egbo akoko ewe re, epo re gbogbo re lara igi kan ao gun pelu ikode kan ao pomo ose dudu ti a ba fe lo ao te nifa OBARA DAGISE NU sori iwon ba ti a fe lo, ap wa pe ofore si. OFO RE: Mo da sasa awo ile ogbo, mo wewe, mo we osi danu, awo eriki odan. O difa fun Orunmila ni ojo ti awon oso ati aje ngbero wipe awon yio di oran si orunmila lorun orunmila ni e kole di oran simi lorun Woni iwo orunmila jeka wo ohun ti awon kofi ni ledi oran si o lorun, orunmila ni ojo ti omode bati ja ewe pegunrun tosi wa egbo pegunrun ni gbogbo ohun ti o ba n se ni buburu yio pada leyin re emi__omo_moti jawe pegunrun mosi wa egbo re loni gbogbo ohun buruku ti o ba n se mi ko pa da leyin mi....ao wa fi we ao si sun kehikehin re nina
hnnmm. 1 Like |
Re: .. by ALIUDAVID: 2:01pm On Mar 05, 2016 |
akingbemi:
Ejo se eniyan le bawa da irun na tabi baber
Beni e le lo blade eo gbe ile yen e wa dasi !! |
Re: .. by ALIUDAVID: 2:01pm On Mar 05, 2016 |
akingbemi:
Ejo se eniyan le bawa da irun na tabi baber
Beni e le lo blade eo gbe ile yen e wa dasi !! |
Re: .. by Ifankaleluya: 5:17pm On Mar 05, 2016 |
Ifa ni; Elefiri-mogun, aja ni aja olofin, agbo lagbo olori, oja-agbala ni ki e fi gbami, oja ti e ba fi gbami ki e ma je ko ja,kike ni ki omo-araye o ma ke mi, gige ni ki omo-araye o ma ge mi, oja ti e ba fi gba mi e ma je ko ja, ewe aje-obale le fi pin ohun lotu-ife nijo n,ogbe-tun-omopon lo ni ke gbe mi pon seyin giri-giri.
Lagbara lowo eledumare awon eleye yio da owo(respect) fun wa.
Ase-orisa lenu mi,eyi mo ba ma ma wi ni irunmole yio gba, ase orisa lenu mi!
Ela-boru, ela-boye, ela-bosise. 3 Likes |
Re: .. by eposho: 5:44pm On Mar 05, 2016 |
lawani: Ifa is scholarship, apprenticeship and etc. Even if you have not gone for igbo odu you can still be an authourity by studying. In the olden days you had to study for years to qualify as an independent practitioner, then you continue studying till you die. If you are very brilliant and resourceful, you will be able to develop new oogun on your own. Entering igbodu is good but it is merely symbolic, scholarship is the more important quality.
If we get our acts together, there will be no fake Babalawos as there will be an institute to examine them to determine that they can recite all the 256 odus and some extensions, then know the basic etutus, by knowing like 2 or 3 thousand Ifa verses and the basics of rituals, a practitioner may be licensed but still placed under tutelage of a more experienced Awo from there through practice he will move to MSc level, Associate degree, Phd and etc. Thus fakes will be eliminated. I have read all the pages of this thread I know it is forbidden from page one to write in English but when I read an excellent remark like this I have to comment. I think this suggestion was highlighted by fellow like ELEBU IBON and some others long time but I don't know where it endede. Truth our cure and development lies in our tradition. Thanks. Isese lagba. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 6:36pm On Mar 05, 2016 |
Mo ni ibere se ogun eyonu yi daju ? Ewe Omisin misin mejeji ao gunpo mon ose ati ewe anu aofi turare bintu si ao wa ko sinu ike funfun ao mafi we.. |
Re: .. by akingbemi(m): 6:47pm On Mar 05, 2016 |
ALIUDAVID:
Beni e le lo blade eo gbe ile yen e wa dasi !!
wot of clipper |
Re: .. by Suraze: 7:30pm On Mar 05, 2016 |
Ejowo Baba Mo Need Ogun Ti Mafini Okiki Owo Tori Pe Olori Nimi Musician |
Re: .. by Ifankaleluya: 7:47pm On Mar 05, 2016 |
skypeme: Mo ni ibere se ogun eyonu yi daju ? Ewe Omisin misin mejeji ao gunpo mon ose ati ewe anu aofi turare bintu si ao wa ko sinu ike funfun ao mafi we.. skypeme: [color=#000099]Mo ni ibere se ogun eyonu yi daju ? Ewe Omisin misin mejeji ao gunpo mon ose ati ewe anu aofi turare bintu si ao wa ko sinu ike funfun ao mafi we.. [/color] skypeme: Mo ni ibere se ogun eyonu yi daju ? Ewe Omisin misin mejeji ao gunpo mon ose ati ewe anu aofi turare bintu si ao wa ko sinu ike funfun ao mafi we.. Ogun-aanu ni ogun yen, sugbon kope. Ewe-ominsinmisn gogoro ati ewe-aanu, pelu eran ike-maalu, ti e ba ti gun tan,oti-shnap ni a o fi po, ao ko sinu igba-funfun tabi ike-funfun, ao wa tu bintu si, ao wa fi eran ike-malu yen gun lori. Lo ba tan! Ela-boru, ela-boye, ela-bosise. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 9:54pm On Mar 05, 2016 |
Ifankaleluya mo dupe |
Re: .. by Lero70: 6:06am On Mar 06, 2016 |
healthFirst: 93.
ASEGBE OLOPELE TO GBONA Igbe ewure, igbe aguntan, agbari Inaki Igboro to seku, alakan ti ara re pe, odindi atare kan, a o jo po, a o wa ra opele kan ti o la enu sile, a o wa di ogun yi sinu efeowu, a o wa we ni owu dudu ati funfun, a o wa ju sinu opele yen, a o wa ran ni awo dudu, a o wa dalu ni otun ati osi, ti a ba fe lo, a o ma pe ofo re si ibiti a dalu yen. OFO RE: ha 3x, e ma bimi 3x, ti ewure ba su, a ki fi bi, e ma bimi 3x ti aguntan ba su, a ki fibi, e ma bimi 3x aki bere oro ana lowo oku, e ma bimi 3x, a ki bere epo lowo alakan, e ma bimi 3x, a ki bere gbigbe sanle lowo opele, - a o so ohun ti a fe si nitori enu ti opele la sile ki pade mo lailai, ki gbogbo awon enia wonyi(Ao daruko awon to fe ba wa ro ejo si) ma le pa enu isale mo toke ba mi fi ro ejo bayi bayi mo lailai - a o ju si apo. ekuise o baba ewe amaa je o, ejowo se odidi agbari inaki ni a o wa ni tabi die lara egungun agbari inaki, atipe ti okobari eyitoseseku se alelo eyitotikutipedie? Esee. 1 Like |
Re: .. by Oluokunoluwole: 9:14am On Mar 06, 2016 |
healthFirst: 141
IFA IWE ISE ATI OSI DANU I I II II I. II II. II OBARA DAGISE NU Egbo akoko ewe re, epo re gbogbo re lara igi kan ao gun pelu ikode kan ao pomo ose dudu ti a ba fe lo ao te nifa OBARA DAGISE NU sori iwon ba ti a fe lo, ap wa pe ofore si. OFO RE: Mo da sasa awo ile ogbo, mo wewe, mo we osi danu, awo eriki odan. O difa fun Orunmila ni ojo ti awon oso ati aje ngbero wipe awon yio di oran si orunmila lorun orunmila ni e kole di oran simi lorun Woni iwo orunmila jeka wo ohun ti awon kofi ni ledi oran si o lorun, orunmila ni ojo ti omode bati ja ewe pegunrun tosi wa egbo pegunrun ni gbogbo ohun ti o ba n se ni buburu yio pada leyin re emi__omo_moti jawe pegunrun mosi wa egbo re loni gbogbo ohun buruku ti o ba n se mi ko pa da leyin mi....ao wa fi we ao si sun kehikehin re nina
eku ise opoplo,ejowo ema binu si ohun ti mofe so yi oo.se igi pegunre ni abi igi akoko toriwipe ofo ti e ko si isele yi pegunre ni eko sibe,koyemi ni oo loje ki nbere ifa agbewa ooo |