Re: .. by Nobody: 10:38pm On Mar 08, 2016 |
| Se Ogbe-Ogunda ni yen sa ? | 1 Like
|
Re: .. by Nobody: 10:39pm On Mar 08, 2016 |
c |
Re: .. by wale259(m): 6:31am On Mar 09, 2016 |
Baba e jo se ewedu na ni Ewe-ooyo ati wipe se a le fi agbon yen se sara fun onibara tabi awon agbalagba ta ba ri awon omo kekere ni aye lewu baba.wiwe ose yi nigbagbo? Ifankaleluya:
Ewe-ooyo ni e o lo re wa ti yio po dada.
Odidi-agbon eyo kan.
Ao sa oyo yen ti yio gbe.
Ao gun po mo ose
Ao pa agbon yen,omi-agbon yen ni ao fi po ose yen
Ao fi ti inu-agbon yen se sara fin awon omo-kekeke,sugbon a ko ni je ninu agbon yen oo.
Ao wa ko ose yen sinu koronfo agbon yen
Ao wa te ni Ogbe-yonu
OGBE-OGUNDA NI A MA N PE NI OGBE-YONU
|
Re: .. by wale259(m): 6:38am On Mar 09, 2016 |
Eku ise lopolopo,sugbon mofe alaye lori ise yi baba,se iwonba ose ta le lo tan ni a ma fi po omi agbon yi ni a bi ale se ose na sile pupo ati wipe se inu omi agbon ni a ma so oguna na si ka to lo lori olo abi omi lasan.ma dupe te ba dami loun awon ibere wonyi. Ifankaleluya: Boya ki e tun lo bere lowo awon agbalagba, OMI-AGBON NI WON N PE NI OMI - APEGUNRUN. EWE-PEREGUN SI DA WA LOTO.
Bayi ni won se ma n lo omi agbon lati fi pa egun, epe, ati ise run.
A o lo wa omi-agbon to po daadaa, ao wa mu oguna to ti pon daadaa ninu ina,ao sare ju si inu omi(owo(hand) ni ao fi mu ogunna yen ninu aro),ao ju si ori-olo,ao lo,ao po mo ose dudu,omi-agbon yen ni ao fi po ose yen. Kanrinkan titun ni ao fi we ose yen ni odo to n san. Gbolohun yi ni ao ma pe ti a ba ti n we ose yen:
ojo ti ina ba wo inu omi ni egun aye re tan, ki egun aye mi ko tan loni.
Owo(hand) mi ti ba omi-apegunrun lo ni, ki gbogbo egun aye mi ko tan loni, ati egun, ati epe, ati ise(poverty) aye mi ko ma ba omi lo loni, ko je ki n gbaye se rere.
Ao ju kanrinkan yen si odo,yio ma ba omi lo. |
Re: .. by wale259(m): 8:42am On Mar 09, 2016 |
Baba e jowo e fun mi ni ifa isoye,e fi sanu fun mi....email me re waleadewale2002@yahoo.com Ifankaleluya:
E seun, Babalawo lo ni isoye,so ifa-isoye po lorisi-risi daadaa,sugbon n ko fe fi ifa sile lori faran yi mo. A o ma soro lona miran! |
Re: .. by wale259(m): 8:46am On Mar 09, 2016 |
Baba e ma fun wa ni awon ise tan ki awa na le ma sa wo ko le ri bo se ye kori fun wa ni ti dada. Ifankaleluya: OBARA-OGUNDA NI A N PE NI OBARA-EGUN TAN.
IFA NI;
Obara-egun tan
oni(today) la o pa egun run
adifa fun orunmila nijo ti omo-araye ni awon o fi eegun,epe ba aye baba je
ifa ni iro ni won n pa
egun kii mu ila
egun kii mu ikan
ati egun ati epe kii mu ata
obara-egun tan
ifa ba mi pa gbogbo egun aye mi.
IFA YI NI A MA N FI, ata,ikan,ila ati etu-ibon se. Ti a ba pari re, enu ona ni ao ti te ifa re,ti a ba pe ifa tan. Ao wa fi etu ibon yen si ni aarin,ao wa sa ina si. Ti ina yen ba gbi, ise yen ti dahun niyen.
Ela-boru, ela-boye, elo-bosise.
1 Like |
Re: .. by wale259(m): 9:13am On Mar 09, 2016 |
Baba ifankaleluya,e ma se be...nitori ta ba ni ka diju keni buruku koja eni rere akoja pelu ati wipe agba o kogbon...emi nife si mo si ti fi email ranse si yin lori e Ifankaleluya: Note; If u xtend an handshake 2 a man wit leprosy 2day,next-time he w request 4 a hug. O se bi owe...mo fi ifa imule awon aje yen ranse si ori e-mail enikan,dipo ko dupe o da esi pada wipe emi o fi ami si gbolohun yen ni. E joo se o si leto bayen? N ko ni fisile mo lofe. |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:29am On Mar 09, 2016 |
skypeme: | Se Ogbe-Ogunda ni yen sa ? | BEE NI, O KARE OKUNRIN YI. OGBE'YONU NIYEN. E LE FIAGBON YEN SE SARA FUN ENIKENI. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:32am On Mar 09, 2016 |
wale259: Eku ise lopolopo,sugbon mofe alaye lori ise yi baba,se iwonba ose ta le lo tan ni a ma fi po omi agbon yi ni a bi ale se ose na sile pupo ati wipe se inu omi agbon ni a ma so oguna na si ka to lo lori olo abi omi lasan.ma dupe te ba dami loun awon ibere wonyi. E LE PO KO PO DADA. SUGBON KIISE OHUN TI AO MA WE NIGBA GBOGBO OO. BI EEKAN LOSU-META NI. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:54am On Mar 09, 2016 |
wale259: Baba e jowo e fun mi ni ifa isoye,e fi sanu fun mi....email me re waleadewale2002@yahoo.com IFA-ISOYE TI O MA N JE GBOGBO OHUN TA BA KA KO DURO SIKUN WA LOKOKAN. E LO RE WA IGBA-AHUN, ATI IKARA-HUN IGBIN. AO JO MEJEEJI PAPO, AO LO KO NI ATAARE NINU OO AO WA TE NI IFA OFUN-SE (OFUN LOWO-OTUN ATI OSE LOWO-OSI) NI A N PE BAYEN AO WA PE IFA RE SI BAYI MO DE IBI WON TI N MUMI OGBON(WISDOM) MO BA WON MU MO DE IBI WON TI N GBAMON-RAN IMO MO BA WON GBA ADIFA FUN ORUNMILA NIJO TI N LORE KO MO-IFA, TI N LORE KO OGUN MO-OGUN WON NI BAWO NI O SE NI GBAGBE IFA NI EEWO-ORISA IGBIN KII-FA KO GBAGBE IKARA-HUN BEENI AHUN KIIFA KO GBAGBE IGBA-EYIN RE WON NI TI O BA GBAGBE BAWO NI O SE NI WO'NU ARA WON ORUNMILA NI EEWO ORISA IGBIN KII-FA KO WO'NU AHUN BEENI AHUN KIIFA KO WO'NU IGBIN OFUN-SE FUN MI NIYE TEMI KI N MU SAWO. AO MA FI MU EKO-TUTU. BI WON TI MA N SE NIYEN, E LE TUN BERE LOWO BABALAWO MIRAN TI O BA MO IFA YEN. ELA-BORU, ELA-BOYE, ELA-BOSISE. 3 Likes 1 Share |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:56am On Mar 09, 2016 |
wale259: Baba e jo se ewedu na ni Ewe-ooyo ati wipe se a le fi agbon yen se sara fun onibara tabi awon agbalagba ta ba ri awon omo kekere ni aye lewu baba.wiwe ose yi nigbagbo? BEE NI. |
Re: .. by ALIUDAVID: 11:17am On Mar 09, 2016 |
akingbemi: wot of clipper
Ele lo ki ori sa ti dan nii, sugbo abe lodaju |
Re: .. by Nobody: 12:18pm On Mar 09, 2016 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 12:55pm On Mar 09, 2016 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 12:59pm On Mar 09, 2016 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 1:30pm On Mar 09, 2016 |
x 1 Like |
Re: .. by wale259(m): 11:04pm On Mar 09, 2016 |
E se baba,Eledumare oni fi yin sile nigba kankan...se mo le lo fun omo mi na bi omo odun meta Ifankaleluya:
IFA-ISOYE TI O MA N JE GBOGBO OHUN TA BA KA KO DURO SIKUN WA LOKOKAN.
E LO RE WA IGBA-AHUN, ATI IKARA-HUN IGBIN.
AO JO MEJEEJI PAPO, AO LO
KO NI ATAARE NINU OO
AO WA TE NI IFA OFUN-SE (OFUN LOWO-OTUN ATI OSE LOWO-OSI) NI A N PE BAYEN
AO WA PE IFA RE SI BAYI
MO DE IBI WON TI N MUMI OGBON(WISDOM) MO BA WON MU
MO DE IBI WON TI N GBAMON-RAN IMO MO BA WON GBA
ADIFA FUN ORUNMILA NIJO TI N LORE KO MO-IFA, TI N LORE KO OGUN MO-OGUN
WON NI BAWO NI O SE NI GBAGBE
IFA NI EEWO-ORISA IGBIN KII-FA KO GBAGBE IKARA-HUN
BEENI AHUN KIIFA KO GBAGBE IGBA-EYIN RE
WON NI TI O BA GBAGBE BAWO NI O SE NI WO'NU ARA WON
ORUNMILA NI EEWO ORISA IGBIN KII-FA KO WO'NU AHUN
BEENI AHUN KIIFA KO WO'NU IGBIN
OFUN-SE FUN MI NIYE TEMI KI N MU SAWO.
AO MA FI MU EKO-TUTU.
BI WON TI MA N SE NIYEN, E LE TUN BERE LOWO BABALAWO MIRAN TI O BA MO IFA YEN.
ELA-BORU, ELA-BOYE, ELA-BOSISE. |
Re: .. by skamo74: 6:38am On Mar 10, 2016 |
Baba kini Ogun ISETO ( Diabetes) |
Re: .. by Ayomidegbenga1(m): 7:24am On Mar 10, 2016 |
Ifankaleluya: OBARA-OGUNDA NI A N PE NI OBARA-EGUN TAN.
IFA NI;
Obara-egun tan
oni(today) la o pa egun run
adifa fun orunmila nijo ti omo-araye ni awon o fi eegun,epe ba aye baba je
ifa ni iro ni won n pa
egun kii mu ila
egun kii mu ikan
ati egun ati epe kii mu ata
obara-egun tan
ifa ba mi pa gbogbo egun aye mi.
IFA YI NI A MA N FI, ata,ikan,ila ati etu-ibon se. Ti a ba pari re, enu ona ni ao ti te ifa re,ti a ba pe ifa tan. Ao wa fi etu ibon yen si ni aarin,ao wa sa ina si. Ti ina yen ba gbi, ise yen ti dahun niyen.
Ela-boru, ela-boye, elo-bosise.
Baba ewe a maa je fun yin, ise Tailor ni mo nse e jowo mo need ogun ti maa fi ni awon omo ise(apprentice) E see pupo 1 Like |
Re: .. by Ayokunumi24(f): 8:21am On Mar 10, 2016 |
Ayokunumi24: Eku ise takuntakun olorun yio ma fun yin se o, ejowo mo nilo ogun fun eti ton tu ti ko si gboran dada mo, o ti to bi ogun odun bayin to ti tu, ejowo e sanu mi, e se pupo ejowo e dami loun ibere mi olorun a se ninu ise tiyin na. |
Re: .. by wale259(m): 11:48am On Mar 10, 2016 |
Baba ifankaleluya,ta ba te ni ifa yen tan,se. Ko ni gbolohun kankan,se o ti di wiwe ni yen,nigba gbogbo abi? wale259: Baba e jo se ewedu na ni Ewe-ooyo ati wipe se a le fi agbon yen se sara fun onibara tabi awon agbalagba ta ba ri awon omo kekere ni aye lewu baba.wiwe ose yi nigbagbo? |
Re: .. by Oluokunoluwole: 2:40pm On Mar 10, 2016 |
Ifankaleluya:
mo ti fi esi ranse si e-mail yin. Bi e ba ti se, be ni o ri tori tokan-tokan ni mo fi yonda ifa yen fun yin. baba kilode ti mo email yin ti e o funmi lesi ohun ti mo bere fun,mobeyin e damilohun awon nkan ti mo bere fun ifa agbeyin oo |
Re: .. by Oluokunoluwole: 3:16pm On Mar 10, 2016 |
Ifankaleluya: [color=#990000][/color]
Ogun-aanu ni ogun yen, sugbon kope. Ewe-ominsinmisn gogoro ati ewe-aanu, pelu eran ike-maalu, ti e ba ti gun tan,oti-shnap ni a o fi po, ao ko sinu igba-funfun tabi ike-funfun, ao wa tu bintu si, ao wa fi eran ike-malu yen gun lori. Lo ba tan!baba se omisinmisin pe meji ni ewo ni gogoro ejowo e se alaye re fun mi atipe se ale lo oye lux lati fi po oogun yi ifa agbe wa oooo
Ela-boru, ela-boye, ela-bosise. 1 Like |
Re: .. by Oluokunoluwole: 4:46pm On Mar 10, 2016 |
Ifankaleluya:
IFA-ISOYE TI O MA N JE GBOGBO OHUN TA BA KA KO DURO SIKUN WA LOKOKAN.
E LO RE WA IGBA-AHUN, ATI IKARA-HUN IGBIN.
AO JO MEJEEJI PAPO, AO LO
KO NI ATAARE NINU OO
AO WA TE NI IFA OFUN-SE (OFUN LOWO-OTUN ATI OSE LOWO-OSI) NI A N PE BAYEN
AO WA PE IFA RE SI BAYI
MO DE IBI WON TI N MUMI OGBON(WISDOM) MO BA WON MU
MO DE IBI WON TI N GBAMON-RAN IMO MO BA WON GBA
ADIFA FUN ORUNMILA NIJO TI N LORE KO MO-IFA, TI N LORE KO OGUN MO-OGUN
WON NI BAWO NI O SE NI GBAGBE
IFA NI EEWO-ORISA IGBIN KII-FA KO GBAGBE IKARA-HUN
BEENI AHUN KIIFA KO GBAGBE IGBA-EYIN RE
WON NI TI O BA GBAGBE BAWO NI O SE NI WO'NU ARA WON
ORUNMILA NI EEWO ORISA IGBIN KII-FA KO WO'NU AHUN
BEENI AHUN KIIFA KO WO'NU IGBIN
OFUN-SE FUN MI NIYE TEMI KI N MU SAWO.
AO MA FI MU EKO-TUTU.
BI WON TI MA N SE NIYEN, E LE TUN BERE LOWO BABALAWO MIRAN TI O BA MO IFA YEN.
ELA-BORU, ELA-BOYE, ELA-BOSISE. |
Re: .. by Oluokunoluwole: 4:50pm On Mar 10, 2016 |
Ifankaleluya:
IFA-ISOYE TI O MA N JE GBOGBO OHUN TA BA KA KO DURO SIKUN WA LOKOKAN.
E LO RE WA IGBA-AHUN, ATI IKARA-HUN IGBIN.
AO JO MEJEEJI PAPO, AO LO
KO NI ATAARE NINU OO
AO WA TE NI IFA OFUN-SE (OFUN LOWO-OTUN ATI OSE LOWO-OSI) NI A N PE BAYEN
AO WA PE IFA RE SI BAYI
MO DE IBI WON TI N MUMI OGBON(WISDOM) MO BA WON MU
MO DE IBI WON TI N GBAMON-RAN IMO MO BA WON GBA
ADIFA FUN ORUNMILA NIJO TI N LORE KO MO-IFA, TI N LORE KO OGUN MO-OGUN
WON NI BAWO NI O SE NI GBAGBE
IFA NI EEWO-ORISA IGBIN KII-FA KO GBAGBE IKARA-HUN
BEENI AHUN KIIFA KO GBAGBE IGBA-EYIN RE
WON NI TI O BA GBAGBE BAWO NI O SE NI WO'NU ARA WON
ORUNMILA NI EEWO ORISA IGBIN KII-FA KO WO'NU AHUN
BEENI AHUN KIIFA KO WO'NU IGBIN
OFUN-SE FUN MI NIYE TEMI KI N MU SAWO.
AO MA FI MU EKO-TUTU.
BI WON TI MA N SE NIYEN, E LE TUN BERE LOWO BABALAWO MIRAN TI O BA MO IFA YEN. E seun gann ni eku agba,baba se die ninu igba eyin ijapa ni abi odidi re ati odidi ikarahun igbin ni.e se pupo ELA-BORU, ELA-BOYE, ELA-BOSISE. |
Re: .. by Ifankaleluya: 6:25pm On Mar 10, 2016 |
wale259: Baba ifankaleluya,ta ba te ni ifa yen tan,se. Ko ni gbolohun kankan,se o ti di wiwe ni yen,nigba gbogbo abi? BEE NI. |
Re: .. by Ifankaleluya: 6:26pm On Mar 10, 2016 |
wale259: E se baba,Eledumare oni fi yin sile nigba kankan...se mo le lo fun omo mi na bi omo odun meta OMO YEN SI KERE OO. |
Re: .. by Ifankaleluya: 6:28pm On Mar 10, 2016 |
Oluokunoluwole: baba kilode ti mo email yin ti e o funmi lesi ohun ti mo bere fun,mobeyin e damilohun awon nkan ti mo bere fun ifa agbeyin oo E MA BINU MESSAGE PO LORI E-MAIL WA NI. |
Re: .. by Ifankaleluya: 6:39pm On Mar 10, 2016 |
Ifa ni,
Ọtọtọtọ, ọrọrọrọ,
ọtọtọ laa jẹpa.
Ọtọtọ nla jẹ imumi.
Ohun tori tori,
ohun tore tore nlaa fọba makin nile Iranje,
ko ba le fi ohun to ri to re ta ni lọrẹ
a dia fun Ogotẹẹrẹ ẹyi ti n gbogun lọ Ẹhinwọran.
Ogotẹẹrẹ lorukọ a n poko.
Ẹhinwọran lorukọ a n pobo.
Eewọ oriṣa oko ii jagun ilobo ko sanwọ-o.
Lagbara lowo Eledumare ao ni sanwo(lack) ohun rere. eewo-orisa ni, oko kii jagun ilobo ko sanwọ.
Ela-boru, Ela-boye, Ela-bosise. 2 Likes |
Re: .. by kuddus: 7:56pm On Mar 10, 2016 |
ejo e fun wa ni ero abilu healthFirst: 146 TI INKAN OSU OBINRIN KO BA WA DADA TABI KO MA WA RARA, YIYO TABI RUNRUN Egbo botuje funfun oojó pelu ako kanhun bilala, aofi kanhun naa Tele ike Eva tabi igo ao ko egbo yen lelori ao fomi ki lagbo fun Ojo meta, aoma mun lararo Kato jeun ejo e fun wa ni ero abilu 1 Like |
Re: .. by kuddus: 7:57pm On Mar 10, 2016 |
ejo nitori olohun |
Re: .. by Ifankaleluya: 9:42pm On Mar 10, 2016 |
kuddus: ejo nitori olohun ERO-ABILU PE ORISI-RISI.....ADURA MI NI WIPE KI OLORUN MA JE KI E BO SI OWO(HAND) BABALAWO TI O NI EKO(KNOWLEDGE) DAADA. TORI KIN-NI KAN WA TI A N PE NI AKOFA(NEUTRALISES OF CHARMS OR MEDICINE IN SOMEONE's BODY), KINNI YI NI BABALAWO TO BA LEKO DAADA MA N KOKO SE LATI FI BA OGUN TO WA LARA ENIYAN JE TO BA FE BA ENIYAN JA. AASAN(gbolohun) RE WA, WON SI MA N SA OMIRAN LORI ESU PELU AWON EWE-IFA KAN. SUGBON JU GBOGBO E LO, TI E BA TI RI OMO-OWU KI E KAN SI MI. KIISE OGUN TI MO LE FI SILE LORI FANRAN YI. 2 Likes |