Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,201,409 members, 7,978,292 topics. Date: Friday, 18 October 2024 at 03:59 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju (565891 Views)
Civil Servant Killed By Thunder In Oro, Kwara (Photos) / Ogun Ibile To Daju / The Bad Shape Of Oro General Hospital, Kwara State (Exclusive Photos) (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (10) (11) (12) (13) (14) (15) (16) ... (27) (Reply) (Go Down)
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by yattybanana(m): 8:30pm On May 02, 2016 |
kadunasouth:ejo sir Lori itoju ito sugar yen, sebi ESO ewe ewedu lenso pe ewe oyo 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:01am On May 03, 2016 |
yattybanana:Beeni eso ewe oyo (seed) 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by aguns1980(m): 2:13pm On May 03, 2016 |
kadunasouth:Baba e ku agbale awon omo araye, olorun a san yin lesan daadaa, Amin. Se ti agbo yii ba wa lori ina ni a maa fo eyin naa si ni tabi akoko wo gan ni? Atipe, nje awon ewe ti a fe ja yii ni iye onka tabi a maa ja iye to wun wa ni? Se eyin oojo ni tabi eyi to ti pe 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by aguns1980(m): 2:41pm On May 03, 2016 |
Baba e ku ise. E jowo e fun wa ni Ogun ti eniyan ko ni beru lati soro lagbajo awon eniyan ti eru ko si ni ba gege bi omokunrin. Ogun ikoya to daju lati le soro nibikibi Lai foya. E se pupo baba! 1 Like 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by adegoke93: 8:36am On May 04, 2016 |
E karo sir,olorun yio ma ran yin lowo o Amin.ejo sir ki lo le fa ki ikan omo okunrin eyan kere ju ojo ori re lo ati wipe kini ona abayo? Elekeji sir,ona wo ni a se le pa kokoro to ma n yo ni ibi agbon ti eniyan ba sese ge irun tan? Please sir i want your response to be a mixture of English and Yoruba because i am not good at reading Yoruba .thanks sir kadunasouth: 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by fbabs(m): 9:01am On May 06, 2016 |
kadunasouth: E SEUN BABA se ka ni wipe obinrin lo fe lo se mesan mesan ni tabi meje meje 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by deriod(m): 9:26am On May 06, 2016 |
baba eku ojumo o ejo se ogun kokoro inu ije la ma lo fun staphloccocus . |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Universal247: 4:19am On May 07, 2016 |
@kadunasouth E jo mo ni lo iranlowo yin ni kiakia.. se ale soro ni watsapp tabi ke sms mi 08022773415 mo ma peyin pada... ewe a ma je fun yin |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by bosrote: 12:23am On May 11, 2016 |
08101646045atwp: Eseun baba, e pe fun was sir. Ejo sir kATO se TUDE kilo ma koko sir e laye wa sir 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by OmoOsanyin: 3:50pm On May 12, 2016 |
kadunasouth: Baba se isale ese kan abi meji? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 6:39pm On May 13, 2016 |
ASINA ATUDE Ewe ewuro ojo, epo obo, eru alamo ao gun papo oronro malu lama fi po ose yi omin kogbodo kan ao ko sinu roba fun fun ao wa so ori niwan ba si ao gbe sinu orun toba yo ao tun po papo ma ose yi taba tipo tan idire ko gbodo kanle mon ao ma fiwe ni ojo merin larin ose sunday monday tuesday thusday ti aba lo ose yi yato si awan ojo wonyi koni sise mon, taba si fe se ose yi arin ojo mererin yi lalese tabase yato si ojo mererin yi koni sise odaju 4 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by revelation2013(m): 8:01pm On May 13, 2016 |
This is a good thread. Keep it up. Sir ogun ulcer ti e post, kini english name awon egbo igi wonyen? Yoruba name ati english name. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 10:14pm On May 13, 2016 |
kadunasouth:Ejo sir, ki lo je oronro malu? 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by misspricy(f): 11:28am On May 14, 2016 |
kadunasouth:. E ku ise baba. E jowo se ewe etiponla ni abi esiponla. Ati wipe kini on je oju oro ? E se pupo 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 11:37am On May 14, 2016 |
kadunasouth:Good morning sir, ejo ki lo je oronro malu? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by misspricy(f): 12:07pm On May 14, 2016 |
kadunasouth:. E jowo baba. Ogun wo ni a le lo lati fi gba owo lowo awon ti o je wa ni owo. E ese pupo sir 1 Like 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ALIUDAVID: 6:17pm On May 14, 2016 |
Baba kadunasouth moti send message kan si email yin baba ejo mon reti esi. Iba eyin agba, iba eyin to laye. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ALIUDAVID: 6:26pm On May 14, 2016 |
Baba kadunasouth moti send message kan si email yin baba ejo mon reti esi. Iba eyin agba, iba eyin to laye. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Toosure70: 11:08pm On May 14, 2016 |
zenith329:cow bile. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ademotech: 3:13am On May 15, 2016 |
molala pe mo ru irin mosi so kale SI ebute ejor kini itunmo re |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 5:37am On May 15, 2016 |
kadunasouth:Good morning sir, ki lo je oronro malu? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 5:50am On May 15, 2016 |
E jo sir, kilo je oju oro tabi oruko miran wo lo je? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by presentley: 9:39am On May 15, 2016 |
zenith329:its the gall bladder. Its the same as the greenish part in a chicken, it makes the chicken get bitter should it get burst and content get spilled on the chicken. 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ademotech: 6:12pm On May 20, 2016 |
kadunasouth:ejor sir awure oni gbe e malu see opoo eyan le lo use yii |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by bosrote: 8:26pm On May 20, 2016 |
bosrote: |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kingAdex789: 12:14pm On May 22, 2016 |
Iba ako da,iba ase da __baba ejo mo ni di awure tabi aworo ti mo ma remole si shop me |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 3:56pm On May 22, 2016 |
kadunasouth: salam aleykum E seun pupo ao ma RI yin ba lase Almighty Allah ati atileyin Anobi Muhammed S.A.W. Baba e Jo mofe Ogun ERO against any asasi. thanks and stay blessed |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 4:03pm On May 22, 2016 |
salam may Allah continue to bless you abundantly bijahi M.T.N sir, what can I use for a brother of mine so that he will grant my request. l want him to finance my business but he doesn't want to turn up at all . I have sent many of his close friends to him but still nothing. what can I do sir. thanks again |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by oluwawunmi(f): 5:33pm On May 22, 2016 |
sir, ogun iju fibrod |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 5:07am On May 23, 2016 |
skamoh74:Asin tan pa lojo ao gun saka saka ao da sinu adi eyan ao ma mun sibi meji meji lojo juma ao tun mafi para Elekeji Asin tanpa lojo epo obo odidi atare kan ao jo ao da si meji epo idakan ma ose iwe eo mu idakan toku eo dasi inu adin eo mala, ele se die ku ninu ebu yi kie po ma epo pupa toba denu epo pupa owo (money) lowa fun ao la Eleketa emaje orogbo eyo kokan lojo kie wa ma mun epo sibi kan lelori Adua wa yio gba Alubarika Anabi s.a.w Mojuba awan agbagba 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 6:00am On May 23, 2016 |
kadunasouth: Allah the Alfa and Omega will protect you and your family for ever in this life and the hereafter bijahi M.T.N e seun pupo sir. 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 6:24am On May 23, 2016 |
skamoh74: am still waiting for this sir or shall I contact you privately |
(1) (2) (3) ... (10) (11) (12) (13) (14) (15) (16) ... (27) (Reply)
Causes Of Seeing Menstrual Period Twice A Month / Postinor 2 - How Effective Is It? / Doctor in the House: Free Medical Advice Available
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 43 |