Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,205,016 members, 7,990,797 topics. Date: Friday, 01 November 2024 at 02:30 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Yoruba Ronu (556 Views)
Yoruba E Ronu (A Must Read)! / If Acting President Osinbajo Were Hausa Or Fulani... Yoruba Ronu / Yoruba E Ronu Yin O. (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Yoruba Ronu by otitokoroleti: 9:08pm On Sep 18, 2016 |
Mo wo Ile Aye o, aye sa malamala;
Mo ma b’oju w’orun okunkun losu bo’le;
Mo ni eri eyi o, kini sele si Yoruba omo
Alade, kini sele si Yoruba omo Odua;
Ye, ye, ye, yeye, ye awa mase hun, oro
nla nbe;
Yoruba nse r’awon nitori Owó, Yoruba
jin r’awon l’ese nitori ipò;
Won gbebi f’alare, won gba’re f’elebi;
Won pe olè ko wa ja, won tun pe oloko
wa mu;
Ogbon ti won gbon lo gbe won de Ilé Olà,
ogbon na lo tun padawa si tunde won
mole;
Awon ti won ti n s’Oga lojo to ti pe, tun
pada wa d’eni a n f’owo ti s’eyin.
Yo, yo, yo, Yoruba yo yo yo bi ina ale;
Yoruba ru ru ru bi Omi Òkun; Yoruba
baba nse…Yo yo Yoruba ronu o!
Yoruba so’ra won di boolu f’araye gba;
To n ba gba won soke, won a tun
gba’won s’isale o;
Eya ti o ti kere te le ni won ge kuru;
Awon ti ale f’ejo sun, ti di eni ati jo;
Yoruba joko sile regede, won fi owo
l’owo;
Bi Agutan ti Abore n bo orisa re o!
Yo yo Yoruba r’onu o!
Ori ki ma i buru titi, ko bu ogun odun;
Leyin okunkun biribiri, Imole a tan;
Ejeka pe Olodumare, ka pe Oba lu Aye;
k’ayewa le dun ni igbehin, igbein lalayo;
Ile mo pe o, Ile dakun gbawa o, Ile o;
Ile ogere, a f’okó yeri…ile!
Alapo Ìkà, o te rere ka ibi…ile!
Ogba ragada bi eni yeye mi omo adaru
pale Oge…Ile, dakun gba wa o…Ile!
Ibi ti n pa Ika l’enu mo…ile!
Aate i ka, o ko ti a pe Ile…Ile!
Ogbamu, gbamu oju Eledumare ko mase
gbamu lowo aye…Ile…dakungba wa o…
Ile
Ehen, ehen awa gbe ori ile yi pe o;
Eni ba dale, a ba ile lo…peregede o…
ehen ehen awa gbe ori ile yi pe o;
Oduduwa bawa tun ile yi se o…to’wo,
t’omo o…ehen…awa gbe ori ile yi pe o;
Oduduwa da wa l’are o, kaa si maa r’ere
je o…ehen awa gbe ori ile yi pe o!
yo yo yo Yoruba ronu o! if you have a working brain, you will understand the motives behind this thread |
Re: Yoruba Ronu by HtwoOw: 12:01am On Sep 19, 2016 |
reaing later |
Re: Yoruba Ronu by Toluwani113: 1:23am On Sep 19, 2016 |
HtwoOw:Summarize it for me! |
(1) (Reply)
BREAKING: Senate Rejects Sale Of National Asset / Former President Jonathan And Wife, Patience Spotted At Port Harcourt Airport / Osinbajo: How I Became Vice President
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 10 |