Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,201,324 members, 7,978,034 topics. Date: Thursday, 17 October 2024 at 05:38 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1843575 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (88) (89) (90) (91) (92) (93) (94) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by Hert777: 8:39pm On Mar 24, 2017 |
08101646045atwp:ama ju wa se o. Ase. Ejowo se sale lo ike olomori funfun lati ko ISE yii si. Ese pupo. |
Re: .. by Jerrydollar(m): 7:58am On Mar 26, 2017 |
okare! Ejo se elebami fi ran se si ori e-mail:adeoyeJeremiahadesakin@gmail.com.....KULADE A GBEWA O! |
Re: .. by ifadamilola: 10:04am On Apr 06, 2017 |
[quote author=gbengaeba007 post=42212409]Mojuba http://www.google.com.ng/url?q=http://kwekudee-tripdownmemorylane..com/2014/09/ife-people-ancient-artistic-highly_14.html&sa=U&ved=0ahUKEwi96LDlu4_TAhUFnBoKHUpjCRwQwW4IFSgAMAU&sig2=AQVZlvA_6HTHCbAg9hHaJA&usg= http://www.google.com.ng/url?q=http://kwekudee-tripdownmemorylane..com/2014/09/ife-people-ancient-artistic-highly_14.html&sa=U&ved=0ahUKEwi96LDlu4_TAhUFnBoKHUpjCRwQwW4IFSgAMAU&sig2=AQVZlvA_6HTHCbAg9hHaJA&usg=AFQjCNF2HcdJXS9vlSS-efK9JCi9pEHuuw -efK9JCi9pEHuuw agbalagba |
Re: .. by ifadamilola: 6:14pm On Apr 06, 2017 |
ejowo talo ni Ogun ti eniyan le ma fi hun aso ofi bi pack merin tabi marun lojumo eseun gan mo nreti esi padA aboru aboye |
Re: .. by Canme4u(m): 6:49am On Apr 08, 2017 |
Just seeing this. Well done everyone |
Re: .. by skolat1: 11:43am On Apr 12, 2017 |
Adupe lowo gbogbo eyin baba ati eyin iya wa ti en orisirisi ognon ati oye se omo araye Ni anfani. Eseun gan. |
Re: .. by skolat1: 11:45am On Apr 12, 2017 |
Hmmmmmm |
Re: .. by agbakuonida(m): 12:08pm On Apr 21, 2017 |
Aboru boye oo. ejo kin Biscuit Okin ati wipe kini ogun ti ale lo fun ofa tio saka kakiri ara eniyan ti ko ni fi gburo re mo. ese oo ewe amaje oo. |
Re: .. by agbakuonida(m): 1:00pm On Apr 21, 2017 |
baba kini ama fi omi ti aju igbin sinu re fun bi iseju marundilogun Se. ati wipe se igbin ti o gbonu daada leso. ese moreti idahun yin |
Re: .. by agbakuonida(m): 1:51pm On Apr 21, 2017 |
se gbogbo ikan ti ajo yen la ma da si ori epo yen le kanna abi die die fun ijo miran abi se elomiran le lo ninu ogun yi. ati wipe iru Ishana wo la so nipa re gan |
Re: .. by agbakuonida(m): 2:07pm On Apr 21, 2017 |
[quote author=seanjizzyayo post=52803943] kini itumo biscuit okin ati ewe ekuya ati ikilo tio owa ninu ise Yi |
Re: .. by agbakuonida(m): 2:17pm On Apr 21, 2017 |
[quote author=seanjizzyayo post=52007305] ejo bi Ibo ni a tule lo yato si ori apata tori wipe gbogbo eniyan ko lo sumo ibi ti apata wa. ati wipe she osan ni a man lo la mole ni abi ale. ese gan |
Re: .. by raymonddodo(m): 9:49pm On Apr 23, 2017 |
HorlarhMheporzy: pemi |
Re: .. by raymonddodo(m): 9:51pm On Apr 23, 2017 |
odabe |
Re: .. by raymonddodo(m): 10:01pm On Apr 23, 2017 |
Ogun awure owo ewe tagiri aogun pelu ose dudu aofi 200 te inu ike osena aowa ko osena sinu ike na aoma we ki orun toyo pemi fun Ogun gbewa ooo 09079098548 abi Ogun so ewe dowo |
Re: .. by raymonddodo(m): 10:17pm On Apr 23, 2017 |
Ogun anu biro fun wae aowa ewe anu ewe jebure atare eyo lilopo aoro sinu ink biro tuntun odaju ikilo Maya eni kenioo 09079098548 |
Re: .. by IBAAGBA1: 5:06pm On Apr 24, 2017 |
E jowo mo need ogun orobo to nyo nidi,o siti pe lara bakanna,e jowo e sanu mi |
Re: .. by raymonddodo(m): 12:06am On Apr 25, 2017 |
ahhh moti mo unko tose ise NLA nio pemi
09079098548 whtsapp 09060525145 |
Re: .. by raymonddodo(m): 12:07am On Apr 25, 2017 |
ifadamilola: aworo NLA waoo |
Re: .. by IBAAGBA1: 12:51pm On Apr 26, 2017 |
E jowo e fun mi ni ogun ti idi eniyan ba nyo jade to ba nyagbe |
Re: .. by skolat1: 11:52am On Apr 27, 2017 |
Ejowo ewe ama je o. Ejowo mo nilo Atona . Eyin ojogbon ejeki aje anfani re eseun. |
Re: .. by Knight0777(m): 11:25pm On Apr 27, 2017 |
OGUN BIRO RIRE FUN IDANWO Eso yerepe, ewe ina, odidi atare kan, ewe odan, a o jo gbogbo re papo, a o po mo oyin igan gidi, a o da si ibikan a o re biro meta sinu re, a o wa gbe pamo si ibi owo fun ojo meje, leyin ojo keje, a o ko kuro ninu oyin yen a o wa lo bo mo ori sare(grave) tiwon sin oku si fun ojo meta. Leyin ojo keta, okan yio salo ninu biro yen, a o ko meji yoku, odi lilo. Akiyesi: ti okankan ko ba ti salo, aje wipe ko sise niyen o. Ki a tun omiran se. Odaju saka. Iba eyin agbagba ti Odumare ko ile aiye le lowo o. 1 Like 2 Shares |
Re: .. by ipobarecriminals: 3:33pm On Apr 30, 2017 |
kadunasouth:E ka san ni be o.Aboru boye oo.E dakun,iru eyin wo ni a ma lo.se eyin ibile ni abi ewo? Iru ororo wo? E se gan |
Re: .. by skolat1: 10:50am On May 02, 2017 |
Adupe baba, ewe amaa jee oo |
Re: .. by HorlarhMheporzy(m): 12:58pm On May 02, 2017 |
Ejowo se mo le lo koko ti anfi se ounje ninu ile se agbo bi malaria tabi typhoid. abi dandan ni ki nwa koko agbo gangan ni. |
Re: .. by jophins(m): 8:31pm On May 03, 2017 |
Ekale eyin Agbalagba ejowo e add me pada sori whatsapps 07031062770 |
Re: .. by babatunde199325: 2:09am On May 11, 2017 |
se ale lo condom pelu Ogun adodun? |
Re: .. by babatunde199325: 2:12am On May 11, 2017 |
ejo se ale lo condom pelu Ogun adodun...? |
Re: .. by omiaruk: 3:34pm On May 11, 2017 |
Eku ogbon. Oti pe ti Mo ti ma n ro PE she Kosi ogun ibile fun aisan HIV ni? Ejowo ebami daun. Eshe pupo |
Re: .. by jentusoul: 6:40pm On May 14, 2017 |
Babawa KADUNASOUTH, Ejowo tiaba ju eyin naa si orita, se eyin naa konifo, atiwipe se ti eyin naa bafo, se kose nkankan sir |
Re: .. by skolat1: 9:54am On May 17, 2017 |
Ejowo gbogbo eyin agbagba , efun WA OGUN ORIFIFO TUULU.Adupe ooooo |
Re: .. by Wolad(m): 11:47pm On May 19, 2017 |
IBAAGBA1: Ewe Agogo-igun, Eso Iwerejeje (oju ologbo), ako kanhun, ao gun po sinu OTI, mimu... |
(1) (2) (3) ... (88) (89) (90) (91) (92) (93) (94) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 33 |