Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,199,028 members, 7,970,153 topics. Date: Tuesday, 08 October 2024 at 09:53 PM

SisiGbeborun's Posts

Nairaland Forum / SisiGbeborun's Profile / SisiGbeborun's Posts

(1) (2) (3) (of 3 pages)

Culture / Mi O Le Wa Je Ki Awujo Ero Ayelujara Ma Dari Igbesi Aye Mi - Kate Henshaw by SisiGbeborun(f): 5:15pm On Sep 14, 2015
Kate Henshaw, gbajugbaja osere Nollywood ti gba awon ololufe e niyanju lati ma je ki lilo awon awujo ori ero ayelujara bii Facebook, Twitter, Instagram, ati bee bee lo dari igbesi aye won. O so eleyi di mimo nigbati o n salaye nkan ti oju oun ri leyin ti awon kan fesun kan pe o se afihan awon nkan to lodi si ofin ati ilana oju ewe awujo ero ayelujara kan ti won si tii jade nibe.
http://www.sisigbeborun.com/2015/09/mi-o-le-wa-je-ki-awujo-ero-ayelujara-ma.html

1 Like 1 Share

Culture / Wole Soyinka Deruba Oyinlola Pe Oun Maa Fi Oruko E Sinu Iwe Lori Awon Opuro by SisiGbeborun(f): 4:51pm On Sep 14, 2015
Rogbodiyan to n lo lori eni to ni Centre for Black Culture and International Understanding ti gbile si bayi. Lojo Jimoh ni Omowe Wole Soyinka se apejuwe gomina ipinle Osun nigba kan ri, Omoba Olagunsoye Oyinlola gegebi opuro.
http://www.sisigbeborun.com/2015/09/wole-soyinka-deruba-oyinlola-pe-oun-maa.html
Culture / Ara Mee Ri Ri.....Posi Alabere Ni Ghana by SisiGbeborun(f): 1:55pm On Aug 21, 2015
Culture / Idi Ti Don Jazzy Ati Koko Master Fi Yapa by SisiGbeborun(f): 1:20pm On Aug 21, 2015
Politics / Re: Caption This Photo Of Military Men During Their Morning Training In Yobe Today by SisiGbeborun(f): 1:18pm On Aug 21, 2015
Before nko? Who wan die naaa

2 Likes 1 Share

Culture / Awon Onigbeja Kan Ti Wo Fashola Lo Siwaju Ajo EFCC by SisiGbeborun(f): 12:35pm On Aug 13, 2015
Se won ni ko si bi obo se sori ti inaki o se... awon egbe kan ti ni ki Aare Buhari ya gbe'ja fun Babatunde Fashola naa. Won ti fi iwe ebe kan siwaju EFCC pe awon owo kan wa ti Fashola na nigba to wa lori aleefa. won si gbodo se iwadi e

http://www.sisigbeborun..com/2015/08/awon-onigbeja-ti-wo-fasola-lo-si-efcc.html?m=1
Culture / Awon Ololufe Reekado Banks Kolu Leyin To Sere Fun Won by SisiGbeborun(f): 12:25pm On Aug 13, 2015
Awon omo UNILAG yi kala gan o. Nitori shandi, won fo gilaasi moto Reekado Banks....
http://www.sisigbeborun..com/2015/08/awon-ololufe-reekado-banks-koluu-leyin.html?m=1
Culture / Jesse Jagz N Se Ojo Ibi Loni by SisiGbeborun(f): 3:44pm On Aug 10, 2015
O ku oriire o, omo olojo ibi. Igba odun, odun kan.
www.sisigbeborun..com

Culture / O Ma Se O, Omiyale Ni Guusu Asia by SisiGbeborun(f): 9:50am On Aug 04, 2015
O le ni eeyan egberun lo'na egberun to ti f'emi s'ofo ni awon apa ibi kan ni guusu Asia latari omiyale to n ba won finra.....o ma se o.

www.sisigbeborun..com

Culture / A Ku Amojuba Osu August by SisiGbeborun(f): 1:28pm On Aug 01, 2015
www.sisigbeborun..com lo n ki gbogbo yin k'aabo s'inu osu kejo, loni ti n se ojo kini, gbogbo nnkan ti a ba dawo le ninu osu yi ati ti odun yi a fi pari, lo ma ja si rere o. AMIN...
A ku isinmi opin ose.
Romance / Ladies And Big Fat Tummies by SisiGbeborun(f): 5:01pm On Jul 31, 2015
It's quite unfortunate that a lot of ladies nowadays find it hard to cut down on junks and fatty foods....(and you now say your bobo is avoiding you). No matter how big a guy's "amusement park" is....forget about six-packs, you'll discover that such a guy would always crave for a woman with a considerable level of flat tummy. I don't blame them, after all, it's guys that woo the ladies(African mentality). All I see these days is ladies with round protruding tummy....ogini? Please ladies, let's try as much as possible to shed some of these unwanted tummy fat so that, the special man in your life will also see you as his special woman.

2 Likes

Culture / Re: Okunade Sijuwade, The Ooni Of Ife Is Dead by SisiGbeborun(f): 11:22am On Jul 29, 2015
Ki olorun te baba s'afefe rere. E ka iroyin yi ati awon miin ni ede Yoruba nibi - www.sisigbeborun..com
Romance / Re: Commitment In A Relationship by SisiGbeborun(f): 8:16am On Jul 29, 2015
Beautiful submission @Jollyjoy, but you started out on a wrong note. Did u really have to insult d writer? Let's grow up please...and thanks for dropping by.
Romance / Commitment In A Relationship by SisiGbeborun(f): 8:02am On Jul 29, 2015
Who do you think stays more committed in a relationship, the male or the female?

What do you think?
Family / Help! My Wife Won't Sleep In The Same Room With Me by SisiGbeborun(f): 12:15am On Jul 29, 2015
Fred is on the verge of losing it right now. He's been married for close to 3 years but after their wedding night, his wife has since moved to the guest room and that's where she's been sleeping. All efforts to get her to occupy her side of the bed in the master bedroom proved abortive. She maintained that she needs her privacy by all means. Even when they have to make love, Fred will have to go and meet her in the guest room. It seems the situation is getting out of hand now. Please advise....

3 Likes 2 Shares

Politics / Re: Describe Buhari's 2 Months Presidency ... In One Word Or Phrase!! by SisiGbeborun(f): 1:29pm On Jul 28, 2015
Politics / Oya! Les Go Dia by SisiGbeborun(f): 11:36am On Jul 28, 2015
Ti e ba fe ka awon iroyin to make sense ni ede Yoruba, e ma lo jina rara... Sisi Gbeborun ti wa ni sepe fun yin. E lo taara si www.sisigbeborun..com. O ta l'enu gaan
Romance / Re: Telemundo And Women by SisiGbeborun(f): 11:30am On Jul 28, 2015
Jollyjoy:
The last time i checked, this was romance section not movies section.

Op when will yhu learn to obey rules? Did i just hear someone say i wonder? Hmmmm me self i wonder..

Telemundo is the definition of romance...ok?
Romance / Re: Telemundo And Women by SisiGbeborun(f): 11:27pm On Jul 27, 2015
grad2012:
why kilode

Repeat episode tinzz

1 Like

Romance / Telemundo And Women by SisiGbeborun(f): 7:00pm On Jul 27, 2015
Please I'll like to find out if there are Telemundo addicts in the house...which of the telenovelas is your favourite?
I'll start, mine will always be Forbidden Passions...
Culture / Ksa Fe Si Ile Ise Radio Tuntun by SisiGbeborun(f): 1:20pm On Jul 27, 2015
Hehehe, King Sunny Ade ti pinnu lati si Music&Culture radio station. O ni ki odun yi to pari, igb'ohun s'afefe maa bere ati pe ile ise radio ma je akoko eleyi to maa ma gbe asa(culture) ati orin Naija l'aruge.

www.sisigbeborun..com
Culture / O D'aaro, Bobbi Kristina Brown by SisiGbeborun(f): 12:27pm On Jul 27, 2015
O se'ni laanu gidi gidi wipe omo kan soso ti Whitney Houston fi s'aye lo ti je olorun ni'pe leyin bii osu mefa to ti wa ni ese kan aye, ese kan orun. O ma se o.
Ki olorun f'orun ke, Amin.
Culture / Awon Olopa Sweden Ti Fi Snoop Dogg Si'le by SisiGbeborun(f): 9:50pm On Jul 26, 2015
Won ti ni ki Snoop Dogg maa lo l'alaafia leyin ti awon olopa mu ni ilu Sweden.....e ka nkan to se - www.sisigbeborun..com
Culture / Ado Oloro(bomb) Kan Ti Bu Gbamu! Ni Somalia by SisiGbeborun(f): 7:06pm On Jul 26, 2015
O kere tan, eeyan mefa lo ti p'adanu emi won nibi isele buruku to sele ni Mogadishu, olu ilu Somalia.......
www.sisigbeborun..com
Culture / Ijamba Ina Sele Ni Oja Badagry by SisiGbeborun(f): 2:46pm On Jul 26, 2015
Awon ohun ini ti o to opolopo milionu naira lo ti jona l'ana ni iso pako kan ni Badagry ni'lu Eko. A dupe pe eni kankan o ku nibi ijamba ina naa. Ina yi tun jo ile ijosin St Anthony Catholic Church kan to wa ni itosi iso pako naa. Awon panapana tete de ibi ina yi sha lati paa ni nkan bi aago mefa abo irole. Eni kan ti o ngbe itosi iso pako, Hamed, so wipe sa dede ni won ri eefin ti o n jade lati inu awon pako ti won ko jo, ti 'Thinner' si gb'ina ni eyi ti o fa ina nla yi.
Culture / Ojo Isinmi T'o Gbeyin Nini Osu July by SisiGbeborun(f): 9:33am On Jul 26, 2015
A dupe l'owo Olorun fun anfaani to fun wa lati ri ojo isinmi to gbeyin ninu osu keje, odun 2015. Eyin Nairalanders, Sisigbeborun lo n ki yin wipe, ose titun yi a san wa s'owo, a san wa s'omo, a san wa is aiku baale oro....
E ku isinmi oni o.
www.sisigbeborun..com
Politics / Sunday T'o Gbeyin Ninu Osu July by SisiGbeborun(f): 9:25am On Jul 26, 2015
A dupe l'owo Olorun fun anfaani to fun wa lati ri ojo isinmi to gbeyin ninu osu keje, odun 2015. Eyin Nairalanders, Sisigbeborun lo n ki yin wipe, ose titun yi a san wa s'owo, a san wa s'omo, a san wa is aiku baale oro....
E ku isinmi oni o.
www.sisigbeborun..com
Culture / Idaamu Jamb Ati Awon Akeeko by SisiGbeborun(f): 8:06am On Jul 25, 2015
O ti wa n di lemo lemo fun JAMB bayi o...kini ka ti pe eleyi ti won tu n so bayi? #shoro niyen?

**** lipsrsealed nje e ti e ti ri awon aso omode ti MAVINS sese ran fun awon omo tuntun.....o fine baje...hehehe - www.sisigbeborun..com
Culture / Awon Koko Inu Iwe Iroyin To Jade Loni by SisiGbeborun(f): 10:00am On Jul 24, 2015
E lo si www.sisigbeborun..com lati ka awon koko inu iwe iroyin gbogbo to jade loni. Punch, Vanguard....ati bee bee lo.
Culture / Eku'le Ati E K'aabo by SisiGbeborun(f): 2:18pm On Jul 22, 2015
Ti e k'aabo ba je, welcome ni ede oyinbo, e jowo kini eku'le ni ede oyinbo?

Ta lo mo?
Culture / E Maa Ko Owo Yin Bo L'amerika -davido by SisiGbeborun(f): 1:18pm On Jul 22, 2015
Hmm, omode n se bobo yi sa... Davido ma ti pe gbogbo akorin egbe re t'oku. O ni ki won ma ko owo won bo wa si ilu Amerika....fun kini?

www.sisigbeborun..com
Culture / Davido Ati Wizzy Lori Lambogini by SisiGbeborun(f): 12:30am On Jul 22, 2015
A dupe ooo....ija ti pari laarin Omo Baba Olowo(Davido) ati Wizkid leyin ti a gbo wipe awon mejeeji jo ya foto papo ni MAMA2015 to wa'ye ni South Africa. Inu mi dun lati je ko ye yin wipe awon mejeeji ti wo ile agbara orin bayi lati se collabo to l'agbara. Lambogini ni akole orin ti won se l'owo ti orin na de ma jabo ninu osu t'ombo yi.
***okay nau... a ku oju lona

(1) (2) (3) (of 3 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 37
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.