Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,199,029 members, 7,970,159 topics. Date: Tuesday, 08 October 2024 at 10:05 PM

SisiGbeborun's Posts

Nairaland Forum / SisiGbeborun's Profile / SisiGbeborun's Posts

(1) (2) (3) (of 3 pages)

Culture / Fayose Ni Ki Obasanjo Daa Pada by SisiGbeborun(f): 12:06am On Jul 22, 2015
Gomina ipinle Ekiti, Ayodele Fayose ti ni ki Baba Obasanjo daa pada bi owo baba'jebu. O ni Jonathan sise gidi gaan nigba ti o wa lori aleefa....

Nje e gbagbo pe looto ni?

Iroyin yen po ju bayen lo....
www.sisigbeborun..com

Culture / Re: MAMA2015: Awon Nkan Ti Mi Fe Ja Yin Si by SisiGbeborun(f): 11:06pm On Jul 19, 2015
Hehehe, iwo lo ro be...nje omo Yoruba tooto ni e?
Culture / MAMA2015: Awon Nkan Ti Mi Fe Ja Yin Si by SisiGbeborun(f): 10:51pm On Jul 19, 2015
L'ana ode yi ni MAMA2015 waye ni ilu South Africa, to si je wipe awon omo Naija ko meje(7) ninu gbogbo awon ami eye(Awards) ti won fi da awon olorin lati ile adulawo(African Artistes) l'ola...

E woo, ki n ma soro ju, e ka ekunrere awon ishele yen ni'bi - www.sisigbeborun..com
Culture / YAGA!!! Happy Birthday, Wizzy Baby by SisiGbeborun(f): 8:29am On Jul 16, 2015
Omo olojo ibi, Ayo Balogun ti gbogbo eniyan mo is Wizkid ti pe omo odun meedogbon loni. O si ti n gbaradi lati fo lo is ilu South Africa fun ipalemo MAMA award ti o ma waye ni ojo abameta ti o nbo yi. Wizkid yio se ayeye ojo ibi re pelu awon olorin jankan jakan ni South Africa paapa julo awon ti won jo ma fi orin da awon eyan l'araya ni MAMA award. O ku oriire o. Oluwa a de e is fun wa.
Eyin ololufe Wizzy, e ya ki ku oriire
Culture / Re: Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by SisiGbeborun(f): 4:41pm On Jul 15, 2015
omitooguns:
Sisigbeborun, oruko e yi le kuu oo. Oda na...emi ko ka itan ni ri.

Die ninu eyi ti moka ni "Sisi jet'we"..."Tijapa tiroko"..."Ruutu abokoku" ati be be lo...oya e sa wo...ki ni itan ti o da ru ko ye da le lori.


Itan yen da le ori awon akoni meje ti won won lo si'nu igbo irunmole. L'ara won ni Akara oogun, Imodoye, Olohun Iyo, Kako onikumo ekun, ati bee bee lo. Ibi ti mo feran ju ninu iwe yi ni ibi ti won ti so wipe "Awa ti a je akoni je meje"....hehehe

1 Like

Culture / Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by SisiGbeborun(f): 3:40pm On Jul 15, 2015
Itan je ohun to se pataki lati igba awon baba baba wa, le yi to je pe won tun fi le awa odo isin yi l'owo. E je ki a wo itan "Akara Oogun" ninu iwe "Ogboju Ode Ninu Igbo Irunmole". Itan yi je okan pataki ninu awon itan isembaye ti o is je wipe sasa ni ogidi omo Yoruba ti ko ti ni gbo ri.

O daa, ewo ni eyin ranti E je ka sare se ere opolo yen ni pa pa pa....

1 Like

Culture / Obinrin Chinko Yi Ni Laye! Ko Jo O... by SisiGbeborun(f): 12:10pm On Jul 15, 2015
Bawo ni obinrin se ma feran moto ju omo bibi inu e lo?? Kayeefi nla....

Hmmm... Oritsefemi dubule aisan - o ma se o....

E ka ekunrere awon iroyin wonyi ni www.sisigbeborun..com.
Culture / Re: Blogging Ni Ede Yoruba by SisiGbeborun(f): 7:27am On Jul 15, 2015
Call it an innovation, call it breaking away from the norm, it's a way to bring the youths to the realisation that our language(Yoruba) must not be thrown away all in the name of western influence or computer age.
Culture / Blogging Ni Ede Yoruba by SisiGbeborun(f): 6:23pm On Jul 14, 2015
Are you tired of reading stories from different blogs/websites in English language? Igba otun ti de o. E lo taara si www.sisigbeborun..com lati ka iroyin nipa oselu, oge sise, oro to nlo, abbl, ni ede Yoruba. O ta l'enu gaan.....
Nairaland / General / Blogging Just Got Better! by SisiGbeborun(f): 6:08pm On Jul 14, 2015
If you speak and/or write the yoruba language very well, then this is for you. The Yoruba language is a very rich one and it will be nice if we can promote it the best way we can. Visit www.sisigbeborun...com for latest gists and juicy gossips wink. O gbasky gaan

(1) (2) (3) (of 3 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 21
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.