Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,159,517 members, 7,840,204 topics. Date: Saturday, 25 May 2024 at 06:13 PM

Ogbon Awon Agba - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ogbon Awon Agba (3538 Views)

Ogun Eyonu Awon Agba Todaju / Ovie Richard Layeguen Ogbon's 100th Birthday Celebration (Photos) / Asiri Aiye Siwa Lowo Awon Agba Woli (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Ogbon Awon Agba by Knight0777(m): 8:23am On May 01, 2017
Opolopo iru Topic yii loti wa lori forum yii. Sugbon, mo si ikanni yi nitori awon idi wonyi:
1. Opolopo iru ikanni yii to wa, ni Ede Yoruba won ko dan moran to.
2. Opolopo ogbon inu ti awon eniyan nfi sita ni kope to sile se akoba nla fun awon ti won gbiyanju re.
3. Mo nife lati se iranlowo fun awon to nla akoko inira koja nipa ogbon inu ti eleda fi fun mi.
4. Mo fe se afihan agbara iwe ASIRI NLA kan ti opolopo mo si SIX AND SEVEN BOOK OF MOSES ati bi awon baba wa ti ma nlo laye ojoun.
AKIYESI PATAKI
1. Gbogbo asiri ko ni ale fi si ori afefe
2. Mi o gba ki enikeni fi anfani yii se enikeni ni ijamba yala nipa ero ibanisoro tabi itakun ifiweranse email abbl.
3. Koko ede ti a o ma so ni abala yii yio je Ede Yoruba sugbon nigba miran, a le so ede geesi ti ise ba lo si ona ibe.

1 Like

Re: Ogbon Awon Agba by blackylola(m): 8:34am On May 01, 2017
Mo un gbadun re bi oyinbo se n gbadun siga
Re: Ogbon Awon Agba by Knight0777(m): 11:22am On May 01, 2017
ONFA TI ODAJU PELU 5TH TABLE OF SATURN IN THE 6TH & 7TH BOOK

1 Share

Re: Ogbon Awon Agba by blackylola(m): 11:44am On May 01, 2017
Ki ni ewo e? Is there any side effect
Re: Ogbon Awon Agba by Knight0777(m): 11:58am On May 01, 2017
Ko ni eewo boti wule ko mo NIWON IGBA TI ABA TI SE BI MO SE SE ALAYE RE SIBE.
Re: Ogbon Awon Agba by Knight0777(m): 1:27pm On May 01, 2017
AWURE TI AFI NRI OWO KIA KIA

(1) (Reply)

History Of All Tribes That Make Up Biafra And Their Connection To One Ancestor / Can One Say That Yoruba Men Are The Most Wanted In Nigeria Nd Outside Of Nga? / Abiku And Emere; How Pregnant Women Can Avoid Them The Yoruba Perspective

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.