Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,163,222 members, 7,853,151 topics. Date: Friday, 07 June 2024 at 11:56 AM

The Oriki Of Omo Ede - What Is Your Oriki - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / The Oriki Of Omo Ede - What Is Your Oriki (12322 Views)

Oriki - Is There Anything Historical In It For Us? / Oriki Of All Towns In Ekiti State / Oriki Omo Ibadan (2) (3) (4)

(1) (Reply)

The Oriki Of Omo Ede - What Is Your Oriki by Gentlebabs(m): 3:06pm On Apr 17, 2018
Ede mo po rogun.
Omo oye
Omo ako ti inu Ewure ji'yan
Omo ako ti inu Agutan jeka
Omo ako tinu igbin jeko
Omo ape labaje
Omo ewule Ejigbo
Omo abelejo ro
Omo Oba tin' f'Oba je
Omo okun Esin
Pmo binu binu omo oye
Omo Ede mo po rogun
Omo afi ojojumo dara bi Egbin
Omo arun gbado wo ilu
Omo arun guguru wole Ede
Omo Timi Agbale, olo ofa ina."

Rep. your clan, what is your "Oriki"

1 Like

Re: The Oriki Of Omo Ede - What Is Your Oriki by Jimsonjaat96(m): 3:07am On Sep 16, 2019
Gentlebabs:
Ede mo po rogun. Omo oye Omo ako ti inu Ewure ji'yan Omo ako ti inu Agutan jeka Omo ako tinu igbin jeko Omo ape labaje Omo ewule Ejigbo Omo abelejo ro Omo Oba tin' f'Oba je Omo okun Esin Pmo binu binu omo oye Omo Ede mo po rogun Omo afi ojojumo dara bi Egbin Omo arun gbado wo ilu Omo arun guguru wole Ede Omo Timi Agbale, olo ofa ina."
Rep. your clan, what is your "Oriki"

Olofamojo, Olofa Omo Ola Nlo Olalomi a b'isu jooko, Ijakadi loro Offa. Ija peki abe owula. Bi ko se oju ebe l'Offa A s'oju poro l'oko. Iba s'oju oloko iba lawon. O s'oju agunmona l'Offa. O s'oju agbeleyarata. O s'oju aporubukako. Kinni nse kagun-kakanrun ni ile Oba? Oka ni nse kagun-kakanrun, Agbado ni agunmona l'Offa Eere ni agbeleyarara, Isu ni aporubu ka oko. Omo odi meta ti nbe l'Offa Odi ti iwaju ni ti Olusanmi Odi aarin ni ti Olumonrin Odi ti eyin ni ti Olugbense Omo Ayejin Omo odo meta kan ti tun nbe l'Offa Ikan ni ka pa erin nla bo oun ki oun di okun Ikan ni ka pa agbo bo oun ki oun di osa Ikan ni ka pa akuko ganga bo oun ki oun di ogbaagba Oba ni okookan Offa ti t'Agbo ra, odoodo won ti to erinla pa. Sugbo bi okan ba di okun, ti okan ba d'osa Nibo ni a ko omo iyebiye wonyi si? Eyi ti a pa erin nla fun o le d'okun Eyi ti a pa agbo fun o le d'osa Eyi ti a pa akuko ganga fun, se oun lo di ogbaagba O d'Aguloko l'Offa O di omi ti gbogbo Olalomi nmu... Peki mo ba Odofin dimu. Mose Ojomu kanrin kese, Mofi eyin Saawo ra'le l'Offa Offa o m'aka Arijasoro, Olalomi lo laare Offa o m'aka, egun eru wole l'Offa oju ti omo lo. Omo okuta meta nsese nsese Ikan ko mi l'ese Ikan se'mi ni pele Ikan se'mi rora Ikan ni, nigbati mio m'ona, kinni mo wa de ilu ero? Ikan ni, nigbati mio m'ona, kinni mo wa de ilu ete? Ikan ni, nigbati mio m'ona kinni mo wa de ilu ilu owonwo? N'ile Olalomi, nibi ti omi ti won to ju oti lo. Ede Okin ti mo ri Okin bumu. Ti mo fi Abata sin ese l'Offa Ti mori Abelenje b'oju, omo la k'Offa o kun keekee Ara Lale, Olalomi omo orubo nla ti o subu l'aro Papa ni ohun bata. O nki mi, O nla mi; Olalomi, talo seun ninu ara won? Ileyi ko gbaaye, a ko lo si Ilofa Nigbati Ilofa ko gbawa, a ko losi Offa Oro Nigbati Offa Oro ko gba wa mo, a ko losi Offa Irese Nigbati Offa Irese ko gba wa mo, a ko losi Igbolotu, Nigbati Igbolotu ko gba wa mo, a ko losi a tun pada si Offa Eesun Nigbati Offa Eesun ko gba wa mo, ni a wa ko si Offa Arinlolu...... Olofa se pele o Akeeruya ni mon ibi oku ope Amokooko ni mon ibi amon gbeepo, Omo oju ti daro daro onimoka. O daro tan. Owo re dudu. Aro dudu ko ya bumu. Ede Olele, aro ko ya buwe Ede Olele, aro ko ya bu boju Igun ni mo ri ni mo d'asa geru. Akala ni mo ri ni mo d'asa j'edo Olofa Imole mo a ri ni mo wa d'asa lami labe Olalomi ni mo ri ni mo d'asa lami lapa Oosi rora lami, t'ooba lami, maje ki obe o jinle lapa mi...

(1) (Reply)

New Blog By A Hausa/fulani Woman Living In England / Ibibio Marriage Rites / Adewole Akanbi: Amotekun Should Fight Ritual Killings, ‘Traditional Corruption’

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 16
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.