Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,160,205 members, 7,842,515 topics. Date: Tuesday, 28 May 2024 at 09:49 AM

Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán - Culture (4) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán (2848 Views)

Àwọn Èso Ati Irúgbìn Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Awòrán / Transportation In Yoruba Land (àwọn Ọ̀nà Tí À Ń Gbà Rin Ìrìn Àjò) / Ònkà - The ABC Of Yorùbá Numerals (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (Reply) (Go Down)

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:43pm On Nov 09, 2023
Ẹiyẹ Awó/Ẹtù — Guinea fowl

Akọ — Ẹtù
Abo — Awó

Popular saying:
1. Àgbà L'ẹtù

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 2:36pm On Nov 09, 2023
Alápáǹdẹ̀dẹ̀ — Swallow

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 2:48pm On Nov 09, 2023
Àtíòro/Àtíàla — Hornbill

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 2:50pm On Nov 09, 2023
Àkàlàmàgbò — Ground Hornbill

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 3:18pm On Nov 09, 2023
Yanja-yanja — Snakebird/Anhinga

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 3:42pm On Nov 09, 2023
Adìyẹ — Chicken

Akọ — Àkùkọ
Abo — Abo Adìyẹ
Awọn ọmọ — Òròmọ Adìyẹ

Popular Proverb:
1. Kíkere L'abẹ́rẹ́ un kere, Ko kìí ṣe mímìn Fún Adìyẹ

2. Adìyẹ t'ó ṣu Tí kò tò, Ara rẹ̀ l'ó wà

3. Bi Ojú Akátá bá Li Ewo, Ṣe Ẹnu Adìyẹ L'ó yẹ K'á ti gbó-ọ

4. Àyè Kìí Há Adìyẹ, K'ó má lè dé ibi ti ẹyin to wà

5. Jàmbá Ti ó un kó Ẹyin lọ l'óri Àba, Ti A bá Dáké, Gbogbo Àkùkọ ìlú L'o ma lọ Síi

6. ìfẹ́ tí A fẹ́ adìyẹ kò de'nú, L'eyin kó dágbà K'a pa-a jẹ — Ibi pípajẹ L'o Mọ

7. Àgbà t'o so yàngán mọ ìdí, L'o sọ ara rẹ̀ di aláwadà fún Adìyẹ

8. Adìyẹ un sunkún Aìlẹ́yin, Àjànàkú ùn sunkún Ai-r'étè bo ti ri

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:13pm On Nov 09, 2023
Àparò — Partridge

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:13pm On Nov 09, 2023
Ògòngò — Ostrich

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 6:12pm On Nov 09, 2023
Ìbákà — Canary bird

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 6:26pm On Nov 09, 2023
Àkókó — Woodpecker

Popular Proverb:

1. A ùn Pe Gbénàgbénà, Ẹiyẹ Àkókó Na ùn Yọjú

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 6:38pm On Nov 09, 2023
Ẹiyẹ Afìyẹ́lúlù — Hummingbird

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 7:32pm On Nov 09, 2023
Ẹiyẹ Òfú — Pelican

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 7:35pm On Nov 09, 2023
Agbe — Blue Turaco

Popular Saying:
1. Orí Agbe A jà fún Agbe, Orí Àlùkò, A Jà Fun

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 7:37pm On Nov 09, 2023
Àlùkò — Cardinal

Popular Saying:
1. Orí Agbe, A jà fún Agbe, Orí Àlùkò A jà fún

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 7:57pm On Nov 09, 2023
Ẹiyẹ Àwòko — White-banded mockingbird

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:01pm On Nov 09, 2023
kannakánná — Pied Crow

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:06pm On Nov 09, 2023
Òtété — Purple glossy starling

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:15pm On Nov 09, 2023
Àrọ̀nì — Scarlet-Chested Sunbird

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:17pm On Nov 09, 2023
Oriri — Red-billed Wood Dove

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:18pm On Nov 09, 2023
Ẹiyẹ Òrofó — African Green pigeon

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:37pm On Nov 09, 2023
Olófèéèré — African Swift

This Bird slam body for mirror well well 😂😂

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:49pm On Nov 09, 2023
Àgbìgbò — African Grey Hornbill

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:55pm On Nov 09, 2023
Ẹ̀lúlùú — Coucal

Popular Proverb:
1. Ẹ̀lúlúù T'o un Fa Òjò, Orí Ara rẹ̀ L'ó ùn fàá Lé

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 9:01pm On Nov 09, 2023
Ẹiyẹ Ọba — Yellow-crowned Gonolek

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 9:04pm On Nov 09, 2023
Olóbùró — Nightingale

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 9:08pm On Nov 09, 2023
Olongo —Orange-cheeked waxbill

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 9:10pm On Nov 09, 2023
Ògé — Egyptian plover

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 9:17pm On Nov 09, 2023
Aṣẹ́rẹ́/Aáṣẹ́ — Standard winged nightjar

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 9:23pm On Nov 09, 2023
Àkẹ̀ — Seagull

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 9:28pm On Nov 09, 2023
Ògbùgbú — Swan

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 9:35pm On Nov 09, 2023
Ológiri — Palm bird Cockatoo

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 9:54pm On Nov 09, 2023
Kowéè

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (Reply)

A Lesson To Learn From Bolivia / Reason Why The Yoruba's Are The Most Successful Tribe In Africa (facts) / Ashamed Of Being African/ Black - Someone Help Me Overcome My Complex!

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 15
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.