Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,201,518 members, 7,978,715 topics. Date: Friday, 18 October 2024 at 01:01 PM |
Nairaland Forum / Entertainment / Literature / Oriki Orile (10665 Views)
Orin Orile Ede Naijiria Ni Ede Yoruba Ati Ni Geesi (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Oriki Orile by oloriireomo(m): 3:09pm On Sep 11, 2013 |
IKOYI ESO Aporogunjo ikoyi gbera n le o dide ogun to lo, Ojo kinni to nikoyi ku, oju mi paa lose agba ni mi Ko tii da,sugbon mo kuro lomo agbekorun lo inu oko. Won gbele won bo onikoyi mo nipekun orisanla,agbedegbede onikoyi lo sun ibe,Atari onikoyi Ko sun ibe, eyin lomo asiju apo piri dagba ofa sofun,pofun yoo yo dagba ofa sile,omo aku fepo tele koto,omo igunnugun bale won a jori akalamagbo bale won a jedo 1 Like |
(1) (Reply)
My Encounter With The Lesbians / Against Her Wishes / Romantic Story : - My Boss (18+) Episode 1
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5 |