Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,174,250 members, 7,891,197 topics. Date: Tuesday, 16 July 2024 at 09:43 AM

Ore Ti Ko Common - Literature - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Literature / Ore Ti Ko Common (798 Views)

A Yoruba Poem: Mura Si Ise Ore Mi. / Êru ti Ife - Ashes Of Love. / Awaye Aiku Ko Si (the Warrior's Requiem For Korede Oladipo) (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Ore Ti Ko Common by oloriireomo(m): 12:48pm On Nov 21, 2013
True touching heart story,i must read.
Onkọtan- oloriire ọmọ
Akọle : oore ti ko common

Ọgbẹni kan de si ilu eko lati oke okun.ọmọ bibi ilẹ gombe ni,sungbọn oke okun lo tẹdo si lati ìgbà ewe rẹ,idi nipe ibẹni awọn obi rẹ f'Orí rẹ sọ'lẹ si.
Ko de ilẹ adulawọ ri.

Ni owurọ ọjọ kan o de si ipinlẹ eko,lọwọ awọn ero ti o ko lọna o beere,,' ẹ dakun mo ń wa arakunrin kan ti o dudu diẹ ,ti o ni irungbọn yẹhukẹ,ti o ga diẹ ,ti o ni sasa loju,'rárá o,ako mọ ẹni naa "awọn erona fesi. ko s'ẹni to mọ ẹni to ń sọ ,wọn si ro wipe Orí rẹ ti ń yi diẹ diẹ ni tabi o ti ta ogogoro diẹ sọfun.

Ko pẹ pupọ ti akusẹ ẹlẹmu kan to ń fi kẹkẹ kiri ẹmu ń kọja lọ.arakunrin yii ri ,o sare tọọ lọ ,o sunmọ .tọwọ- tọwọ o wipe"ẹ ma binu sa,ẹyin ni mo wa wa lati oke okun....Ọlọ́runwipe okunrin kan wà ni ilu eko, o dudu diẹ , o ni irungbọn yẹhukẹ,o ga diẹ ,o ni sasa loju ni eyi ti o tumọsi pé ẹ yin ni ẹni naa.mo ti daamu jinna ,lati ijẹta ni moti ń daamu kaa kiri. Ọlọ́run wipe ki ń saanu fun yin.ẹ ma binu pé mo gba akoko yin.ẹ gba sọwedowo yi ,millionu mẹwa ni mo kọ si inú ẹ,ki ẹ gba owo naa ni ile ifowa pamọ banki akọkọ ti o ba sunmọ agbegbe yin.ko tán sibẹ o, ẹgbẹrun lọna aadọta naira niyi ki ẹ fi s'owo apo nitori pé ẹ le ma i tii raaye lọsi ile ifowopamọ.ẹ gba kọkọrọ ọkọ ọlọyẹ ti mo wà gunlẹ si ọọkan yẹn.ẹ dakun ẹ ma binu pé mofi akoko yin sofo,ti mi o ba se nnkan ti mo ń se yi ara koni dẹmi ,'ọgbẹni wi.",kinni ń o fisan -an fun ọ Ọlọ́run mi ,iru oore ń la banta banta ti o se funmi yii?,'ẹlẹ mun wi,osi daku loju ẹsẹ.

Omi garawa mẹwa ni wọn dale ́ lórí koto pada ji saye.loni yii,ọgbẹni ẹlẹmu ti ni ile ni V.i (victoria iland)ni ilu eko.osi ti di ẹni ti ń lọsi oke okun bí ẹni to ń lọsi ọja.
Ni fẹẹrẹfẹ ti o ku ki ọdun yii o kẹru rẹ ń lẹ,mo wure fun ọgbọn ènìyàn ti o ba ri amin kan se tabi fẹran :
•Ni ibikibi ti oloore rẹ wà,ara koni rọ'kun kosi ni rọ adiẹ rẹ afi bo ba se ọ loore.
•Afẹfẹ koni fẹ ko ma kan igi oko lara...ni ibi kibi ti alaanu rẹ ba wà koma wa ọ .boba ń sun ko taji,boba ń rin ko tẹsẹmọrin máa bọ lọdọ rẹ .

•Alaanu rẹ yoo wa ọ ri.

• Loni , ọrun si iwe iranti kan ọ

•Ni aye rẹ,ibanujẹ k'ẹru rẹ .

•Ibanujẹ kẹru rẹ

• Ẹkun oun ose k'ẹru rẹ.

• O ti dagbere fun osi loni.

• O dagbere fun isẹ(poverty).
[b]True touching heart story,i must read.

[/b]True touching heart story,i must read.

Re: Ore Ti Ko Common by akejujoe(f): 2:06pm On Nov 21, 2013
Amin o

(1) (Reply)

A Boy's Diary / Resist Bad Habits Today!! (a Must Read Article For All) / The Girl At Shoprite

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 43
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.