Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,174,246 members, 7,891,172 topics. Date: Tuesday, 16 July 2024 at 09:27 AM

Olómo Ló Layé.omo Wa Ò Nì Kú Mó Wa Lójú - Literature - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Literature / Olómo Ló Layé.omo Wa Ò Nì Kú Mó Wa Lójú (813 Views)

IBADAN Ni Mo Wa - My Ibadan Lifestyle / Ìyàwó Wa (our Bride) / Chronicles Of Omo Pastor | Episode 7 (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Olómo Ló Layé.omo Wa Ò Nì Kú Mó Wa Lójú by oloriireomo(m): 5:42am On Nov 25, 2013
""By;olóríire omokótuòjíire èjíwòrò

|}-Olómo ló layé,
Èdùmàrè wá fúnwa lómo àmúsèye.
Omo tíí tójú ará,
Tíí tójú ile,
Tíí tójú òbí,
Fúnwa lómo àtàtà.
Tíí múnú ìyá dùn!
Gbogbo omo tuntun tin be láyé,
Orógbó lóní kéegbo,
Gbó pèlú ìdèra.
Omo owó kìí kú lójú owó, omo esè kìí kú lójú ese
àwon Omo wa ò níkú.
Tiyin naa ò ní dàgbégbín bí èbù isu.
Odoodún la n rórógbó,
Odoodún la n ráwùsá,
Odoodún la n rómo obì lórí àte.
Lodoodún ni lolorun o fomo rere
Ke gbogbo en to nwomo.
Bibi la bimo tunntun,
Èdùmàrè jómo tuntun ò dàgbà
Koun náà ó dolómo láyé.
Kulukulukulu omo weere
Lódèdè gbogbo wa.
Aboyún inu ko bi tibi tire,
A kìí gbèbí ewúré
Akìí gbèbí àgùntán
Lójó ìkúnlè aboyún.
Ká gbóhùn ìyá
Ká gbó tomo titun
Wéré lewé nbó lára igi
Gbèdè níí ro kókò lágbàlá
A taboyun a ti koko!
Yio royin lorun gbedemuke.
Omidan to n woko
Koluwa o funwon lóko rere.
Àpón tí òlaya,
Gbaya rere kowon lona.
Aya eleso.
Ogede kii gbodo ko yagan
Je ki won o fowo bosun ki won fi pamo lara
A tomidan a tapon
Èdùmàrè wa dawon lohun lasiko
Agbe níí gbére pàdé olókun,
Alùkò níí gbére pàdé olósà
Koluwa o gbomo rere pade awa.
Bíná bákú á feérú bojú
Bógèdè bá kú a fomo è rópò.
Ojó táa bá pajúdé
Omo rere ni kó jogú wa .

1 Like

Re: Olómo Ló Layé.omo Wa Ò Nì Kú Mó Wa Lójú by yolanda233(m): 6:06am On Nov 25, 2013
This is good and great way to start the day!we need more !!
Re: Olómo Ló Layé.omo Wa Ò Nì Kú Mó Wa Lójú by DEllaluv(f): 3:44pm On Nov 25, 2013
Na wa o....translate pls
Re: Olómo Ló Layé.omo Wa Ò Nì Kú Mó Wa Lójú by AdeDelaw(m): 9:13am On Nov 26, 2013
9ce job, keep it up.
Re: Olómo Ló Layé.omo Wa Ò Nì Kú Mó Wa Lójú by ninja4life(m): 12:15pm On Nov 26, 2013
Nice piece,hope d next one will be a story in yoruba
Re: Olómo Ló Layé.omo Wa Ò Nì Kú Mó Wa Lójú by ayando(m): 12:34pm On Nov 26, 2013
hmm, nice. you tried with the ami(sign).
Re: Olómo Ló Layé.omo Wa Ò Nì Kú Mó Wa Lójú by oloriireomo(m): 6:06am On Dec 16, 2013
Thank u all

(1) (Reply)

Man On Fire (action Story) / The Joy Of Every Writer / Jigawa Corper

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 9
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.