Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,197,942 members, 7,966,486 topics. Date: Friday, 04 October 2024 at 03:29 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / African Poetry: Ise Loogun Ise - J.F Odunjo (7503 Views)
British Tottenham Choir Singing Yoruba song - Ise Oluwa / A Yoruba Poem- Ise Logun Ise (work Is The Antidote For Poverty) / Timeless Yoruba Poem By J.f Odunjo (2) (3) (4)
(1) (Reply)
African Poetry: Ise Loogun Ise - J.F Odunjo by obaede: 6:22pm On Oct 04, 2014 |
Awon Yoruba ni bi onirefin ko ba fingba mo, eyi to ti fin ko le parun laelae. Okan lara awon gbajugbaja ewi akosori ile iwe alakobere nigba kan ri ni yii, eleyii ti opolopo awon agbalagba aye ode oni ka ninu iwe Alawiye ti won koko te jade lodun 1943. Nje eyin si ranti bi? Ise l'ogun ise Mura s'ise ore mi Ise la fi n'deni giga Bi a ko ba reni feyin ti Bi ole la'nri Bi a ko ba reni gbekele A tera mo'se eni Iya re le lowo lowo Baba re le lesin lekan Bi o ba gbo'ju lewon O te tan ni mo so fun o Ohun ti a ko ba ji'ya fun Se kii le pe lowo Ohun ti a ba fara sise fun Nii pe lowo eni Apa lara Egunpa niyekan B'aye ba n'fe o loni Bi o ba lowo lowo Aye a ma fe o lola Tabi ki o wa ni'po atata Aye a ma ye o si terinterin Je k'o de'ni tin rago Aye a ma yinmu si o Eko si'nso ni d'oga Mura ki o ko dara dara Bi o si r'opo eniyan Ti won f'eko s'erin rinrin Dakun ma f'ara we won Iya n'bo fun'omo ti ko gbon Ekun n'be fun'omo to nsa kiri Ma f'owuro sere ore mi Mura si'se ojo'nlo. www.olayemioniroyin.com/2014/09/ewi-ise-loogun-ise-jf-odunjo.html?m=1 3 Likes |
Re: African Poetry: Ise Loogun Ise - J.F Odunjo by 2prexios: 10:26pm On Oct 08, 2014 |
b'omode ba k'oyan ale, awon aga a f'itan b'ale. G.F. Odunjo, bi o tile je wipe baba ti ku, sugbon ise rere ti won fi sile ko ni parun laelae. Ile Akoko latii gbedo. Baba lo kowa labidi, won kowa labidi olowe, baba kowa bi a ti maa ko moo ka, baba kowa ni 'tan Mojisola Alaso Oke. Awaye iku osi. Boba se pe aiku laye, aba ba Awolowo, baba ninu Oloselu, Ababa Asikiwe, aba ba Muritala, ti won nfi orin ki lojoun ana. Owu ni ka jeran pe lenu, ounfa onafun o je. Bi mo ba wo rere ile aye, ti mo ranti baba to bi mi, okan mi a si maa ranmi leti pe baa ba bini, oye ka tunra eni bi, ka se oun to to nitori, iku o dojo arun o dosu, ojo a ba ku laa dere. Iku o mara beeni ko menikan. Iku o kuku mo majesin beeni ko meni oosa. Ise rere loye ki koowa o maa se nitori pe, ojo atisun lebo. Eledua nii ku soni ni gbogbo ojumo tii mo, rere ni koju wa o ri l'otu ife rere, nibi oju tii mo wale aye. Laini deena penu, Alawiye laba maa pe ni akomolede, alawiye naa tun loye ka maa pe ni sagbade, oun naa lore ewe. Eyin ewe iwoyi eye elo ni suuru, ogbon ni baba nfi'tan igba atijo koni. Onisuuru nii fun wara Kiniun, Omo atata, kaka kin bi egba obun, ma kuku bi okansoso oga, ma roun yan araye loju, ma roun gberaga: se okansoso araba, kii segbe egba osunsun, omo to jafafa kan soso, kii segbe egba irunbi omo. To, akewi nrele na, o tan lenu, o ku nikun. O digba, Ori rere lakuro nlo nibu omi. |
Re: African Poetry: Ise Loogun Ise - J.F Odunjo by Cathyla: 11:53am On Sep 24, 2018 |
One of the great men time will never be able to represent... Rest on baba J.F ODUNJO |
(1) (Reply)
Cushite People / Man Calls Woman ‘n***a’ Told Her To f*ck Off.Turns Out She's The HR... / New Igbo Words In Nsibidi
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 16 |