Stats: 3,176,901 members, 7,899,244 topics. Date: Wednesday, 24 July 2024 at 09:36 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Nigeria's National Anthem In Yoruba Language (36768 Views)
Degrading State Of Nigeria National Park-old Oyo. / .... / Best National Anthem In The World (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Nigeria's National Anthem In Yoruba Language by sugarboii(m): 6:58am On Apr 08, 2015 |
Very Lovely....... Take a look.... It Reads: VERSE 1 Dide eyin ara Waka je ipe Naijiria K'a fife sin 'le wa Pel'okun at'igbagbo Kise awon akoni wa, ko mase ja s'asan K'a sin t'okan tara Ile t'ominira, at'alaafia pelu iso'okan VERSE 2 Olorun Eleda To ipa ona wa F'ona han asaaju K'odo wa m'otito K'ododo at'ife po sii K'aye won je pipe So won d'eni giga K'alafia oun eto le Joba ni 'le wa THE PLEDGE Mo se ileri fun Orile-Ede mi Naijiria, Lati je olododo, eniti o see f'okan tan Ati olotito eniyan Lati sin in pelu gbogbo agbara mi, Lati sa ipa mi gbogbo fun isokan re Ati lati gbe e ga fun iyi ati ogo re. Ki Olorun ran mi l'owo 1 Like |
Re: Nigeria's National Anthem In Yoruba Language by Yannahowen(m): 10:57pm On Jan 28 |
You are very stupid 2 Likes |
(1) (Reply)
Douzy - The Individual / Pictures Of Python Found In My Compound Last Night At 2am / Car With Learner Sign Crushes Six Children To Death In Edo
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6 |