Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,201,398 members, 7,978,265 topics. Date: Friday, 18 October 2024 at 01:09 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1843622 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (21) (22) (23) (24) (25) (26) (27) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by edrys(m): 9:22pm On Sep 25, 2015 |
Eku Ise takukun lori Ikanna yi, Eledua A pelu gbogbo wa. Ejowo mo ni lo, elo Ose Ero fun tita, igbonna, ati Eyin fun Omo ikoko. Ati Irufe Ogun to le se Omo Owo l'afani. Ese ngo ma reti.@ healthfirst, kadunasouth. |
Re: .. by orisafemi: 8:11am On Sep 26, 2015 |
iba omode iba agba iba okunrin iba obinrin ejowo gbogbo agba ologbon oni mimon oloye gbogbo yin pata pata ni moju ba yin ejowo gbogbo eyin ti eba mon nipa ogun (adesun)gbogbo yin patapa ni mope ejowo se ogun adesun se owo ti eyan bafi si orire ti eyan fida ajo se ti eyan bamu se owo ye amapada si ori oga yeni abi bawo ni ase mamu ni ojo jumon ejowo gbogbo eyin agbalagba ologbon onimi mon ti emon nipa ogun adesun yin dada ejowo mofe jeki efiye mi dada seti awa ti ojewipe afi ogun sise jeun akan mase ogun ni tori afa ni arara wa ati awa eyan wa ejowo ti irun awaba bayi base irun ogun yin se omo wa koni kun ejowo ese alaye re fuwa dada olohun ni mofi beyi o 1 Like |
Re: .. by olabode800(m): 4:26pm On Sep 26, 2015 |
baba keepe o. Ejo kini ogun ti o daju fun ofa ara. |
Re: .. by isdula: 2:49pm On Sep 27, 2015 |
ewe ama je ooooooooo....eju wo kini ogun ti eniyan koba le ni kanlee dada..... |
Re: .. by Davidifa(m): 4:25pm On Sep 27, 2015 |
Ejo Adeesu yi se ti a ba se fun eniyan se omo eni tose ose yi fun eniyan lo ma ku ni abi eni to loo? |
Re: .. by Ade231(m): 9:58pm On Sep 27, 2015 |
healthFirst: Eku deede asiko yi o baba eku ojo meji o asi ku odun o,ejowo tori eledua kini eewo Adeesu yi eso fun wa mo fi eledua beyin,tori eru ma n ba emi fun irufe awon oogun bayi. 1 Like |
Re: .. by Sobandemojisola: 5:49pm On Sep 28, 2015 |
E e |
Re: .. by Nobody: 3:09pm On Sep 30, 2015 |
x 4 Likes |
Re: .. by Nobody: 3:10pm On Sep 30, 2015 |
Ade231: E ka daada..mo ti so eewo re sibe. |
Re: .. by Nobody: 3:15pm On Sep 30, 2015 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 3:38pm On Sep 30, 2015 |
x 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 3:45pm On Sep 30, 2015 |
x 2 Likes |
Re: .. by sammyjay76(m): 4:06pm On Sep 30, 2015 |
kadunasouth:IBA ARA IWAJU O, IBA EYIN AGBA GBA, E JOWO ISE YI SE FUN ENI KAN LO LE LO NI? ABI ELOMII LE LO NINU E? EDAKUN EFOYE YE NI O. |
Re: .. by Davidifa(m): 4:43pm On Sep 30, 2015 |
Ejo ki ni mo le fi ta okada mi ni kiakia tori mo need owo nikiakia |
Re: .. by Davidifa(m): 4:46pm On Sep 30, 2015 |
Ewe ama je ooo,ejo adeesu yi ti a ba se fun eniyan sebi eni to ko owo ori alagamo ni omo re a ma ku? |
Re: .. by jamiu3209(m): 6:25pm On Sep 30, 2015 |
Eku deede asiko yi, ewe ama je o....ejo wo moni nidi Ogun Ariran ati Ki Ogun maa ran Eniyan tiwon ba naa yan ni nkan...e seun mojuba |
Re: .. by kadunasouth(m): 6:57pm On Sep 30, 2015 |
Awure Owo Olosekan Ao wa oga gbigbe ti irure ka dada ao ra isasun tuntun olomori kekere odidi atare kan ao fi atare kan si legbe ao jo ao lo ra aso funfun opa kan kio te sile ki owa fi miliki olope kan lo lori aso funfun ati koko ati aso yi loju si ori atan. Ona owo yio si fun o kosi aburu kan kan lori iseyi NB ti yio ba je funo isere koju osekan lo, Ale se ise yi lojo lasan sugbon ojo sunday lodaraju ijo tabajo lagbodo lo 4 Likes 1 Share |
Re: .. by Ade231(m): 8:10pm On Sep 30, 2015 |
kadunasouth: Mojuba eyin agbalagba o ewe a ma je o ejowo se inu isasun titun yi ni ao ti po ebu yen pelu milk ni abi in nkan miran bi cup abi abo eseun gaan ewe o ma je fun wa o. 1 Like |
Re: .. by kadunasouth(m): 8:21pm On Sep 30, 2015 |
Ade231:Ele lo ninu cup asile lo isasun ye na kafilo sugbon akogbodo fi isasun yi jo isemiran ao lore jusi ori akitan nio 1 Like |
Re: .. by Ade231(m): 8:22pm On Sep 30, 2015 |
healthFirst: Baba health eseun pupo eledua koni fi yin sile nigba kankan gbogbo nkan yin koni dojuru lola eledua ejowo se ao ni fi kainkain we rara ni abi ao lo kainkain ti aba ma lo titun kankan ni ao ma lo ni ojo kankan ni abi eyokan ni ao fi we iwe na tan ema pe fun wa o...Ase. 2 Likes 1 Share |
Re: .. by Ade231(m): 8:27pm On Sep 30, 2015 |
kadunasouth: Ese gaan baba ao ma ri yin ba lola eleduwa ko si ni pada leyin gbogbo wa,ema binu o se ihoho ni ao wa ti ao fi lo ise yi ni abi ale wo aso sorun se ese gaan. 1 Like |
Re: .. by kadunasouth(m): 8:48pm On Sep 30, 2015 |
Ade231:Ewo aso sorun aso fufun dara asilewo eyi keyi ninu aso tabani 2 Likes |
Re: .. by enigstil(m): 9:07pm On Sep 30, 2015 |
Iba gbogbo awon agbalagba to n be lori ikanni yi.Edakun mofe mu wa gege bi aba, yato si awon ogun ti o je fun isora ati eto wa, mofe ki ama fi ti ilera na si dada. Edakun se ari enikeni to mo nipa ogun Cancer bi? |
Re: .. by enigstil(m): 9:15pm On Sep 30, 2015 |
Aboru boye o baba, edakun kini itunmo ti oju orun ba pari? healthFirst: 2 Likes |
Re: .. by Davidifa(m): 10:15pm On Sep 30, 2015 |
Ejo kini mo le fi ta okada mi ni kiakia |
Re: .. by isdula: 6:14pm On Oct 01, 2015 |
ewe ama je ooooooooo....eju wo kini ogun ti eniyan koba le mi kanlee dada..... |
Re: .. by Nobody: 7:30pm On Oct 01, 2015 |
Iba Eyin Agba O, Ki A Ri Yin Pe, Ewe A Ma Je O. Ejowo Se Ewe Yi Ni Won Pe Ni '' Rerinkomi "
|
Re: .. by afeezwaheed8: 4:12pm On Oct 02, 2015 |
Baba oo ke pe Oo. Ama juse fu n yio. Ejo mo ma n ti n pe ero ibani soro yin ko lo. Ejo mo fe bayin soro |
Re: .. by Davidifa(m): 10:16pm On Oct 02, 2015 |
Ti a ba se adeesu fun ore se inkan ko ni se mi sha |
Re: .. by KolaBELIEVE: 3:57am On Oct 03, 2015 |
healthFirst:eku ise ooooo! Ejowo mo nilo osole 1 Like |
Re: .. by enigstil(m): 6:06am On Oct 03, 2015 |
Benni ohun ni, Yoruba tun ma pe ni, imi esu. owonoko: |
(1) (2) (3) ... (21) (22) (23) (24) (25) (26) (27) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 41 |