Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,211,368 members, 8,011,545 topics. Date: Sunday, 24 November 2024 at 08:38 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1847216 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (27) (28) (29) (30) (31) (32) (33) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by kadunasouth(m): 1:11pm On Nov 01, 2015 |
Ogbe-fun 2 Likes
|
Re: .. by kadunasouth(m): 1:14pm On Nov 01, 2015 |
Ifa re ni lokeyi Bostilo: 1 Like |
Re: .. by Bostilo: 2:27pm On Nov 01, 2015 |
kadunasouth: Ogberi nimi koye mi raara. Esanu mi |
Re: .. by omoalade144(m): 8:04pm On Nov 01, 2015 |
akaale o baba, ejoo kilo nje ajesi adie, atipe kini won pe ni ikobere |
Re: .. by omoalade144(m): 8:10pm On Nov 01, 2015 |
Ewe amaje sir o, ejoo ki lonje ajesi adie,atipe kini onje ikobere.eseun agba yin adale |
Re: .. by Nobody: 10:35pm On Nov 01, 2015 |
Ifa ni; Mo yó kèsèkèsè Mo gbàdè borì Mo yòlè-yòlè Mo f`èjigbàrà ìlèkè òun okùn borún Emi ò mó`kan Emi ò mó`kan Mo gorí ìlé Olójà Èsò ilè –Ifè wòn rí mi Wón n yanso ò ró Àgbáágbá Ifé wón ri mi Won n láwúú borún Òbíbí má bí mí lu igún Jé kí n gbó Bí igún tíí gbó Obibi mà bi mi lu Ákála Jé kí n dágbá Gègè bí Ákála Àgbáágbá wón kíì ró gbáá Bì ilèkún áásé Ifá wáá se mí ní Babáláwo Nitorí bí babáíáwo bá di Babáláwo tán Wón s ni baárù niwájú ilé Ifá wáá se mí ní Babáláwo Nitorí bí babáíáwo bá di Babáláwo tán Wón à lèsin kúùrù lèyinkúnlé Ifá wáá se mi ní Babáláwo Bi Bábáláwo bá di Bábáláwo tán Wón à Iètalélégbèje aya werewere nílé Ifá wáá se mi ní Bábáláwo Bi Bábáláwo bá di Bábáláwo tán Wón à Iètalélégbèje omo werewere sayè Ifá jé ki n tó bábá a wón se Àlóófohún oko Iwo ni bábá ewera Ifá je ki n to baba a won se Òdúsó nìì solojà lawujo Ikín Ifá je ki n to baba a won se Àlóófohún oko Iwo ni baba ewera Ifá je ki n to baba a won se 4 Likes |
Re: .. by Lionhearted: 6:19am On Nov 02, 2015 |
kadunasouth:Mi o ri esi email ti mo fi ranse siyin. |
Re: .. by keyguy59(m): 11:35am On Nov 02, 2015 |
AFOSE ase oka ati odindi atare kan ao Jo papo ao fi sin gbenre kan si isale ete ao ma fi ahon kan Okigbe ida ogbe pada sodo eni sawa)ao wa agbon tobo sile funrare ao da lu lori ao lo efun ati osun po ao ro sinu agbon yen ao gbe sile di aro kutu ojo keji aoji po ao gbemu laiti soro si eni keni ao lo la agbon toku mole lorita laro yen otan MALU-opolo odidi kan ao fi okun di ese re ao wa ewe ina esinsin ewe airagba ewe oyin ewe sawerepepe pelu iyo ao lopo ao fi kun eyin opolo yen ao maki opolo yen pe "se ofe kuni? maiku, ori unfo e? Edo unrin e?, aragbigbona ni? Tio ba ti wa ku ao wa tu okun ese re ao jopo mon ijakariwo ati odidi atare kan ao fi se igbadi tabi tira ti won ba luwa mon ao sowipe "OJO TI OPOLO BATI KUN OSUN SAWEREPEPE OJO NA NI RORUN Amudo: imi ewure oriso,imi aguntan oriso,ewe rekureku. Eso agunmona ao gunpo aofi awo ojiji di mo ara aba irin ni owo mejeji aofi owu dudu ati funfun wepo o4 ibiti ewure abaso ewure si ni susi. Ibiti abaso aguntan si ni susi .rekureku kifo koja oju ona.agunmona kiraye gun igi re jake ao daruko obirin nasi ao kan mo ara igi abo odaju gan o ASEJE OWO NLA TODAJU- ewe tanapowo 50, iyere lopolopo, ao fi se akuku adie je, lepo niyo, ao ge ori ati ese adie naa ao ri mole ao se aseje naa, ao ri owo lopolopo OWO-ao te ifa ejiogbe sile ao pe ofo yi si lori-Oludari aye loruko ti anpe ifa,ina kaan loruko ti anpe etu,ojo ti obinrin bati di aya oba ojo naa ni won fi owo tire wo,ki tomode tagba ma fi owo wo emi lagbaja omo lagbaja loni,ao koju seyin fi ese osi ta yepe naa.(A le ra nkan ni owo eniyan ki won ma gba owo,eri daju pe efun won ni owo won)use it for your own protection AGBELEPOTA: Ori ako alangba1, ao fi osun pa, ao ko atare9 si lenu,ao jopo ao fi sin gbere mesan si arin ori. OGUN EYONU AIYE: Odidi ladaripon1, Ewe ewuro oojo, odidi atare1. aojopo, ao da sinu epo pupa ao ma la. TI AKIFI RANTI SA OGUN SENIYAN. Ewe igbagbe eyo atare 7 fun obinrin 9 fun okunrin ao lopo gbere 11 lori. ORUKA AYETA:ao ge igi atori mejo(ni dogbandogba,oruka irin dudu mejo,awo{skin}o wawa,odindi atare kan,ao jopo ao ko gbogbore sinu igo kan ao fi etu die foko mu ao ki oruka kan bowo.Efi etu die si adie lenu kie ki oruka kan bo lese ki wa yibon si wo. ogun ki ole ma wole;ao ge ora ara ewure die ti aguntan die ati ti elede die sinu fitila kan,ao fi ewe ko ti won pe ni idariko tabi modesina si ao fi fitila miran de,ao we lowu dudu ati funfun a o gbeko enu ona OGUN ORUKA ANO SUBU. Bo wu ki enia ti tobi to tabi ki agbara re ju ti enikan ti a ba fi oruka yi na yio subu lese kan na. Ewe ina gbigbe ao lo pelu alahannahan ao pa bara kan ni oko [parsa] ao ko egbogi ti alo yi si ao wa ko oruka irin iye ti aba fe si ao wa osun ti won fi kun ibeji lara ao ko le oruka yi na ao de pa mo bara na ao lo ri si idi ogede wewe gba ijo meje ao lo ko oruka yi ni ijo keje ao to ju re. Lilo re:- ao fi ikan bowo fi na enia yio subu. OSOLE NLA TODAJU- odidi tagiri mejo a o ge wo si meji meji ti yo wa je 16, a o ko won sinu isasun pelu ori eiye akala, olongbo kan, iru woro ti ko ni iyo ko po die, ati ewe orijin a o jo gbogbo re a o si lo kuna daada a o ma bu ebu na die si owo osi wa a o si fi oyin gidi po a o fi lo ni eekan losu o ti di dsame date ta lo la o tun lo ni d following month, odaju baba mi kan lo fun mi. OTIDE OOOOOO, AMUDO AMUDO AMUDO, tested and OKAY AMUDO... Ewe ogbo meta, ewe apada meta, odidi oga kan, omi toromini, Áo jopo ao p month ose, ao ko sinu aso funfun, ao so ko si ibikan ninu ile (house) ti kogbodo kan ile, (ground). Tia abafe lo ao bu die ninu ose ye ao ho si owo, ao daruko obinrin ti a fe lo fun sinu re, ao fi we owo mejeji. OFO RE.... Ogbo loni kio gbo temi lonni, apada loni kio ma le pa oro mi da, aso alaso ni oga ngba, ekuin ekekun ni toromini nji sun, ekun mi ni ki lagbaja ma sun loni o . ODAJU Ogun Asma Ikarahun igbin ao lo dada yio kuna ao walo sugar oni koro eyo meta mon ti yio kuna dada ao mala yio gbadun pelu ogo oloun 3 Likes 1 Share |
Re: .. by keyguy59(m): 1:24pm On Nov 02, 2015 |
bawo bari awo,,,,awo asoro awo....bo gberi bari ogberi ,,,ogberi asoro ogberi......dide mode emi owa subu awo....dide mode emi o wa subu ogberi......to ri bi ado ba wo nu ado,,,ado mejeji arinu ara won......ogberi ko gbodo ri omije lo ju awo....e jo mo fe mo phone number healthfirst.....ewe a ma je ooo |
Re: .. by Ousmaf(m): 5:58pm On Nov 02, 2015 |
keyguy59:ejoo sir se odindi OLONGBO abi ori re lao lo fun osole nla yen abi bao? 3 Likes 3 Shares |
Re: .. by keyguy59(m): 7:57pm On Nov 02, 2015 |
odindin ologbo ni oooooo .....ko ba je gbigbe...ko sa ti je ologbo |
Re: .. by keyguy59(m): 8:22pm On Nov 02, 2015 |
ikun aboyun to ga ekan si mi........08133500074
|
Re: .. by Nobody: 9:43pm On Nov 02, 2015 |
keyguy59: ewe ama je funyin on e jowo baba ogun wo lo le mu ki oko olomokurin to kere tobi? |
Re: .. by Nobody: 12:25am On Nov 03, 2015 |
keyguy59: Pls we do not allow phone numbers here. We do no also allow translation of Oogun to English language. Pls take note. check my signature for my e-mail and e-mail me, i'll send my phone number. Thanks |
Re: .. by keyguy59(m): 11:27am On Nov 03, 2015 |
e ma binu sir....emi ko mo wipe a ki fe number wa sori afefe ooooo........ |
Re: .. by opeey360(m): 9:22pm On Nov 03, 2015 |
Ago onile oo |
Re: .. by mondaylyno(m): 11:31pm On Nov 03, 2015 |
Mo need ogun osole |
Re: .. by Youceemeri: 11:32pm On Nov 03, 2015 |
kunleoosha: cc: healthFirst,kadunasouth,keyguy59, |
Re: .. by mondaylyno(m): 11:43pm On Nov 03, 2015 |
Aboru boye oo. mo need ogun egbo adajinaAboru boye oo. mo need ogun egbo adajinaAboru boye oo. mo need ogun egbo adajina |
Re: .. by sammyjay76(m): 1:23pm On Nov 04, 2015 |
GBOGBO ILE NI MO KI O. EJOWO OGUN IBILE HERNIA TO DAJU E BA WA FI SITA .ATI OGUN IBA TYPHOID. EWE A MA JE O. |
Re: .. by hamykaz: 1:53pm On Nov 04, 2015 |
ewe a maa he o, ejowo kinni WO n pe ni, awure owo agboojo, nitoriwipe omo ile eko giga ni mi, a si to fe wole sugbon kosi agbara fun a won obi mi lati san owo ile iwe mi, ejowo mo ni lo Ogun ti alaanu fi n was eniyan ri, ipari OSU yii ni a maa wole, owo naa si din die ni egberun lona ogorun,#100,000 |
Re: .. by KolaBELIEVE: 2:45pm On Nov 04, 2015 |
kadunasouth:ejowo se lararo lama ma lo ni abi ale? Ejowo se koni pa awon omo teyan bi lara lojowaju? 1 Like |
Re: .. by absoluteSuccess: 9:07pm On Nov 04, 2015 |
Mo ki mutumuwa o. Yoruba bo wonni eti to ba gbo alo, dandan ni ko gbo abo. Se mo so nipa alicin pride nijosi? Ah, nse ni egbogi naa ngeregejige si lojojumo. Ori ti yoo dade, inu agogo ide ni tii wa. Ogoro awon tiwon ti lo egbogi mi ni won nkan sara si agbara Olorun to da ewe ati egbo fun kowa. Arakunrin kan so pe ogun na pelu oun ti o wo ailoyun iyawo ore oun odun meta san, ekeji wipe nkan osu to se fun odun merin di atunri. Emi na dupe temi o, ati beebee lo. Bayi, oruko egbogi na ti yipada. Marada ni oruko tuntun t'onje. Abija wara ni, kiise akerekoro. Nkan eni kii di meji kinu bini, mo tun ni asiri kan fun iwulo pupo, o si je oun ti o le je ki eje po daradara ninu fanran isan ara. Ayunlo ayunbo l'owo nyenu. |
Re: .. by keyguy59(m): 11:08am On Nov 05, 2015 |
"OGUN TI OKO OKUNRIN BAKERE TI YIO FI YO JADE TI YIO SI TOBI" ao wa igbin nkan toba bonu, ao ju sinu omi fun igba die, bi iseju mewa tabi marundogun,ao yo igbin naa pada, ao fi sile, tobati yo ori jade funrare, ao fi ada be ori re lekan, ao wa gun po mose dudu, ao mafi fo gbogbo ara oko wa. oko wa yojade ti yio si gun dada. 9 Likes 1 Share |
Re: .. by Nobody: 4:55am On Nov 06, 2015 |
healthFirst:. E jowo e ba wa fi ami si ori akogun yii 1 Like |
Re: .. by Sobandemojisola: 8:32am On Nov 06, 2015 |
B |
Re: .. by keyguy59(m): 12:49pm On Nov 06, 2015 |
Ori mi jowo ma je fi owo osi ju we ile baba to bi mi lomo......ta lo so wipe yoruba o ni science....ti gbogbo eniyan mo si ogun.......ti eyinbo ba soro ni pa science ti won pe ni imo ijile......ba kan na ni yoruba pe ti re ni ogun....ti definition je.......osuka oru eru agba....ologbon lo le gbe.....ki awon baba wa laye jowun ana to le pa ewe po wipe ise bayi ni o se....oye ke mo wipe owun na ni won pe ni imo ijinle..........iba olobinkin osanyin.......iba....iba orunmila baba agbonmirekun.....iba awon agbagba to gba ni waju ati ni eyin ti ko je ki oowo...iba ile aboko ye re.....iba agbede meji orun owun aye....mo se iba gunnugun ti jebo isalu aye......mo se ba akala ti je bo i sa lu orun.......bi omo ti tun ba de ileaye agbe ekun wa yin.....iba obo ti je ki ako,o ma da ti nu re sile..... Iba araba nilu remo.......iba ni mo se ema je ko pa mi lare oooo........OGUN WARAPA BO LONA TO DAJU |
Re: .. by Youceemeri: 7:40pm On Nov 06, 2015 |
Aboru bo ye oo, e jowo o ti to osu merin ti iyawo ile me ti se unkan osu keyin lati ijo ti oyun to baje ni arare ni ko ti ri mo ejowo e sa nu mi ki ni mo le lo fun Gbogbo Aye oju o gbodo ti omo awo. Baba KADUNASOUTH ati baba HEALTHFIRST EJOWO E DA SI IBERE MI |
Re: .. by Nobody: 9:21pm On Nov 06, 2015 |
. |
Re: .. by mondaylyno(m): 9:23pm On Nov 06, 2015 |
Aboru boye oo
ejo mo need ogun egbo adajino to daju |
Re: .. by ALIUDAVID: 10:01pm On Nov 06, 2015 |
Eku dede asiko yii, baba efun wa ni (ogun atupa aye) atupa wa ko ni ku o, ati (awo tabi digi aye) ti won fin woni. mo se iba eyin agbagba ati eyin to ni ile aye. |
Re: .. by ALIUDAVID: 6:07pm On Nov 07, 2015 |
ERO MAGUN (THUNDERBOOT) Ifun aja, igba eyo atare(200), igba obi pupa(200), igba obi ifin(200). A o gun po a o sa yio gbe, a o fi ran onde tabi igbadi si idi wa.. Ogun ti obirin ba nse isekuse.. Ewe ewura, ao fi nu oko nigbati a ba ba obinrin na lo po tan, ao wa odindin eko kan, ao gbo ewe ewura yen si omi to mo ti kopo ao yo omi re, ao fi foko mu ati obinrin yen... Ti obirin yen bati ba okunrin mi lo po yi bi si okunrin yen lara. 1 Like |
(1) (2) (3) ... (27) (28) (29) (30) (31) (32) (33) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 77 |