Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,209,738 members, 8,007,041 topics. Date: Tuesday, 19 November 2024 at 02:38 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1846900 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (39) (40) (41) (42) (43) (44) (45) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by omoalade144(m): 8:57pm On Dec 13, 2015 |
Aboru boye o, baba. |
Re: .. by Snowealth: 9:53pm On Dec 13, 2015 |
E kaale Baba healthfirst ati Baba KadunaSouth, mo se ba eyin agbagba ati omo awo patapata yi o ma ju wa se o. A o si ni te oju ile mole, mo ki yin wipe eku ise takuntakun, eledua yi o ma wa pelu yin. A seye lalakan n se epo, aseye la o se o. Ase . |
Re: .. by Nobody: 11:09pm On Dec 13, 2015 |
Snowealth: E seun o. Isese A Gbe Wa O! |
Re: .. by castrol180(m): 10:30am On Dec 14, 2015 |
E se o baba, e dakun mo fi iwe ranse si yin bayi bayi lori itakun pelu apo iba ni soro yii tydot4ever@yahoo.com, e seun o, yi o ma ju yi n se o. |
Re: .. by enigstil(m): 8:08pm On Dec 14, 2015 |
Baba ki e pe, ashe. Ejowo ewe iyalode yi, se tutu ni tabi gbigbe. quote author=healthFirst post=40921823]112 AFORAN EYONU AYE Epo obo, Ewe iyalode Ewe ajeobale . Ao lo awon meteeta ni otooto , ao ko po epo obo mose, ao wipe pe eyin aiye o, ao jewo Isele ti o sele si won bi a se n po mose, mo nbeyin lowe, mo si fe ki e ba mi se. Ao tun po ewe iyalode mo ose yi, ao tun se alaye bi ti akoko yen, ao tun po ewe ajeobale moo, ao tun jewoo oun ti o sele ati ise ti a fe ki won bawa se, ao ma wa wipe; Eye kan n se mo mi nsere nsere(2x), Emi lagbaja mo ni ki ni eyin eye fi n se mo mi be, won ni nitori oro {ao so isele na}ti mo da ni, mo ni nitooto emi ni mo da oro naa, sugbon mo fe ki e ba mi foo danu. Otan. Ori ako okuta ni ao ti we. [/quote] 2 Likes 1 Share |
Re: .. by Nobody: 9:14pm On Dec 14, 2015 |
g |
Re: .. by Nobody: 9:18pm On Dec 14, 2015 |
f |
Re: .. by Nobody: 9:37pm On Dec 14, 2015 |
enigstil: Tutu ni ke lo 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 9:38pm On Dec 14, 2015 |
castrol180: Mo ti respond |
Re: .. by omoalade144(m): 10:06pm On Dec 14, 2015 |
Eku asale o baba kadunasouth ati
baba Heltfirst
ejoo,edakun,e funwa
ni ogun Atepa\Isana todaju. |
Re: .. by enigstil(m): 12:11am On Dec 15, 2015 |
Eshe modupe baba, quote author=healthFirst post=41007253] Tutu ni ke lo[/quote] |
Re: .. by Shomar: 11:58am On Dec 15, 2015 |
E fun wa ni ogun Lagunlagun todaju dada |
Re: .. by Nobody: 3:51pm On Dec 15, 2015 |
x 2 Likes 1 Share |
Re: .. by wale259(m): 4:08pm On Dec 15, 2015 |
Ifadamilola30:Ejo baba,Agbelepota yii ebu to ba ku kini a ma fi se leyin ti ati lo iwonba ti afi pa oju gbere abi opo eniyan le lo. Osole te so,se ologbo kekere ni abi nila ati wipe nibo la ma ro ogun na si fun lilo diedie. E se |
Re: .. by Nobody: 7:58pm On Dec 15, 2015 |
wale259: Agbelepota ewo? Emi o post Osole kankan o, mo de ti ba awon to n post Osole wi. E sora fun Osole o. Eni tio ba ni Ajesara Imunle Agba to gbona gbudo jina si oogun Osole. Igboran san ju ebo riru lo o. 1 Like |
Re: .. by Shomar: 9:15pm On Dec 15, 2015 |
healthFirst:Ipara abi? 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 10:48pm On Dec 15, 2015 |
Shomar:Beeni 1 Like |
Re: .. by Nobody: 10:49pm On Dec 15, 2015 |
Shomar:Beeni 1 Like |
Re: .. by Shomar: 11:44pm On Dec 15, 2015 |
healthFirst:BABA, lagunlagun nko? |
Re: .. by BABAODE: 9:15am On Dec 16, 2015 |
OGUN OWO NLA TODAJU-Bi awon era ti ma nbo ounje beni ogun yiri. Ori oka kan,ori ere kan,ori eiye osin kan,owo osi eran aluki,(........),(........),odidi eiye etu kan,awo ekun die,iye agbe mewa,iye aluko mewa,ikoride mewa,(........),(........),eiyele funfun meji,iyanrin okun ati ti osa,ileke ifa,abeere lopolopo,ose dudu lopolopo,ao ko gbogbo re si inu odo, ao si gbe owo eyo(aje)nla kan le lori, ao gun gbogbo re papo, ao ko sinu awo fun fun olomori kan. ao fi obuko kan se sara fun ose yi, Aso funfun lao mofi bora sun, ao mo we ose na lemeji lososu. EWO RE:Obinrin ko gbodo de ibiti osena bawa................Gbogbo iseyi ko ni mofi sita o,sugbon enito ba nife ati gba eyi toku ko pemi sori number mi. 08063121300 |
Re: .. by BABAODE: 9:25am On Dec 16, 2015 |
Ise yi dara gan ni,ti obinrin ti nse nkan osu o bati debe rara, kosi wahala kankan(no repercusion) sugbon ewu wafun eni to se ogun owo na ti obinrin to nse nkan bati debe. |
Re: .. by fbabs(m): 4:32pm On Dec 16, 2015 |
kadunasouth: GOD BLESS YOU for this Se a le lo dish tabi plate dipo igba (calabash) Se a le lo frying pan dipo agbada 1 Like |
Re: .. by fbabs(m): 4:34pm On Dec 16, 2015 |
kadunasouth: Kinni o nje Ori Apanri ati oko ataare . E SEUN 2 Likes |
Re: .. by ALIUDAVID: 9:45pm On Dec 16, 2015 |
OGUN IFERAN FUN ENIKENI TO DAJU. Awo ewure dudu, Irun abe, Ewe amunimuye, Odidi atare kan, Ekanna owo(10) ati ese(10), Iru ipenpeju eniyen die, Irun ori die.. Ao jo gbogbo re po ao ma fi sinu ounje tabi obe die fun eni naa, ti o ba ti je yio nife re.. Odaju Iba eyin agbagba, aye mujuba. 2 Likes |
Re: .. by Shomar: 9:47pm On Dec 16, 2015 |
fbabs: fbabs: fbabs:lizard ati one set out of three set of aligator peper. 2 Likes |
Re: .. by ALIUDAVID: 9:51pm On Dec 16, 2015 |
Ekale ni ile, ejo talo ni ogun catach ton fa aya(heart),oju ati imu didun ti aba ti sin tan... iba eyin agbagba, ao ni fi inra logba. |
Re: .. by Nobody: 1:09am On Dec 17, 2015 |
BABAODE: te ba fe fi oogun sita, ao fe Oogun Owo, ao de fe ke fi ero ibanisoro sita. ao fe awon 419 rara. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 1:14am On Dec 17, 2015 |
fbabs: ori Aponri ni Ori Alangba Adaripon. Oko Ataare ni ida kan ninu ida meji to wa ninu Ataare 3 Likes |
Re: .. by kadunasouth(m): 2:29am On Dec 17, 2015 |
fbabs:Beeni sugbon ti ibile lo daraju 3 Likes 1 Share |
Re: .. by kadunasouth(m): 2:52am On Dec 17, 2015 |
OGUN IFERAN Gbogbo nkan lalelofun Ewe omisimisi gogoro ati pelebe, gilasi tiwan nfi wo oju dada, koro sugar meta ao lo kuna dada ao teni eji ogbe ao pe ohunre si ao da sinu oyin ao mala Eleri ikan 3x Aba orisa 3x Amunidele ire 3x Arile rere yasi woni lewu ola 3x, Awon mererin niwon da ifa fun orunmila nigbati ifa nlo ba olokun sore 3x won ni olokun ma binu siyan ni 3x orunmila ni olokun koni binu si ohun, won ni ibinu omo araye nko, orunmila ni koni binu si omo araye, oni nitoripe oba ilu kibinu oba ilu, oba osin kibinu oba osin, Oba Ajalaye kibinu Oba Ajalawarun, Oba ajalawarun kibinu oba olomerenmere, Oni bi omode bawo digi arerin bi agbalagba bawo digi arerin, nitori adun duntan niti ewe omisimisi ndun kan araWon, Adun denu ni sugar ndun, omode ki fi oyin senu ki opose, Agbalagba kifi oyin senu ki opose, EJIOGBE gbe ife mi si okan............tabi gbogbo araye ki o fi ife aje sin mi 5 Likes 4 Shares |
Re: .. by Nobody: 5:59am On Dec 17, 2015 |
x 1 Like |
Re: .. by segwise(m): 7:05am On Dec 17, 2015 |
Baba healthfirst, mo ti fi iwe ranse si ori email yin ni owuro yi pelu email address segwise@gmail.com. Mon reti esi laipe. Ese pupo. 1 Like 1 Share |
(1) (2) (3) ... (39) (40) (41) (42) (43) (44) (45) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 42 |