Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,197,743 members, 7,965,799 topics. Date: Thursday, 03 October 2024 at 09:24 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1842738 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (49) (50) (51) (52) (53) (54) (55) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by Nobody: 12:14am On Jan 31, 2016 |
keyguy59: E JO WO E BA WA FI OGUN OKO OLOMOKUNRIN TO BA KERE SITA? SE PANDORO ATI ORI NA SISE NI? |
Re: .. by belatoxx: 6:17pm On Jan 31, 2016 |
ABORU BOYE: BABAHEALTHFIRST EGBAMI OO osole nla to nsoni di Olowo okan malu ao ki ori igun si iho kan, aotun fi egberun kan naira we Igbo ao kisi iho elekeji , ao wa ki atare si iho eleketa ao jo ninu ikoko tuntun ao mafi foko mu lararo, lowo bade EJOWO SE ISE YI KO NI ABURU KAN KAN 2. MO NI LO OGUN ITAJA TO JE BI IDAN AGBAYIN ADI ALE OOOO |
Re: .. by ojukoro: 8:56pm On Jan 31, 2016 |
Aseje Isora nibi ewu kewu Sofun awon alfa ki wan bae han hantu yii.41ولا تمسوها بسوء فيأخذكم عذاب قريب .e fi se Obo Malu pelu ewe rekureku iyere epo ati iyo.e ge Obo malu yen si41.walai ise ni o 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 12:14pm On Feb 01, 2016 |
Sidiq80: E kan si mi lori whatsapp tabi ke pe mi. |
Re: .. by Buzanskyz(m): 4:48pm On Feb 01, 2016 |
ewe ati egbo ama je ooo baba healthfirst efunmi ni gbere ajepo |
Re: .. by Eedrice1(m): 5:29pm On Feb 01, 2016 |
[quote author=omoaribaba1 post=35968222][color=#770077][/color]Ogun aseje owo pupo odaju Eran elede ao gesi meta ao wa igbin apinu kan ao gesi meta ewe papasan ata Ijosi epo iyo ao se laseje toba fejina ao lo owo eyo meta tikoluju ao fi te ifa ejiogbe ao si pe gbolohun yi si Ayeooo 3ce Aye awowo ni ile alara, koromilorun awowon ni ile ajero osemigukeguke awo won nile orangun ile ila, odifa fun orunmila oniti obare aye Aye atuyetuyele, ifa jara odemi emi (L L) gbede gbede gbede niro elede lorun, nijo ti elede ba pe ifa ifa adabobo, ijoti igbin bada enu dele ojona nijifa ile, emi (L L) kinjifa owo nlala lodo okunrin lodo obinrin lodo omode lodo agbalagba orunmila owo eyo ni mofiwa owo nlala wa si odore. [ @omoribaba. E Dakun, Se A O Da Owo Eyo Yen Si Inu Aseje Yen Ni Abi Ao Fee Si Inu Afefe? Ewe A Maa Je O. Ase..... Iba Eyin Agba] |
Re: .. by keyguy59(m): 3:28am On Feb 02, 2016 |
AWURE OWO KIAKIA ao wa omundun ewe ege mesan
fun okurin, meje fun obirin, aolopo ma ose iwe ekan
soso, aofi we ni aro, aose be fun ojo meta telerawon,
olohun ngbo ise ni iseyi, 1 Like 1 Share |
Re: .. by Nobody: 3:57am On Feb 02, 2016 |
E jowo baba, e funwa ni Oogun nnkan omokunrin to kere lati le so di nla. E seun o. |
Re: .. by belatoxx: 12:20pm On Feb 02, 2016 |
MO NI LO OGUN ITAJA TO JE BI IDAN AGBAYIN ADI ALE OOOO |
Re: .. by Buzanskyz(m): 12:24pm On Feb 02, 2016 |
baba ejowo bawo ni mo se le ri yin basoro nitoripe mofeko bon se da ifa |
Re: .. by Nobody: 3:34pm On Feb 02, 2016 |
Buzanskyz: E pe mi lori ero ibanisoro tabi ke lo whatsapp. |
Re: .. by Nobody: 3:38pm On Feb 02, 2016 |
keyguy59: Baba keyguy59 ejowo e funmi ni email yin....ejowo e de tun daun si awon ibere ti mo bi yin....ewo awon mention yin |
Re: .. by keyguy59(m): 4:16pm On Feb 02, 2016 |
ogun todaju:ao wa owo eyo kan,ao fi pa
esinsin kan,ao lo po mon eyo atare meta,ao fi
singbere kan si waju ori,ikan si arin ori,ikan si ipako.ti
gbogbo nigeria ba yinyin lorun koni yin,odaju 1 Like 1 Share |
Re: .. by skamo74: 6:39am On Feb 03, 2016 |
[color=#006600][/color] eku owuro gbogbo ile. ejowo oo gbogbo ile mofe AGBO ati AGUNMU fun AKO JEDIJEDI. ati fun IDI YIYO. oju oniti awon agbagba odua ati nairaland ama ju awon omode se oo... ase |
Re: .. by janle: 1:18pm On Feb 03, 2016 |
healthFirst eku ise ajinde ara yoo ma je o. Baba mofe iranlowo yin lori nkan omokunrin mi to kere. Mofe kie funmi ni ogun timo le lo si ni kia_kia. Oju koni tiyin o. |
Re: .. by Nobody: 1:51pm On Feb 03, 2016 |
x 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 1:53pm On Feb 03, 2016 |
janle: Opo eeyan ti n beere fun Oogun yi, sugbon kii se Oogun ti a le fi sita lofe. Ogun re sowon pupo, ayederu lo po sita sugbon otito re wa daada. Te ba nilo re, ke kan si mi lori e-mail tabi whatsapp |
Re: .. by Nobody: 2:06pm On Feb 03, 2016 |
x 1 Like |
Re: .. by janle: 2:11pm On Feb 03, 2016 |
Mo nfe oogun ki nkan omokunrin tobi e fi ran mi lowo. Ifa yo gbe wa o |
Re: .. by janle: 2:16pm On Feb 03, 2016 |
Bawo ni mose le ri number yin tabi email yin |
Re: .. by janle: 2:23pm On Feb 03, 2016 |
Kanbo loni mun, agbo 'sale loni ohuohu bi a ba n soro awon to ni imo nipa esin abinibi wa oga baba healthFirst adura temi si yin niyo. Eo ni feyinti sukun omo, ibanuje koni fi'le yin se'bugbe, gbogbo ohun te ba dawole ni yo ma yori si rere. Kori be ko se be. Ni agbara olodumare |
Re: .. by janle: 3:32pm On Feb 03, 2016 |
E jowo kinin won npe ni omundun ewe ege |
Re: .. by belatoxx: 4:33pm On Feb 03, 2016 |
MO NI LO OGUN ITAJA TO JE BI IDAN AGBAYIN ADI ALE OOOO Ati wi pe ewe wo ni won pe ni ewe safara ejo wo e daun si ibere mi |
Re: .. by Nobody: 11:47pm On Feb 03, 2016 |
keyguy59: IBEERE E jowo baba, se owo eyo ti ko luju ni a maa lo ni, tabi eyi to luju? Se ewe esisi ni tabi esinsin(housefly) |
Re: .. by skamo74: 6:43am On Feb 04, 2016 |
healthFirst: 1 Like |
Re: .. by skamo74: 6:47am On Feb 04, 2016 |
skamo74: Eseun pupo baba wa healthfirst. ojo yin yio di ale pelu alekun alafia ati ola nla . Olodumare yio ma ba wa dunyin ninu kale ase ! ase!! ase !!! |
Re: .. by skamo74: 6:50am On Feb 04, 2016 |
healthFirst:e jowo sir se Egbo Igi Udi ni abi Egbo igi Idi? 1 Like |
Re: .. by Nobody: 7:42am On Feb 04, 2016 |
skamo74: Iru ibeere wo ni e n beere yi? Kini won ko sibe? |
Re: .. by Nobody: 7:54am On Feb 04, 2016 |
janle: mejeeji wa ni oju iwe kini. E tun wo isale awon akosile mi fun e-mail mi |
Re: .. by Nobody: 7:55am On Feb 04, 2016 |
skamo74: A se alaye lekun rere sibe...ewo tun ni ibeere te n beere? E joo, ema gbiyanju lati ka akosile daada ke to ma beere ibeere. |
Re: .. by janle: 9:26am On Feb 04, 2016 |
[FUN ANFANI ENI TON WA AYETA TO DAJU] ewe efirin, osedudu bi oni.[100]naira pelu oju olongbo kopo die. Ao gun ewe yi mo osedudu yi, ao te oju olongbo yi si lara. Ao ma fi we. Pelu kaninkan adayeba. Osi tun sise fun ada. Ao bu die sinu oti schnapes. Sugbon oni eewo o. Aye mo juba o. |
Re: .. by janle: 9:35am On Feb 04, 2016 |
[OGUN MAJELE] iboju igbin pelu omo atare eyo mesan ao lo po ao fi singbere yipo orun wa. Pelu ogo olohun bi won ba fun wa ni majele je. Ao po. Aye mo juba. [OGUN MAJELE] iboju igbin pelu omo atare eyo mesan ao lo po ao fi singbere yipo orun wa. Pelu ogo olohun bi won ba fun wa ni majele je. Ao po. Aye mo juba. [OGUN MAJELE] iboju igbin pelu omo atare eyo mesan ao lo po ao fi singbere yipo orun wa. Pelu ogo olohun bi won ba fun wa ni majele je. Ao po. Aye mo juba. 1 Like 1 Share |
(1) (2) (3) ... (49) (50) (51) (52) (53) (54) (55) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 30 |