Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,227,772 members, 8,071,619 topics. Date: Thursday, 06 February 2025 at 07:41 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1854078 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (66) (67) (68) (69) (70) (71) (72) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by skamo74: 9:03pm On Mar 22, 2016 |
Thanks Baba. this is what we want sir. May you live long sir. thanks for the Understanding sir stay blessed sir Ifankaleluya: |
Re: .. by Ifankaleluya: 9:46pm On Mar 22, 2016 |
wale259:kosi iye sugar ti a ko le lo mo. 2 Likes |
Re: .. by Ifankaleluya: 9:51pm On Mar 22, 2016 |
Ifa ni; Eke(do mi) a pa eleke Odale(do do do) a pa odale Oun ti a ba se nisale(mi do do) ile Oju olodumare nii to Dia fun Amokun-se-ika(do do) To ni oba aye ko ri oun Bi oba aye ko ri o n ko Oju Olodumare nwo oo. Aboru,Aboye. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:15pm On Mar 22, 2016 |
IMULE AWON AJE Odidi Ologinni dudu minrintin kan ti ko ni ami. Eiye ega kan Abo adie dudu kan Ewe-ajeobale pupo Egbo-Aje-obale Aso-waji ko ni ataare kan-kan ao la adie yen ninu,ao ki ologinni yen bo inu re,olonginni yen na ma wa ni lila(mi do) ninu,ao wa ki eiye-ega yen sinu re, ao wa ko ewe ati egbo aje-obale yen le lori,ao wa fi aso-iwaji yen di papo. Ao gba sinu agbada, ti a ba ti jo tan ti a si lo,ao wa te ni ifa Osa-meji. Ifa re: Mo siju wo apa mi otun mo ri igba eleye,won fori gun rawon igege igege. Mo siju wo apa mi osi mo ri igba eleye,won fori gun rawon igege igege(re do do),dia fun orunmila nijo ti nbe larin eleye,ti won ni awon da ise baba ru,awon o ba ise orunmila je,orunmila ni iro ni won n pa,ati ile atona ni a fi jin olonginni,e ma fi gbogbo oun ti mo ba se jin mi,eiye keye kii fo ko ba sori ajeobale,bi alaso waji ba koja loru oro re a si ru eleye ki eleye loju. Ki oro emi lagbaja omo lagbaja ko ma ru eleyekelye loju. Ao ma fi fo eko-tutu mu lalaale. Aboru,Aboye,Abo-sise! 3 Likes |
Re: .. by wale259(m): 8:52am On Mar 23, 2016 |
Sir,igba kigba lale we Ose yi abi bawo? Ifankaleluya: 1 Like |
Re: .. by wale259(m): 8:58am On Mar 23, 2016 |
Se a ma ko ewe ati egbo ajeobale yen le Ega yen lori ninu Ologinni abi a pa ologinni de a si ko ewe ati egbo yen le ni?aso waji yi,se a ma ri lodo anwon elewe omo ati wipe ki ni minrinti Ifankaleluya: 1 Like 1 Share |
Re: .. by Lero70: 1:53pm On Mar 23, 2016 |
Ifankaleluya:edakun baba se eeso laara pupa ni tabi funfun. Eseepupo. 1 Like |
Re: .. by dominicson: 1:56pm On Mar 23, 2016 |
Yes, for those who have called to ask which one(Imule) I think is best for them or a specific situation. Divination reveals this best. Because what Mr. X uses and later thanks his Babalawo (who in turn would thank Ifa, and Ifa, Eledumare) Mr. Y may not see/feel its impact/potency, or it may not work as effective as it did for Mr. X. However, for those that are predominantly water or more of water(water element/those born under water signs or stars), water plants and animals are the best for them. Crab. Fish. Frog. Toad. Isawuru. Crocodile. Oju-oro. Osibata. Ireke. Ogede. Etc. If these are used to make Imule or Awure or sacrifice or anything for them, it will work very well. While the 'air' people should try birds: vulture, bat, eagle, dove, mistletoe, etc. I'm not saying your Ori/Ipin/Head may not request things outside these boundaries if the oracle is consulted, but efficacy/effectiveness of charms prepared with materials(plants and animals) that are naturally compatible with your star/element is guaranteed, consulting or not. But for those that combine two elements(cusp), say water and air, duck will be very good for you. I'm actually not 'speaking' with neophytes here! 3 Likes 1 Share |
Re: .. by dominicson: 1:59pm On Mar 23, 2016 |
Yes, for those who have called to ask which one(Imule) I think is best for them or a specific situation. Divination reveals this best. Because what Mr. X uses and later thanks his Babalawo (who in turn would thank Ifa, and Ifa, Eledumare) Mr. Y may not see/feel its impact/potency, or it may not work as effective as it did for Mr. X. However, for those that are predominantly water or more of water(water element/those born under water signs or stars), water plants and animals are the best for them. Crab. Fish. Frog. Toad. Isawuru. Crocodile. Oju-oro. Osibata. Ireke. Ogede. Etc. If these are used to make Imule or Awure or sacrifice or anything for them, it will work very well. While the 'air' people should try birds: vulture, bat, eagle, dove, mistletoe, etc. I'm not saying your Ori/Ipin/Head may not request things outside these boundaries if the oracle is consulted, but efficacy/effectiveness of charms prepared with materials(plants and animals) that are naturally compatible with your star/element is guaranteed, consulting or not. But for those that combine two elements(cusp), say water and air, duck will be very good for you. I'm actually not 'speaking' with neophytes here! 1 Like |
Re: .. by Lero70: 2:11pm On Mar 23, 2016 |
Ifankaleluya:ejoo baba ifankaleluya, se omo ologinni dudu ni aoloni? nitori molerope yio soro pupo ki agba ologbo too le wonu abo-adiye, abi onibiaotisee ni? 1 Like |
Re: .. by Lero70: 4:36pm On Mar 23, 2016 |
dominicson: Sir can you help me to check what my own ipin/ori require? Thanks Sir. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 7:24pm On Mar 23, 2016 |
wale259: Bee ni. Ose yi ko ni alebu kan-kan...kiise wipe ao ma ko owo ninu igba(re mi) kan or whateva. O kan jewipe olohun a ma bo asiri wa ni akoko ti a ba n lo ni. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 7:27pm On Mar 23, 2016 |
Lero70: Olonginni yen o nilo lati tobi pupo. Sugbon abo adire yen gbodo je eyi to ti pa omo ri oo. O gbodo dudu tan daada....ni yio fi je ise ti a fe ko je. |
Re: .. by Ifankaleluya: 7:28pm On Mar 23, 2016 |
Lero70: E seun fun ibere yen, eso-laara pupa lo dara ju, sugbon mejeji ni baba-awo mi ma nlo. |
Re: .. by Ifankaleluya: 7:31pm On Mar 23, 2016 |
wale259: minrintin yen tumo si wipe ti ko ni abawon kankan(ko dudu dale), aso-waji yen, aso-dudu ni ooo,awon elewe-omo ma n ta daadaa. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 7:32pm On Mar 23, 2016 |
skamo74: thank you too 4 d gesture. GOD bless u real gud! |
Re: .. by Ifankaleluya: 7:50pm On Mar 23, 2016 |
Aje(re mi) bori ogbon(re mi) Otosi(do do do) so ofo oro A bu ni lole(mi re) o mo oun ti n se ni A kunle(mi do) a yan ipin A dele aye tan oju n kan gbogbo wa Ipin o se pada lo yanmiran Aya fi bi a ba tun aye wa. Ewe le(re) ole(mi re) le alele wure Dia fun orunmila baba o ma se owo(do do) imele Imele(do mi mi) ni mo se ti mo fi lowo(mi mi),laya,bimo,nire gbogbo Ero(do do) ya, e wa wo ise imele n se. Eledumare yio je aye onikaluku ko rorun(re do) ooo. Ase! Aboru,Aboye,Abo-sise! 2 Likes |
Re: .. by Ifankaleluya: 7:53pm On Mar 23, 2016 |
IFA ISEGUN OTA KAN NI Eso-agunmona eyo kan ni ao lo re wa, ao lo po mo omo-atare-meta. Ao fi sin gbere kan si aarin ori wa,ao wa fi omi-omu pa oju re. 3 Likes |
Re: .. by Ifankaleluya: 7:56pm On Mar 23, 2016 |
@wildLife
pls i need ur e-mail or line. |
Re: .. by omoemi007: 8:11pm On Mar 23, 2016 |
Kini iwulo ewe akoko |
Re: .. by Nobody: 8:16pm On Mar 23, 2016 |
Ifankaleluya:K.imma reply u soon sir! |
Re: .. by wale259(m): 8:27am On Mar 24, 2016 |
Ase!Ase!! Ifankaleluya: |
Re: .. by wale259(m): 8:38am On Mar 24, 2016 |
Imele ni mo se ti mo fi lowo,Imele ni mo se ti mo laya,Imele ni mo se ti mo fi bimo,Imele ni mo se ti mo fi kole,imele ni mo se ti mo nire gbogbo... Ero(do do) ya, e wa wo ise imele n se,Ero ya! Ifankaleluya: |
Re: .. by quasimishaq7(m): 12:22pm On Mar 24, 2016 |
isegun ota ao lo ge igi igo eyiti oba ga towa ao haha eggun arare pata ao fi eyo atare mesan gun ao fi sin gbere yi ka ese wa mejeji |
Re: .. by quasimishaq7(m): 12:25pm On Mar 24, 2016 |
mowa bi lati wa tan yin bi se pe mo fe ki ase ara wa ni a fani alf ni emi mo ki se babalawo |
Re: .. by quasimishaq7(m): 12:37pm On Mar 24, 2016 |
kerukeru adodun a o lara adie agbebo eyo kan ao fi yerepe ologo ao fi bo ni di ao ni je ki owo letan to batobi ogban iseju aowa du ao wa fi blend yo poma idire ao jo pelu odidi atare kan ao fi singbere kokan si eti obo mejeji to se o k gbere kan lori oko 2 Likes |
Re: .. by Sidiq80: 3:14pm On Mar 24, 2016 |
Baba ifakaleluya eku ise o,number mi ni yi o (08076503605)mo nilo ogun yi .ese o |
Re: .. by wale259(m): 3:18pm On Mar 24, 2016 |
Ako aaya ni baba... Ifankaleluya: |
Re: .. by wale259(m): 3:39pm On Mar 24, 2016 |
E bami be Ifa ko pa egun to le wa laye mi. Ifankaleluya: 1 Like |
Re: .. by wale259(m): 5:48pm On Mar 24, 2016 |
obara-egun tan,ifa ba emi Wale pa gbogbo egun aye mi. wale259: |
Re: .. by Ifankaleluya: 7:19pm On Mar 24, 2016 |
IFA NLA TI ENIYAN FI MA N SE ORIRE ATI INTERVIEW ONIBEJI 1. IYE-AGBE EYOKAN IYE-ALUKO EYOKAN IYE-OKIN EYOKAN IYE-EYELE MERINDINLOGUN ILEKE-ITUN MERINDINLOGUN ILEKE-IFA(do do) MERINDINLOGUN ABERE MERINDINLOGUN EWE-IRE FITILA OLOJU-MERINDINLOGUN ORI(do mi) EPO-PUPA ADI HNMMMMMM!....IFA ELERI IPIN ATUN ORI E NI TI O SUN-WON SE, MO MORI-BALE. ABORU, ABOYE, ABO-SISE GBOGBO BABALAWO. EWE-IRE YI NI AO KOKO GUN DAADAA, AO GUN AWON IYE YEN MO, AO KOKO LO AWON ILEKE YEN LORI OLO(re re) KI O MA BA TA DANU, AO WA DA SI INU ODO YEN, AO GUN GBOGBO RE PAPO, AO WA GUN OSE PAPO MO. AO GBE EPO-PUPA, ORI, ATI ADI YEN SINU OORUN LOKOOKAN. TI WON BA TI YO DAADAA, AO DA WON SINU FITILA YEN TI YIO PO DIE, AO WA GBE OSE TI A TI PARI YEN SINU FITILA YEN, AO TI SE OWU-FITILA SI GBOGBO OJU TO WA NIBI FITILA YEN. NITORI TO O BA TI KU ISEJU-MARUN TI A FE WE OSE YEN NI AO TI TAN INA SI GBOGBO OJU FITILA YEN KI A TO BU OSE YEN, INA YEN YIO SI WA NI TITAN TI AO FI WE TAN KI A TO PA. GBOLOHUN RE NIYI TI AO MA PE TI A BA TI FE BU OSE YEN EWE IRE O NI ORUKO MEJI, IRE NI IRE N JE, ITUN LO NI KI TOMODE-TAGBA MA FI IRE OWO WON TUN MI SE, IFA LO NI KI TEWE-TAGBA MA IRE OWO WON FA MI MORA, ABERE LO NI KI TERU-TOMO MA FI IRE GBOGBO BERE MI, BI EIYE BA PE IGBA NINU IGBO WON A SI FI IRE GBOGBO JIN OKIN, KI TERU-TOMO, TEWE-TAGBA MA FI IRE GBOGBO JIN EMI LAGBAJA OMO LAGBAJA,BI AGBE TI N GBERE PADE OLOKUN TI AYE FI N YE, KI TOMODE-TAGBA MA GBE IRE PADE MI KI AYE O YE MI, BI ALUKO TI N GBERE PADE OLOSA, KI TEWE-TAGBA O MA GBERE PADE MI, TOTUN-TOSI NI EYELE FI KORE WOLU,ATI OTUN ATI OSI MI NI KIN N FI MA GBARE LOWO TAKO-TABO, OWO(hand) MI WA BA FITILA LONI, LATI ONI LO KI IMOLE O TAN SI ONA MI KI IRE GBOGBO MA JE TEMI LAGBAJA OMO LAGBAJA. 2. TI O BA TI KU OJO-META TI A FE LO SIBI INTERVIEW NI AO TI MA WE OSE YEN. AO WA LO WA AFOMO-RERE(mi mi), AO LO MO ATAARE EYO KAN PERE, AO FI SIN GBERE KAN SI IWAJU ORI WA. PELU OGO-OLORUN ADURA WA YIO SI GBA. ABORU,ABOYE, ABO-SISE. 1 Like
|
(1) (2) (3) ... (66) (67) (68) (69) (70) (71) (72) ... (99) (Reply)
Viewing this topic: 2 guest(s)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2025 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 68 |