Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,227,742 members, 8,071,499 topics. Date: Thursday, 06 February 2025 at 02:00 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1854053 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (76) (77) (78) (79) (80) (81) (82) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by ayokomi1010(m): 2:34am On Jun 07, 2016 |
baba ifakaleluyah,Mo fe ka soro labe aso e Jo Mo fi ifa beyi ,08135072961 |
Re: .. by wale259(m): 2:19pm On Jun 07, 2016 |
Amin Ase! E seun lopolopo....baba modupe,iru eniyan bi tiyin opo,ifa a ma je yin nigba gbogbo.Ase!!! Ifankaleluya: 1 Like |
Re: .. by Tevez83839: 7:58pm On Jun 07, 2016 |
Hello |
Re: .. by Tevez83839: 8:08pm On Jun 07, 2016 |
Edakun eranmilowo baba Ifakanlelluyah tabi healthfirst tabi kadunasouth....artist nimi pelu paintersugbon ise daagun funmi .kosise,kosowo eramilowo ,mo fe ma gba contract nlla nla .ise kekeere owo nla,ki emi naa je eyan lawujo ati olowo laarin egbe painter ati ore ilu mi.toori Oorun ni mo ma n sunkale ni shop mi .edakun e seeto awure tabi osole tutu koda kii ba se eyi ti maa rimole ni shop mi .kin sati lowo lowo ,kin jeeyan laipe edakun08162736520 |
Re: .. by Ifankaleluya: 8:35pm On Jun 07, 2016 |
Tevez83839: Ore wa, mo le ran e lowo. Sugbon kosi nkan ti a le se ti e ko ba ni owo lowo, ati wipe ifa ti a ma fi n da oja sile, ile-iwe, ile-kewu, ile-epo ati be be lo ni e le ri mo shop yin yen ti e o si yin olohun logo laipe lai jina. Ti a ba fe se ifa yen....eroja re po die Lara re ni eiye-logeesa meji, eiye kowe meji, eiye olongo meji, eku-egungun ti o n jade ni every year, esun olubongaga, iyepe oja nla to wa ni ilu nla merin, ati be be lo. E ko le da se. Awon miran na wa, ti e ba ri odidi abo elede, ewe-kunkun, egbo-opoto, ewe adurosusu ti be be lo. |
Re: .. by Tevez83839: 10:44pm On Jun 07, 2016 |
Edakun odara efunmi ni awure togbona ,todaju tojepe maa fi maa ri owo titi mafi se iyen .ki e si funmi ni number yin pelu adress yi |
Re: .. by Tevez83839: 4:00pm On Jun 08, 2016 |
Edakun eranmilowo awure togbona |
Re: .. by zoyimz: 12:51am On Jun 10, 2016 |
My I writ me Ur number |
Re: .. by zoyimz: 12:54am On Jun 10, 2016 |
Pls text Ur number via WhatsApp 07082366130 or ericifeanyi99@gmail.vom |
Re: .. by ishlan: 5:00pm On Jun 10, 2016 |
Ejowo baba, se ale lo ise yi ni bi 4:30am idaji lasiko awe yi. |
Re: .. by ishlan: 5:17pm On Jun 10, 2016 |
[quote author=kadunasouth post=40632145]Asiri Owo(Asiri bibo) Eye lekeleke odidi kan ao fi orisi owo meji, eyokan lapa otun, ikan lapa osi e.g (1000 naira and 500naira) or 200/100 Ao gbe sinu agbada ao ko opolopo ewe aje lelori ti yio bomole ao wa fi odidi atare meta si ati oko atare meta ati eyo atare meta ao jo ao ma fi miliki olope lo lararo kato soro si eniyan odaju Ise yi dara debi wipe taba lotan osukan si meji atun ma sise lo larawa, lekeleke ki rinrin idoti asiriwa yio bo, ise yi daju tobarise oti kuro ninu egbe otosi. Danwo o confirm No repercursion[/quote ejowo baba, se mole malo ise yi ni asiko awe yi ni bi 4:30am idaji? Eseun sir 4 Likes |
Re: .. by Ayokunumi24(f): 9:31am On Jun 12, 2016 |
[quote author=Ifankaleluya post=46339628] Thank you very much for the gift you sent this morning bro, GOD bless you real good. Amen! E seun modupe, owo yin o ni kan isale apo, e o ni wa owo ti Nile aye yin. Ifa ni; Ajikore, Arinkore, oji-kutukutu ko okun ola(wealth) lowo Ajikore loruko ti a pe ifa Arinkore loruko ti a pe esu-odara Oji-kutukutu ko okun ola lowo loruko ti a pe eyin iyami eleye Eyin meteta ni kin ni mo pe yin fun Mo ni nitori okun-ola ti e ko lowo ni Ki e ko fun wale259 To ba se bi ise ti wale259 ba ni E ni yio la laye Afaila ojo, bi ojo ba la ki wale259 o la ejowo baba mo nilo iranlowo yin, e jowo e funmi ni ogun eti to n tu ti kosi gboran daradara mo, e se pupo |
Re: .. by ALIUDAVID: 7:26pm On Jun 14, 2016 |
Ekale o, ejo oruko wo ni wo tun pe "ewe rere" iba agba, iba eyin to laye. |
Re: .. by kleanboy9: 12:33am On Jun 17, 2016 |
Baba healthfirst... Plz i need your address |
Re: .. by zenith329: 5:46am On Jun 18, 2016 |
[quote author=Ifankaleluya post=44438123]Aworo Itaja Era aladi Awo-eta Ao fi owo(re mi) fon ina si Ose Ao gun papo ati ose yen,ao wa pe gbolohun re si, ao ma fi we. Gbolohun re; Afi atewo fon ina kii duro, ina loni ki e fi owo(re mi) owo(hand) yin ba mi na, era loni ki e fi owo owo(re mi) yin ba mi ra, eta ni koko ta ki omo-eranko miran to ta. E jo sir, e ma binu si mi, ba w o ni ao fi owo(re mi) fon ina si? |
Re: .. by zenith329: 9:18am On Jun 18, 2016 |
Eka aro gbogbo ile, e jo, mo ni lo agadagodo todaju. Baba ifakehaleluya, dominicson, marv 006 etc e jo, e fun mi ni ise pe. |
Re: .. by dominicson: 2:24pm On Jun 18, 2016 |
zenith329: Agadagodo to daju! Or I don't get you right? Well, if that's exactly what you mean, I don't believe you would expect me or any cultured and disciplined African to post such, for whatever reason, where it will be abused. Agadagodo to daju should be able to lock, or open and close, anything. Agadagodo a ma ti enia, a ma gba ohun(voice) lenu enia, a ma ti ojo(rain), oko(car), irin-ise, a ma ya(separate), a ma di/so enia meji(to make man love a woman, and vice versa, and all), just to mention but few. Eyi ti mo le yonda fun yin, requires that a pregnant woman grind it, with a little of her urine, or of any other pregnant woman's. Its materials won't cost you less than 70K to procure though, it can do the aforementioned. It does more. Aside the financial implication however, you will need two strong men to assist you preparing it. Regards. 2 Likes |
Re: .. by Ifankaleluya: 5:06pm On Jun 18, 2016 |
IFA TI A MA FI N SI IPA BURUKU KURO LARA ENIYAN ONI IRETE-META Ao lo efun loto, osun loto ati edu loto. Ao wa te ni irete-meta loju opan-kan na Ao wa ro itan-ifa re si Ao wa po mo ose. O di wiwe lale-lale Ifa re; Aku-mo-nisepe loruko ta pe ina Agbi-mo-letu loruko tape omi Ara-mo-sindin loruko ta pe ori eni Nijo ti eyin meteta n tode orun bo wa ile-aye E ni, eniti ori re ba buru Tori re ko sunwon Ti ko ni aje Ti ko ni ire gbogbo E ni e o ma ba bi gbogbo e danu O wa to gege, ke wa bi gbogbo ibi ara lagbaja omo lagbaja danu lati oni lo Efun ni biwa osun je Osun ni biwa efun je Atefun-atosun, edu ni biwa won je E wa ba gbogbo ogun buruku ti n be lara lagbaja omo lagbaja je lati oni lo Irete-meta ni e fi ba te gbogbo olubi ara re mole lati oni lo Ela-boru, Ela-boye, Ela-bosise! 3 Likes |
Re: .. by zenith329: 9:45am On Jun 19, 2016 |
Ifankaleluya:E jo sir, e ba wa te irete meta si ta |
Re: .. by zenith329: 11:04am On Jun 19, 2016 |
E jo sir, ki lo je koro isin? |
Re: .. by Olateju77: 3:35pm On Jun 19, 2016 |
gawab: Ifankaleluya: gawab:iba olorun .iba eniyan,iba abatenije ,iba atuntenise ,iba babalawo iba afa iba pastor mose iba gbogbo ile oru mi ni olateju |
Re: .. by Olateju77: 3:50pm On Jun 19, 2016 |
iba olorun ,iba eniyan,iba abatenije,iba atuntenise,iba adahunse,iba afa ,iba pastor ,iba gbogbo agbagba ton be ni ile yi ,ifankealeluya iba yin o ,baba wa healthfirst iba yin o ,oruko mi ni olateju ejowo ofe iranlowo yin ogun ibalopo enu orun nibamija lati bi odun mefa seyin i osi somi di alaini nkoko gbogbo ogu ni moti lo ko duro afi ifaseyin nikan mofi eledumare ati ifa be gbogbo ile esanu mi kini mole lo si won ni awon agba ni |
Re: .. by Olateju77: 3:57pm On Jun 19, 2016 |
baba ifankealeluya ati baba heathfirst mofe peyin si ori ago ero temi re 08033589537 ati 08129953818 ejowo mofi edua beyin o |
Re: .. by Ifatoki16: 5:42am On Jun 21, 2016 |
Ifankaleluya:..ASE O.Aboru Boye. |
Re: .. by Olateju77: 1:26pm On Jun 21, 2016 |
ekasan o gbogo ile |
Re: .. by Ifankaleluya: 7:58pm On Jun 21, 2016 |
zenith329: Eyi ni Irete-meta ! ! ! ! ! ! !! !! !! ! ! ! Aboru, Aboye, Abosise. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:41pm On Jun 21, 2016 |
Ogun ta fi wo egbo jina Epo jebo, epo ira, egbo jasoke, ao fi omi se, ao ma fi we egbo na yo si jina kiakia 2 Likes |
Re: .. by Tevez83839: 11:04am On Jun 22, 2016 |
Hello baba Ifankaleluyah |
Re: .. by Ifankaleluya: 11:02am On Jun 25, 2016 |
Agunmu Inarun Egbo-ipeta, egbo-ifon, iru, egbo-inobiri, ide-osa, egbo-tude, alubosa elewe, ata dudu, ao gun po ao ma fi mu eko-gbigbona. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 11:07am On Jun 25, 2016 |
Awure Iha epo, Ejinrin were, Aso Eegun, Odidi atare kan Ao jo po, a o ma fi sa ori Ofo re: iha ni sariya ina, ejinrin ni sariya iti, tomode-tagba ni se aariya egun, tewe-tagba ni ko ma fi owo sariya mi. Aboru, Aboye, Abosise. 3 Likes |
Re: .. by emtar(m): 9:37am On Jun 27, 2016 |
Sir baba, i here request to give cure guide to someone that always cover with "spider-web". What to do by that person to cure it? God bless u. E seun baba |
Re: .. by Nostradamus: 9:33am On Jun 28, 2016 |
Ifankaleluya:baba edakun e fun wa ni ise yii tan,tori awon to n sise olopa ati olode(security guard).lagbara olorun ko ni sise fun eni ti o fe lo fun ise ibi. |
(1) (2) (3) ... (76) (77) (78) (79) (80) (81) (82) ... (99) (Reply)
Viewing this topic: 1 guest(s)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2025 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 42 |