Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,173,932 members, 7,890,068 topics. Date: Monday, 15 July 2024 at 08:47 AM

.. - Culture (86) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1836823 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (83) (84) (85) (86) (87) (88) (89) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by rubbyplus: 2:46pm On Oct 14, 2016
@Baba domonicson e ku ise takuntakun. Eku ise itusile omo araye.
Ejowo e fun ni. Ise imule Alapamasise, amona owo ma re...
E jowo e fi ranse si email mi: rubbyplus@gmail.com.
Phone no:08034290951 for whatsapp. Pls add me
Re: .. by rubbyplus: 4:35pm On Oct 14, 2016
Ifankaleluya:
FUN ENITI KO BA SE ASEYORI LORI GBOGBO IDAWOLE RE TABI TI AWON AGBALAGBA KO JE KO RI ONA ABAYO.

IFA NI AWA NI TI A LE FUN YIN,KO KIN NSE OGUN LASAN.

IFA YI JE AKO ATI ABO.

Baba ifankaleluya -aboru boye.
Eddakun e sanu mi; email mi niyi: rubbyplus@gmail.com

1 Like 1 Share

Re: .. by Omoakin247: 12:08am On Oct 15, 2016
Hun, mose iba akoda, mose iba aseda ooooooooo...........alafia fun onile ooooo, eje ki alafia je temi naa oo, ojo akoko mi re lati darapo mo yin nibi, ejo eje kin ri temi se ooooo, mose ba kin to wole eje kodun, kope, kotun dun fun mi ooo, EWE AMA JE OOOO.......
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:49am On Oct 15, 2016
EBE AWON AGBA

A o lo epo-obo, a da senu ona,a po mo ose, a wa fi iyo fon inu-isasun tuntun kekere kan,ao gbe ose yen sinu re, ao wa fi odidi igbin kan bo inu ose yen. O di wiwe leyin ojo keje ti a se ose yi.

Abori, Aboye, Abo-sise!
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:52am On Oct 15, 2016
; ;DD
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:53am On Oct 15, 2016
Mo Dan wo osise Ni kiakia ni
Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:05am On Oct 15, 2016
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ati paapa eyin Omo June 22 to July 23 ati 2/19to3/20 haa! Afiti ori won bagbe alawore kowon nitori hmm olagbara'o ajuwase'o

Asitun nfi asikoyi sofun eyin aworo sasa todarare loju wipe anfani Ti si sile bai lati join egbe awon ojogbon Ti ape oruko'e Ni MAJEMU LAILAI on wasp.
Bere lati Omo ogbon odun soke
Be sini awon ojogbon ti angba wlole Ni awon ojogbon bi AWO' ALFA' ATI WOLI
Kajolasepe'o
AJUWASE'O
Re: .. by rubbyplus: 5:22am On Oct 16, 2016
Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:05am

E seun pupo fun alaye yin. E dakun, nibo laa fi ojo ibi naa ranse si,
email ati phone no mi ni yi:rubbypls@gmail.com; 08034290951. Add me to Whatsapp
A ma juse fun yin
Re: .. by Lero70: 1:55pm On Oct 17, 2016
dominicson:

O seun gan. Adura re yoo gba. Oju ko ni tie. Omo araye ko ni binu re. O o ni te oju ile mo'le. O o ni si oko ja je. Porogodo aye ko ni lu fun o jo. O wi're! Agbekale oro re fi han pe omoluhabi ni o. Oo ni je ibaje nigba kookan.

Ba mi fi omi lo kekere yi:

House arrest

Iha, damonito, koleorogba, ose dudu, a o gun papo, ita gbangba nibiti elomiran ko le ti we ni a ti ma n we. Ko si igba ti a ko le we.

Psalm:
Damonito kan kii fi ito tie dola, warawara ni koleorogba n s'oje, gbogbo eniti ba n p'ori mi nibi, oso ni, aje ni, emere ni, kenimani, babalawo, pastor, ala-laafa,abbl, Iha lo ba mi ha won mole ki won ma le jade mo. Ki won ma a gbe yara pe omo alakara.

Baba mi agbalagba, eseun pupo mo mooloore, Eledumare koniije kee wale (come down) laelae, iwaju iwaju leemaalo, omoaraye onii fowo ibaje kan okankan ninu awon eeso yin, ibanuje kere otobi koniikanyin. Esee modupe gan ni,
edakun Baba moni ibeere bii meji nipa ise tiefunmi yen ni,
ekinni, se aha taafi nmemu tabi foko-tutu ni tabi iha taafi ndana?
Ekeji, se ewe ni damonito ni tabi egbo atipe oruko miran wo lotun nje?
Eseepupo unomaa retiresi lati odo yin. Eseepupo yio maa juse o. Ase.
Re: .. by dominicson: 9:12pm On Oct 17, 2016
Lero70:

Iha(re mi) ti a fi n da'na(da ina).

Ewe ni Damonito(mi re mi mi). Damonito naa ni sawerepepe.

1 Like

Re: .. by Lero70: 10:38am On Oct 18, 2016
dominicson:

Iha(re mi) ti a fi n da'na(da ina).

Ewe ni Damonito(mi re mi mi). Damonito naa ni sawerepepe.
Esee modupe Agba koniitan lorile, Yio maa juse funyin lagbara Edumare.

1 Like

Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:35pm On Oct 20, 2016
Edakun'O
Mio wole lasan'o
Ni iwole mi Nimo se iba:-Mo se iba Akoda, mo se iba Aseda, iba iwariwa mefa toda imole sile, onile apa'otun iba, onile apa'osi mo se iba, eje'ojuwa se'o.
Mio safoju dio
Aku'ijometa'o!
Se alafia nio
Gbogbo Omo egbe tiise fans ikan Ni Yi patapata Ni moki'o
Koda motun se iba eyin Ti etun gbon jumo lo'o!
Nipaa ba'i
Ki enikeni Ki obeere nkan asiri tabi oogun teebafe!
Ajuwase'o
Konibaje!
Kaduna south is the best!!
Re: .. by Thunder04(m): 6:04pm On Oct 21, 2016
ejo baba eso lilo ogun alantakun yii baba, ewe amaaje oo. Philipjoseph01@gmail.com
Re: .. by Lero70: 4:59am On Oct 22, 2016
Lero70:

Esee modupe Agba koniitan lorile, Yio maa juse funyin lagbara Edumare.

Ekuise o, Eledumare yio maatiyinleyin, eosiniisaseti lagbara Ogaogo.
Edakun efunmi ni email ati phone number yin, nitori eyin agba naa lesope gbogbo aso ko ni a nsa loorun. Eseepupo. Email temi niyi tailadoriginal@gmail.com
Re: .. by Lero70: 5:04am On Oct 22, 2016
dominicson:

Iha(re mi) ti a fi n da'na(da ina).

Ewe ni Damonito(mi re mi mi). Damonito naa ni sawerepepe.

Ekuise o, Eledumare yio maatiyinleyin, eosiniisaseti lagbara Ogaogo.
Edakun efunmi ni email ati phone number yin, nitori eyin agba naa lesope gbogbo aso ko ni a nsa loorun. Eseepupo. Email temi niyi tailadoriginal@gmail.com
Re: .. by 08101646045atwp(m): 12:52pm On Oct 22, 2016
Fun anfani eyin ti enbere nipa ogun ti afi nwa nkan ti ole bajilo!

Ise ti afi nwa nkan ti ole bajilo!
Ewe Ina ati ewe esisi ati ako alangba ao gun papo, ao Sa ti yio gbe.
Lilore: Ao wa eyin na sinu akufo ikoko ni dede ago mokanla, ao maafin Lai nije Ki o fin si Awa na Lara
Pelu gbogbo bai wipe gbogbo iyeju awon ti ogbe nkan baibai lo tabi iyeju awon ti ogbe nkan lagbaja Ki ara maani komaroju raaye Ile aye re mon'o!
Afi tobada pada
Ao Sa bee ni ijo kini ikeji ati ijo keta!

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o
Re: .. by 1factfinder: 7:23pm On Oct 22, 2016
E ku ise anu,olorun yi o tunbo ma fun yin se o,odua atiyin leyin.Inun mi dun gidigidi lati ri iru eka yi o.Yoruba yio ma tesiwaju,orumila yio ma fun yin se o
Re: .. by dominicson: 8:06pm On Oct 22, 2016
Lero70:

Ekuise o, Eledumare yio maatiyinleyin, eosiniisaseti lagbara Ogaogo.
Edakun efunmi ni email ati phone number yin, nitori eyin agba naa lesope gbogbo aso ko ni a nsa loorun. Eseepupo. Email temi niyi tailadoriginal@gmail.com

08145802864
Re: .. by Lero70: 8:18pm On Oct 22, 2016
dominicson:

08145802864
Modupe pupo lowooyin, aamaariiyinba aso teefi npidan konii faya lagbara Onnile.
Ejowo email yin nko? Efunmi ni ohun naa. Eseepupo.
Re: .. by dominicson: 8:54pm On Oct 22, 2016
Lero70:

Modupe pupo lowooyin, aamaariiyinba aso teefi npidan konii faya lagbara Onnile.
Ejowo email yin nko? Efunmi ni ohun naa. Eseepupo.

benige4@gmail.com
Re: .. by olamilekan2016: 9:48pm On Oct 24, 2016
Eka le Baba ejowo mo sese darapo mo egbe yi nio,edakun(please)ise oni imule iwe ejowo se mole ripe,ati pe owumi kin no number yin eseun
Re: .. by Lero70: 8:24pm On Oct 26, 2016
dominicson:

benige4@gmail.com
eseemodupe o lagbara Olorun ekoniisaseti. Esee gan.
Re: .. by olamilekan2016: 10:41pm On Oct 28, 2016
Baba domicson ejowo number mi niyi 08103080251 ejowo mofe Dara pomo esese lagba,moju eyin agba
Re: .. by olamilekan2016: 11:25pm On Oct 28, 2016
Aboruboye Baba Ifankaleluya number mi niyi 08103080251
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:51am On Oct 29, 2016
MARAN TODAJU GAN!
Omo ile3,ao ko tele agbada,ao bu sibi epo pupa meta si,sibi iyo meta,ao wa jopo,ao wa fi singbere lati arin idodo yio pade nibi idodo pada ao wa tun sin meta sisale.

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:55am On Oct 29, 2016
MARAN TODAJU GAN

Re: .. by rubbyplus: 1:11pm On Oct 29, 2016
@Baba domonicson e ku ise takuntakun. [color=#006600][/color]
Mo juba ooooo. Iba omode, iba agba!!!. Iba gbogbo eyin awowo sha sha ori ikani yi. Eku ise itusile omo araye.

Ejowo e fun ni. Ise imule Alapamasise, amona owo ma re...
E jowo email m niyii: rubbyplus@gmail.com.

A ma ju yin se oooo

Ase Edumare
Re: .. by Olaiya111: 12:37am On Oct 30, 2016
Aseje owo todaju: aowa agbon odidi kan, aora eyin agric meta loja, aogbe isasun tuntun kana, aojo omin agbon yensi, tio bati ho dada aojo eyin agric yi si ao so si eri osuka, aojeki otutu aose adua si aokoje.
Re: .. by Olaiya111: 12:39am On Oct 30, 2016
Edakun mo nidi ogun egba todaju ni kia kia
Re: .. by 08101646045atwp(m): 7:39am On Oct 30, 2016
Eleyi Kolosise fun owo'o!
Eyonu Ni aseje eleyin'o.

Nipa Ti ohungba iru'ohungba wo Ni eyin nfe
Atipaapa iru eyi Ti kibaje, bi eyin na bafi oju sun'nukun woo...
Eori wipe iru ogun bai soro latifi sori afefe!
Nitori sawo'sogberi lopoju!
Kosinitorimi'baje
Akonisasise'o
Ajuwase!
Re: .. by 08101646045atwp(m): 11:32pm On Oct 30, 2016
Osole:ododo rerinkomi pupo,oju maalu mejeji,#1000 note,padi atare kan jijo po ao maa fi peak milk loo.

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o
Re: .. by 08101646045atwp(m): 5:33am On Nov 01, 2016
ASINA OWO / KIWON LE OWO NLALA BERE WA. ileke itun, ileke ifa, abere, ewe anu, ewe ela. gigun pomo ose, aofi omi agbon po ose na pelu lofinda bittu. Aoma fiwe pelu ohun OHUN; Itun loni ki efi owo million tun mi se Ifa loni ki efi owo nlala fami mora Abere loni ki efi millions bere mi. Nibiti oka bakasi lonje oka nba Ki millions oto mi wa, kiwon wafi damilola.

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o

(1) (2) (3) ... (83) (84) (85) (86) (87) (88) (89) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 48
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.