Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,198,088 members, 7,967,043 topics. Date: Saturday, 05 October 2024 at 10:42 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1842808 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (67) (68) (69) (70) (71) (72) (73) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by bwayomide: 8:19am On Mar 25, 2016 |
eejo baba,se ao ka omo ileke itun ati ifa ye ni woro kankan ti yio fi pe merindinlogun ni tabi a o ka ni eyokan bi won se di si ara igi re titi ti yio fi pe merindinlogun,ese baba,oodua a gbe wa ooo. |
Re: .. by dytex: 9:58am On Mar 25, 2016 |
eku ise o odua agbewa o ejowo nje tiwon ba ji irawo eniyan nje eniyan le ri gba pada eseun 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:09pm On Mar 25, 2016 |
bwayomide: Ao ka Ileke-Itun yen ni eyo ko kan ni. 2 Likes |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:15pm On Mar 25, 2016 |
dytex: Baba...ti eniyan kan ba so fun yin wipe ogun kan wa ti e le se. O kan fe gba owo lowo yin lasan ni. E ke si awon babalawo to gbofa yanran-yanran ki won o ba yin so ifa kale ni, ki ifa o ba yin ba olodumare soro ki eleda yin o so bi e o ba ti rin irin-ajo aye yin . Etutu dara ju egberun-ogun lo..! 2 Likes |
Re: .. by wale259(m): 11:24pm On Mar 25, 2016 |
Sir,ki ni a ma fi Abeere yen se nibe? Ifankaleluya: 1 Like |
Re: .. by castrol180(m): 7:58am On Mar 26, 2016 |
Pls if you are just visiting this thread for the first time but you'd like to either comment or contribute in any way, kindly read the first page about the rules.you also post incomplete ogun on several occasions, just for example where you put ayeta out and u decide to type ewe..... and now u are telling others not to |
Re: .. by Ifankaleluya: 2:45pm On Mar 26, 2016 |
omoemi007: Iwulo ewe-akoko(re do re) po daadaa, koda a ma n fi se awure. Bayi ni a ti ma n lo fun awure Ao lo wa ewe-akoko yen ti yio po daadaa...ao wa fi schnapps gidi gbo ewe yen, ao wa ro pada sinu igo yen, ao wa da apo aso fun-fun fun,ao wa gbe si igun(re re) yara. Ao ma mu die-die ni ara-aro pelu adura,ti a ba ti fe bu,ao fi owo(hand) gba igo yen,ao wa wi bayi pe...''fun mi lowo kin daso fun oo, ai ti fun mi lowo ni ko ti je kin n daso fun oo''. Adura wa yio si gba pelu ogo-Olohun! Aboru, Aboye, Abo-sise. 2 Likes 1 Share |
Re: .. by kuddus: 12:13pm On Mar 27, 2016 |
ejo e fun wa ni ero eniti won na logun |
Re: .. by Aareago1: 12:53pm On Mar 27, 2016 |
Ifankaleluya: E seun fun ise yii, sugbon ibeere wa. Bawo ni ise yii se maa sise? 2. Eewo wo ni ise yi ni? 3. Ti eeyan ba lo ose yii tan, se eeyan le na owo ti a fi sori oga yen abi bawo? E seun. Ko ni tan mbe o. |
Re: .. by castrol180(m): 9:35am On Mar 28, 2016 |
omoalade144: Iwe ti won fe ta ni 15,000 naira, bawo le se fe ki gbogbo wa ni lowo? Won ko fe ki a ni iwe na, nitoripe ti won ba fe ka ni lowo ko ni won to ba yen. Egberun meedogun naira 1 Like |
Re: .. by alexdan1881: 4:59pm On Mar 28, 2016 |
kadunasouth:ESE gan Ni baba olohun ama wa pelu yin. kini OKO ATARE? 1 Like |
Re: .. by alexdan1881: 6:27pm On Mar 28, 2016 |
kadunasouth: Ese baba olohun a ma wa pelu yin. ejo kini onje ( meaning) KOLOBI? 2 Likes |
Re: .. by alexdan1881: 6:27pm On Mar 28, 2016 |
kadunasouth: Ese baba olohun a ma wa pelu yin. ejo kini onje ( meaning) KOLOBO ? |
Re: .. by wale259(m): 7:31pm On Mar 28, 2016 |
E sir,bi eniyan to ti ma n ji bi ago meta,merin lati se adua,se ko se nkankan to ba lo ko to bere adua abi o di ti ile ba mo. alexdan1881: |
Re: .. by alexdan1881: 10:29am On Mar 30, 2016 |
Mi o ro pe wahala wa fun yin. Ogbona ( Charcoal) lo fe lo. Efi okan bale 1 Like |
Re: .. by alexdan1881: 10:42am On Mar 30, 2016 |
kadunasouth:Se Ise yi ko Ni Repercussion? |
Re: .. by alexdan1881: 10:53am On Mar 30, 2016 |
kadunasouth: Se ama se igbin yi lepo lata ni 1 Like |
Re: .. by Rokeeb75: 7:50pm On Mar 30, 2016 |
Moki gbogbo awon agba agba ton fi tewe te gbo se awon omo eniyan ni anu oo, Ewe yo maje fun yin lase Edumare..... Edakun Efun mi ni Ise MAYEHUN to daju ti eniyan le lo fi ba eniyan Soro lati ori Phone ti yo si se bi a tinfe... Ejowo |
Re: .. by Ifankaleluya: 8:07pm On Mar 30, 2016 |
Ifa so ninu odu-mimo re Ogbe riku sa. Ogbe sa N o la Ogbe ko sa N o la Oriire Agbo nii s'Agbo nire kaa oko difa fun Alakoko(re mi mi mi) A bu f'osorun akoko(do mi mi) Alakoko oo, Oba lo je! Osorun re Oba lo je! Ifa bo ba semi(re mi) titi ki o gbemi dele Aje(re mi) kinrinjin(re re re),kinrinjin(do do mi) Ibi rere n l'ope n gbemi i re, Ori o ba semi titi ki o gbemi dele ire gbogbo kinrinjin, kinrinjin Ibi rere n l'ope n gbemi re. Lagbara lowo Eledumare, Ori wa yio se wa titi, yio si gbe wa dele(mi mi) Ire gbogbo. Ase! Aboru, Aboye, Abo-sise. 2 Likes |
Re: .. by Ifankaleluya: 8:17pm On Mar 30, 2016 |
IFA ERO TI A MA N SE SINU ILE TABI SHOP Ewe-ekuku, Ewe-ekuya, Ewe-imi esu Ejo-aro kan to tobi ao gbele larin ile tabi shop yen, ao fi eja-aro yen tele koto yen, ao ko ewe-imi esu le lori ao wa ko awon ewe yen toku si ao wa fi yepe ki mole(mi do), Awon agbalagba ki yio le wo ile tabi shop wa lati di wa lowo..! 3 Likes |
Re: .. by Rokeeb75: 10:02pm On Mar 30, 2016 |
[color=#990000]EJOWO MOFE MAYEHUN EYI TI A LE FI GBA NKAN NI OWO ENIYAN LATI ORI PHONE.... EJOWO MA DUPE DUPE TI EBA SE MI LORE YI.. |
Re: .. by cancioamor: 10:50pm On Mar 30, 2016 |
she nkan etoyin lefe fi gba. tio ba ti je nkan eto yin, eyi ti mofe fun yin koni sise ooo? Rokeeb75: |
Re: .. by Djbless: 12:18am On Mar 31, 2016 |
ejo baba mo send message kan si yin lori email eti dami loun |
Re: .. by Tevez83839: 6:51am On Mar 31, 2016 |
Number mi niyi baba healthfirst .pls add me to whatsapp group 08162736520 |
Re: .. by mrdayo23456: 9:25pm On Mar 31, 2016 |
Baba mobeyin efunmi ni ogun ti eniyan lefi ba oyibo soro tia funi lowo |
Re: .. by zenith329: 10:10pm On Apr 01, 2016 |
Ejo, kilo je koro isin? |
Re: .. by dominicson: 12:18am On Apr 02, 2016 |
Zenlife: Perhaps you need to pay her dowry again! But this time to Osumare. It is always found at the riverside. When it is found, the simple ritual is made there, saying: Osumare, Osumare, Osumare, lati ijo alaye ti d'aye ni iwo Osumare ti n se oko odo, ko si si enikankan ti n ba o du. Lati oni yii lo enikeni ko gbodo ba mi du (your wife's name), be it her parents, her work, her boss, her anything. Mo ti mu owo ori re(do) wa fun iwo Osumare loni o, emi nikan ni kin ma ba se loko-laya o, ife t'emi nikan ni ki o ma gbile ninu re, oro mi nikan ni ki o ma wo o l'eti." You will then take one of the moneys paid to osumare, give to your wife to buy you something with it. 2 Likes |
(1) (2) (3) ... (67) (68) (69) (70) (71) (72) (73) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 38 |