Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,227,558 members, 8,070,748 topics. Date: Wednesday, 05 February 2025 at 09:48 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Aso Oge Funke Akindele Ta Lenu Yeriyeri (830 Views)
E Kwuola Mkpa Ọ Dị Inyocha Ụgbọala Oge Ọbụla / Yeye Oge Pays Courtesy Visit To Ooni Ife - Pictures / Funke Akindele Looks Absolutely Flawless In New Photos (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Aso Oge Funke Akindele Ta Lenu Yeriyeri by OlayemiOniroyin(m): 8:15pm On Aug 31, 2015 |
Aworan Funke Akindele niyii niluu Oba nibi to ti n yo ayo ojo ibi re to ko laipe yii (August 24). Ka ma paro, Funke Akindele ta lenu! Lati irun ori re de bata to wo sese ni i sana bi ti ina elentiriki. Aso kaba to wo tun leku! Aso naa kii se tile yii, toke okun ni. Aso ti won fi goolu ati owu dudu ran pelu bata onile gogoro lese. Aso naa o de orunkun re; ilaji itan lode. Eleyii to fi anfaani sile lati ri ilaji itan ese re nita. Itan omoge naa tutu loju bi edo eran ti won ko jade lati inu omi bee lo mo lolo lailabawon bi ara omo tuntun jojolo. Yato si eyi, aso oge re tun rora si igbaaya re sile ferefe, eleyii to je wi pe ko si okunrin ti o gboju sona ibe ti ko tun ni fe tun wo leekan si. Atike oju re ko poju, iwonba naa si tun ni itote pupa enu re. Eniyan dudu ni Funke sugbon o dabi eni wi pe oju re ti n funfun. Odun 1977 ni won bi Olufunke Ayotunde Akindele si agbegbe Ikorodu to wa niluu Eko. Ojo aje to koja yii lo si pe omo odun mejidinlogoji (38). A ki Jenifa wi pe oku ori ire. Igba odun, odun kan ni http://www.facebook.com/photo.php?fbid=882443721841512&set=gm.1038794672838508&type=1
|
Re: Aso Oge Funke Akindele Ta Lenu Yeriyeri by asgat1love: 8:17pm On Aug 31, 2015 |
whats dis one saying faaa |
(1) (Reply)
Muslim Youths Fast Becoming Vampires As They Attack Yet Another Christian / See How Nigerian States Got Their Names / An Insight On Believe.
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2025 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 9 |