Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,199,804 members, 7,972,878 topics. Date: Friday, 11 October 2024 at 09:20 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Yoruba Commonwealth and Politics (696939 Views)
OPC - Faseun & Adams Unite For Security Of Yoruba Commonwealth / SEUN - Re: Yoruba-commonwealth-politics / Goodluck Jonathan Returns From Commonwealth Assignment (photo) (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (72) (73) (74) (75) (76) (77) (78) ... (384) (Reply) (Go Down)
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:25pm On Oct 28, 2015 |
Rilwayne001: Mo mo wipe oma soro fun opolopo lati so Yoruba la lai fii geesi si 2 Likes |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by tunde1200(m): 9:25pm On Oct 28, 2015 |
Omo ilu Igbaja legbe ilorin ni mii. Aareonakakanfo: |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:27pm On Oct 28, 2015 |
Aareonakakanfo: 'Erin' bawo le se ri si? |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:28pm On Oct 28, 2015 |
tunde1200: Bawo lo se sunmo ilorin to.Idi ti mo fi n bere ni wipe alaimo kan nimi ni pa oro Ilorin.mo fe mo ni pa awon Yoruba to wa n be 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by laudate: 9:29pm On Oct 28, 2015 |
Aareonakakanfo: Ehn.... the only word I recognise in this whole phrase is 'Egbon.' Now, please tell me, what is the meaning of the rest of the words you wrote up here?? Please....abeg, just kindly translate. I hope it means you are going to send me some money?? 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:30pm On Oct 28, 2015 |
Aareonakakanfo: awon eni eleni, oro do'ju e, wa yi ese pada. Alagba Shym3x nko, a ma kofiri wan? 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:30pm On Oct 28, 2015 |
laudate: Eewo le leyi oo. ema so geesi ni wakati yi.To ba to asiko, maa so itumo gbogbo nkan ti mo wi fun yin 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by SUBWAY101(m): 9:31pm On Oct 28, 2015 |
Rilwayne001: Oga mi, Mo gbo wipe omo Ilu Kwara le yin. Shey lo to o nii? |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by SUBWAY101(m): 9:32pm On Oct 28, 2015 |
Aareonakakanfo: Ara Kurin yen Ki she Omo Ile Yooba, O ko feran wa nii. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 9:32pm On Oct 28, 2015 |
Se woni omo ale omo ni kii mo itan ile baba re. Ti oridi eyi, mo pe gbogbo eyin omo kaaro ojire lati tiraka ka iwe itan yoruba yii. Mo sheshe daunlooodu re lori ero ayelukara mi ni. Iwe naa poo sugbon laipe laijina maa gbiyanju lati kaa tan.
|
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:33pm On Oct 28, 2015 |
9jacrip: Alagba shymm3x ti so fun mi wipe awon o ni so nkankan ni wakati yi ki awon eyan ma fi se yeye.egbon lobinrin ilekehd nko? aba won naa ti salo ni |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:34pm On Oct 28, 2015 |
SUBWAY101: Mo moomo pe wa sibi yii.emi naa mo wipe ki n se Yooba |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:35pm On Oct 28, 2015 |
Rilwayne001: Mo ni iwe yi sile sugbon mi o tii ka |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 9:35pm On Oct 28, 2015 |
SUBWAY101: Beeni omo iya.. Omo Ilorin ni baba to bimi lomo, omo Ède si ni Iya mi, sugbon Ibadan ni wo bimi si. Omo ilu pupo lemi see, sugbon mo feran Ilorin gidigan ni. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by SUBWAY101(m): 9:37pm On Oct 28, 2015 |
Aareonakakanfo: O da be nigba yen. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:38pm On Oct 28, 2015 |
Ogbeni nisai.mo ri yin te n wo tiredi yi.Oya ewa so ede abinibi yin oo |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by tunde1200(m): 9:38pm On Oct 28, 2015 |
kojina sii Ilorin pupo bii maili ogoji lomafii jina. Aareonakakanfo: |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by PrincessJaneDoe: 9:40pm On Oct 28, 2015 |
Aare, Yoruba mi ku die ka to, amon mon gbiyanju. Mi o gbo ede mi o Yoruba Eko nikan ni mo le so. Kini oruko awon mods section yi? (eforiji Yoruba-English mi ) alcatraz001, alcatraz002 |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 9:41pm On Oct 28, 2015 |
Aareonakakanfo: Beeni omo iya, ko rorun. sheri ti gbogbo won kan lugbe |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Musiwa419: 9:42pm On Oct 28, 2015 |
Kilo'n sele ni ibi bayi ni ale yi o |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:43pm On Oct 28, 2015 |
Rilwayne001: Emi naa ti mo wipe gbogbo wan ma sa lo.O dami loju wi pe awon kan wa ni awon tiredi biafra yen ton ro ejo lowo lede geesi 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:43pm On Oct 28, 2015 |
Aareonakakanfo: Alagba Shymm3x le ma ko ede na die die, ko je ko soro lo titi nitoripe eje yoruba wa lara wan. Egbon Ilekehd le so Yoruba, ati jo so yoruba die ni ana. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by totit: 9:44pm On Oct 28, 2015 |
Aareonakakanfo: Eru ti wa je? Bii temi ko o. Ra ra o Moo kunle repetè, kooada pupoo gan Omo egba la wa se oo Baá wa oo |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by SUBWAY101(m): 9:44pm On Oct 28, 2015 |
Rilwayne001: O da bee. Emi no nii awon ore to je omo Omupo, won de ma nfi ye mi pe, omo odua tokan tokan la won. Odua agbe wa ooo. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:45pm On Oct 28, 2015 |
PrincessJaneDoe: Yooba eleyi ti e so ni bi yii koo ku die ka to o.Yooba gidi ni ele yi ti e so yii oo.O ka mi lara wipe mii pero ogbeni alcatraz001. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 9:47pm On Oct 28, 2015 |
Aareonakakanfo: Tiredi awon omo olori pelebe (biafra) ma ndun bii kaasi nkan. Erin le mi ma nfi won rin. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:48pm On Oct 28, 2015 |
9jacrip: Boya ka fun alagba shymm3x la ye lati so Yooba pelu geesi papo. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by laudate: 9:50pm On Oct 28, 2015 |
Uh...this is so unfair! Am going to report all of you to my maternal grandmother's sister! |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:50pm On Oct 28, 2015 |
totit: E kaa bo oo Rilwayne001: Kilode ti awon yooba se wa feran tiredi awon olori pelebe ba yii.mii ti e ka won kun.alawada lawon olori pelebe yen 1 Like |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by superstar1(m): 9:50pm On Oct 28, 2015 |
ibo ni IlekeHD wa ni ale yii. a ko si eri ina ikoni nijanu/bureki re ni ale yii. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 9:51pm On Oct 28, 2015 |
Aareonakakanfo: Ilorin o se bee yato si Ogbomoso rara. Kini awon nkan ti efe mo nipa Ilu Ilorin ? |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 9:51pm On Oct 28, 2015 |
SUBWAY101: Asee oo |
(1) (2) (3) ... (72) (73) (74) (75) (76) (77) (78) ... (384) (Reply)
Kenyans Are Far Behind Nigerians In Every Aspect – Fani-Kayode / Anambra light of the nation, eastern economy power house. / Enugu, The Pride Of The East.
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 36 |