Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,227,626 members, 8,071,028 topics. Date: Wednesday, 05 February 2025 at 01:57 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju (569451 Views)
Civil Servant Killed By Thunder In Oro, Kwara (Photos) / Ogun Ibile To Daju / The Bad Shape Of Oro General Hospital, Kwara State (Exclusive Photos) (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (17) (18) (19) (20) (21) (22) (23) ... (27) (Reply) (Go Down)
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 1:56pm On Feb 15, 2017 |
IFERAN: afara oyin, iyo, ao lo papo ao po mo ose dudu ao mafi we IPARA IFERAN: omo nile 1 ayee, atare odidi 1,ao jopo ao da sinu ipara ao mafi para. IFERAN:- Ewe orijin, epo eyin Ti adie paku AO lo papo AO fi ori po, ao maa fisi oti idodo wa N.b:- enu Ni Edie fi ntun eyin re se Lori aba Ki gbogbo eniyan'omaafi enu Tunmise loni IBA fun gbogbo atoni sona'o Eyi Ti abatunse Loni kie monfi biwa'o Omo elomii Ni kie fibi'o Nitori use konko lake odo Omo eja Ni won fi nbi. /+\ |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 1:57pm On Feb 15, 2017 |
IFERAN: afara oyin, iyo, ao lo papo ao po mo ose dudu ao mafi we IPARA IFERAN: omo nile 1 ayee, atare odidi 1,ao jopo ao da sinu ipara ao mafi para. IFERAN:- Ewe orijin, epo eyin Ti adie paku AO lo papo AO fi ori po, ao maa fisi oti idodo wa N.b:- enu Ni Edie fi ntun eyin re se Lori aba Ki gbogbo eniyan'omaafi enu Tunmise loni IBA fun gbogbo atoni sona'o Eyi Ti abatunse Loni kie monfi biwa'o Omo elomii Ni kie fibi'o Nitori use konko lake odo Omo eja Ni won fi nbi. /+\ Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP! ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045 OR https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above! Jowo mafi number re si abe comment'o Whala'oni payin'o Add links yen si odo'e Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere. Ajuwase o |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 2:09pm On Feb 15, 2017 |
OSOLE GBEWA PAJAWIRI Omo yahoo na lelo daada kosi ewu Ori kanakana 3, alangba 3 atare aja 3, pelu pelu biscuit okin ati opolopo ewe ola ao jo papo ao ma fi omi alujannu lo ebu na......... N.B:- owo Ni afi ma nlo ebu na'o Iru owo ewo Ni ao maafi lo? =**** Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP! ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045 OR https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above! Jowo mafi number re si abe comment'o Whala'oni payin'o Add links yen si odo'e Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere. Ajuwase o |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ignitereaders: 3:21pm On Feb 15, 2017 |
These were people that exposed other to the disease the most. Their activities caused more death than imagined. http://blog.ebolaalert.org/superspreaders-were-the-drivers-during-the-last-ebola-outbreak/ |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by adeolabilkis002: 10:32pm On Feb 15, 2017 |
E kale sir,e jowo kinni mo le se ki awon egbon mi merin nkan ki won le pe mi pe kinni ki awon se Funmi.Nitori won si nitosi beeni won ki gbe call Mi. Ki ni maa se ti oko mi afi pada wa si ile nitori iya yi poju funmi pelu omo meta |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:37pm On Feb 24, 2017 |
Ekule eyin eyan mi eyin ololufe etoye mo kiyin pe oto ojo meta, mose irin ajo ranpe nio modupe lowo gbogbo eyin ti epe lati bere alafia mi ati awan to send message ati chat lori watsup adura gbogbowa yio gba lase odumare laipe eto yio bere pelu awan ogun ibile ati iwosan fun arun gbogbo, ati ona ta nfi bo ninu ide aye raye, Mose iba eyin toloun ko ayele lowo emaje kin sise o efi ojure womi Ase ntodumare 3 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ademasta(m): 7:39pm On Feb 24, 2017 |
kadunasouth:Baba o |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by CivilianJTF(m): 7:41pm On Feb 24, 2017 |
Baba e kaabo o... E da'kun e gbami... Iyawo mi n binu o... Mi o le se ju iseju meji lo lori obinrin... E joor e gbami baba kadunasouth |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by EasyMind(m): 8:37am On Feb 25, 2017 |
kadunasouth: Baba e kaabo o, e de ku ojo meta... Aa ma ju yin se o |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by eeby1983(m): 11:26am On Feb 25, 2017 |
kadunasouth:Aboruboye oo baba, eku ojometa ogbon ati imon ti olorun funyin Koni pare orunmila a gbeyin oo |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:53pm On Feb 25, 2017 |
CivilianJTF: Elora ogede agba dudu meta kie bo epore danu kie ge si 201 kie sa si orun ko gbe dada kie loma atale ati kanhun bilala die ko kuna dada kie ma fi mu ogi gbigbona iyawo yin yio gba pe okunrin lako okunrin lada eni togbamu gan okunrin ni 5 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:00pm On Feb 25, 2017 |
Ogun aleko ati moko tobi Pandoro tutu ào ge kekeke ao ko sinu koko ao da eru alamo ati eru awanka le lori odidi atare to gbo dada kan si ao bu omin toma dada si ao se yio jina dada ao mamun laro ati ale die die idaji stainless cup ni odiwan mimunre tobasepe ani match tobaku awa kan aomu . Wadupe fun oloun NB gbogbo igba taba fe mu agbo yi lao ma gbe kana 9 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by flakings007(m): 6:19am On Feb 26, 2017 |
kinah:call 08134541163 |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by CivilianJTF(m): 9:39am On Feb 26, 2017 |
kadunasouth:Wow! Baba e seun o, modupe gidi. Sugbon, e joor o... Se garlic ni atale ni... Ewo photo yi na 1 Share
|
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by possible26: 11:34am On Feb 26, 2017 |
baba eku ojo meta oooo...ejor e fun wa ni ogun aseje ririse ati aseje arisiki todaju |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by IBAAGBA1: 10:28pm On Feb 26, 2017 |
kadunasouth:E jowo sir,ewe wo ni won npe ni ewe firiganmu,atipe kilo nje girija ti o lomo ninu,e se sir 3 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by IBAAGBA1: 2:05pm On Feb 28, 2017 |
kadunasouth: E jowo sir baba ewe wo ni ewe ajade,e se pupo sir a ma juyin se o |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 4:02am On Mar 01, 2017 |
CivilianJTF:Ginger ni atale o then kanun bilala niwanba lema fisi nibi odiwan garlic odidi kan kogbudo jubelo |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 4:04am On Mar 01, 2017 |
IBAAGBA1:, Owa lodo awan elewe omo ebere wan a funyin 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:44pm On Mar 07, 2017 |
ATUDE Asin odidi kan ao jo pelu odidi atare ninu isasun tuntun ao lo kuna ao fi sin gbere yipo owo wa mejeji ao fi iyoku fokomu odaju Atude ota inu iroko pelu egbo tude ao gun yio kuna dada ao dapo ma nescafe ao to die die sinu omin gbona ao fi oyin die si bi ao se ma lo niye lararo 3 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by CivilianJTF(m): 3:45pm On Mar 08, 2017 |
kadunasouth:E seun baba. Keepe funwa o! |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by possible26: 7:45pm On Mar 09, 2017 |
[quote author=kadunasouth post=54369305
IBA OMIN O!, OMIN TI INA MU TOKU
OHUN NA NI OMO ENIYAN MU TOLA,
MOBOJU WO APAMI OTUN WONJU BINNBIN
NI, MONI BOLEJU BINNI KOJU BINNI,
AJIBOWU NISE ALAGBEDE ODE ORUN,
MOBOJUWO APAMI OSI WONJU BINNI
BINNI MONI BOLEJU BINNI BINNI KOJU
BINNI AJIBOWU NISE ALAGBEDE ODE
ORUN AGBALAGBA BABALAWO KOLEBINU
KOFI OMO BIBI INURE BOFA AJIBOWU
NISE ALAGBEDE ODE ORUN AGBALAGBA
ISEGUN KOLEBINU KOFI OMO BIBI INURE
BO OSEYIN, AJIBOWU NISE ALAGBEDE
ODE ORUN AGBALAGBA ALUFA ABI EWU
GEREJE KOLEBINU KOFI OMO BIBI INURE
PA ILEYA, AJIBOWU NISE ALAGBEDE ODE
ORUN WONNI KIN MASU SEPO MOSU
SEPO WAN OBAMI WI RARA, WONI KINMA
TO SALA MOTO SALA WAN OBAMI WI
RARA, MOWAFI IKO ODIDERE NUDI OMO
OYEBE YEBE AYAMI OGBIRIGIDI MODI
IRULA ORITA AYAMI OGBIRIGIDI MODI
OMO OBANILE IFE ONI AYAMI OGBIRIGIDI
MODI IRULA ORITA AYAMI OGBIRIGIDI INU
KIBI BABALAWO KOFI AJA BO IFA INU KIBI
ADAHUNSE KOFI ELEDE TE ODU , EFUN
OMO OGERE IDE, EEDI OMO OGERE OJE,
OGANNA NI ORUKO OGERE IDE EFUN ATI
EDI WONJE ERU OBA NILE IFE, ONI NI IGBA
IWASE, ERU KISIPA OMO OHOWOREJE,
EDUMARE MAJE KI EFUN ATI ED OMO
ARAYE OMUNMIN POPO OKUN KONI ENINI
IRAWO OSA KONI GBOGBO, AKIGBE
AWORAN GEGE KAMOFI OWORE BA
IBIKAN LODIFA FUN YEWANDE TOFI
ODUNMETADINLOGUN WASE OGBURU,
OGBURU OGBARA MORE NITI APA OKUN
OMOLAYO OMO AJOMITAN WUWO OSO
GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO, AJE
GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO, IKU
GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO ARUN
GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO etc
OMIN WO YANRIN GERERE OMI OLAPA
OMIN OLESE OMIWO IYANRIN GERERE
GBOGBO ENIYAN TIN BA NDOJU OTA KOMI
KI OMI AYE BAMI GBEWON LO MOBA OMIN
MULE LONI, ENIKAN KIBANI MULE
KOTUNSE IDANI, EWO ORISA. baba e dakun bawo lase ma lo ise yi |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by YoungAbiodun1(m): 9:55am On Mar 10, 2017 |
Modupe gidi gan fun idawun yin lori ibeere mi iyen (ogun fun ara tin wu)eseun gan an ni.Uhn,ajanaku koja mori nkan firi,taa ba rerin kaso wipee arerin.Ise takun takun le n se lori ikanni yii.Mo gbaa ladura wipe ki olorun oba tun bo maa se alekun ore ati ibukun fun un yin.Ejo,eniti ara re un wu yi,won ti lo ogun lorisirisi fun un sugbon ti o jasi wipe ti enina ba ti yagbe fun iye ojo die,ti arare si ti lole toba ya arare a tun bere sini maa wu pada paapa julo ikun re lo maa un wu ju ai eni imale gbe.Inu mi adun gidi gan an ti ogun ti e fun mi yi ba je ti arare kosi wu pada mon.IBA AWON TO LAYE,IBA YIN OOO |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:45am On Mar 12, 2017 |
possible26: Elowa cup tabi igba funfun tabi awo funfun ti kosi fulawa larare ki ebu omin ti ebale mutan sinure ki e wa pe gboloun yi si kie gbemu kie se die ku kie fi sari ema se etoyi ekan larin ose ti ota bapo funwa ao lo lerawan fun ojo meje ASETA TO DAJU NI, 6 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 9:55pm On Mar 12, 2017 |
OSOLE OWO TIMU OWO NLA TI ALE FI KOLE LARIN OSU META! Sugbon nigbati Emi danwo, Mio kole'o Sugbon hmmm!!! Nkan Ti mofise komabaje'o!!! :- EWE BARA MESAN TI OOJO, AOGUN MO ERU ALAMO IYEKIYE, AOPO LOSE, AOFI EJE EIYELE funfun PO OSE NA DADA, AOKO ose na SINU IGBA OLOMORI, AOGBE PAMO FUN 16DAYS. Aoma buwe lararo, pelu ogo Eledumare owo ti ama fi kole nlala yio wa larin osu meta pere. IKILO: enikeni kogbodo ri igba yi ki ojo na tope. Osole yi Koni daun daada na. Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP! ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045 OR https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above! Jowo mafi number re si abe comment'o Whala'oni payin'o Add links yen si odo'e Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere. Ajuwase o |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by possible26: 11:37pm On Mar 12, 2017 |
modupe baba olohun o jeki e pe fun wa Amin 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Jummyphabulous: 8:15am On Mar 13, 2017 |
Ekaro sir, have when through ur post n saw that u have done great for pple. Am 27 year with 2 kids. Mo ri pe ikan osu mi polapoju, won wa ya scan funmi ni ile iwosan. Won ni moni arun iju. Sugbon okere. Pls sir i need herbs that will shrink the fibroid so that it will not develop. Thank u |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ibro2much(m): 8:06pm On Mar 15, 2017 |
08101646045atwp: ekuse baba o,ewe ati egbo yio ma je wa o ejowo ibere mi ni wipe se agogo mokanla ale tabi owuro ni ao maafin ni? |
(1) (2) (3) ... (17) (18) (19) (20) (21) (22) (23) ... (27) (Reply)
Causes Of Seeing Menstrual Period Twice A Month / Postinor 2 - How Effective Is It? / Doctor in the House: Free Medical Advice Available
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2025 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 61 |