Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,189,836 members, 7,938,450 topics. Date: Tuesday, 03 September 2024 at 06:31 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (118) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (380441 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (115) (116) (117) (118) (119) (120) (121) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 3:51pm On Sep 17, 2007
Digital:

Okan e ma doti ooooo grin grin
se oko mi lo doti ni abi okan mi?


abeg make una no steal my slipas,i dey mosalasi dey pray for una.

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Aladunni(f): 5:53pm On Sep 17, 2007
mo tile miss eyan kan ni bi o, she admin won kin wa si bi ni. or won tii ban eyan kan nibi rara ni. e maa se pelepele sha a o. thread yi o dun gan ni o. mo proud lati je omo yoruba to the core. ilorin ilu awon alfa ni ti wa, ilu to jina sina to sunmo aljana, moti pe gan nibe sugbon igbomina ni mi sha. e kun o, e nle faaaaaaaaaaaaaaa
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by penfold(m): 7:44pm On Sep 17, 2007
@iya aje

aworan ti o gbe si afefe yi hmmmmm, o ga o, emi koba beere pe nibo ni o ti ri sugbon je ki n dake nitoripe o ye emi ati iwo wipe aworan yiiiiiii, hmmmmm, o daa na, emi o sówo re si o lati ori ero ibanisoro ti mo fi ya ti n ba ti pada de ibi ti "network"wa!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 10:18pm On Sep 17, 2007
iya aje, se the moon don dey bo si ta?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 1:30am On Sep 18, 2007
grin grin grin grin

egbe ni bobo yio,onfi padlock ti slipppers shocked shocked shocked

maje kaye ba e gbo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 1:48am On Sep 18, 2007
egbe lasan lasan, o n'pe ra e ni iya aje, awon aje ma le e kuro ninu aarin won, won o like lati ma faramo egbe grin grin

awon egbe e n'wa igbale ton fi ina sise (vacuum cleaner) grin grin iwo n'fi padlock si bafroom slipas, oju o tie ti e ra ra cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Digital(f): 9:11am On Sep 18, 2007
iya aje:

se oko mi lo doti ni abi okan mi?


abeg make una no steal my slipas,i dey mosalasi dey pray for una.

Oro pa esi je, oro di huuuuuuu. iya aje oro ohun ma ga gan ni oh
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by waxyweller: 12:24pm On Sep 18, 2007
Eni bashe ahji wasiu Oye kaki ,OMO GBOLAHAN MI OO, Oya ebami kalo silu canada oo, *Singing KWAM 1*grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by obedz(m): 8:07pm On Sep 18, 2007
mo wa nibiyi o grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 8:10pm On Sep 18, 2007
minute:

grin grin grin grin

egbe ni bobo yio,onfi padlock ti slipppers shocked shocked shocked

maje kaye ba e gbo.
no blame me,i put d padlock because of people like you.
debosky:

egbe lasan lasan, o n'pe ra e ni iya aje, awon aje ma le e kuro ninu aarin won, won o like lati ma faramo egbe grin grin

awon egbe e n'wa igbale ton fi ina sise (vacuum cleaner) grin grin iwo n'fi padlock si bafroom slipas, oju o tie ti e ra ra cheesy
debosky sora e o,se o ro pe mi o mo pe o fe ji slipas mi ko ni mosalasi ni ojo jimoh to koja,now ti mo ti fi padlock si je ki wo bo se ma ji ko lo ile re
infact mo plan lati lo ko slipas mi pamo si central bank because of yougrin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ssRhino: 11:23pm On Sep 18, 2007
Digital, Yoruba teacher
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 3:32pm On Sep 19, 2007
nkan tobari kofi ti-kona mi ni kolobo ---iwo loni salubata  e!!!

bata yen naa loti je lesese yen,otun ti fi ese e ran.lol.

otun ti je labe. arinka njabataagrin grin grin


anyway, 
*singing ebeneza obey*

kininbe nigbo
tondun mohuru mohuru mohuru.  2xe.lol
bio panije kokuku panije
bio si panije komashe panije .lol

koye dun mohuru mohuru mohuru
momi mo.


inu mi dun gidi leni,morowo he!!LOL
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 10:07pm On Sep 21, 2007
ki le le yi o e ja so
ki le le yi o, e ja so

eja tutu shokoyokoto
eja tutu, shokoyokoto

ajashoro!!! whistling and hummming eja tutu shokoyoko grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 10:10pm On Sep 21, 2007
ki lo shele? o da bi pe awon won yin ni thread yi se kurukere kurukere.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 10:12pm On Sep 21, 2007
omoge je ki n'ko e daa daa bi won se n'ko orin yen

ki le leyi o, eja osan

ki le leyi o, eja osan

eja tutu, shokoyokoto

eja tutu, shokoyokoto

emi o le je oun ti o da, kin la ju mi sile kin won wa fi mi s'aponle

eleda o something something something something o, oyin momo cheesy

*emi gaan ti gbagbe ipari orin naa*
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kateflow(f): 10:12pm On Sep 21, 2007
omo dara tan like mama iya re lo fi jo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by shakira: 10:18pm On Sep 21, 2007
a star has been born
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 10:20pm On Sep 21, 2007
kateflow bee ko ni jazzman se korin yen o grin

omo dara just like mama iya e lo fi jo

walk like mummy, talk like mummy

omo dun, ati check e, iya e lo fi jo!

o baby baby you drive me crazy

ati bee bee lo grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kateflow(f): 10:22pm On Sep 21, 2007
lol jo oo emi o gbo yoruba
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 10:25pm On Sep 21, 2007
debosky, o se gan.

whistling and humming eja tutu shokoyoto, eja tutu shoko yo ko to (now ebi obe Shoko pa mi grin)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by buttyelele: 9:46am On Sep 24, 2007
waxywella or whatever u are called u are a bleeped up nigger.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by buttyelele: 10:18am On Sep 24, 2007
i studied linguistics in U.I and mother tongue was really promoted, am always impressed when our laguage is being promoted, some think the language is endangered, because it has not been passed from one generation to another, all the alo apagbe, the folklores, games we used to play in yoruba when we were younger is all gone, all the bat somi were were, the poems i.e adiye mi eyi ti mo ra, all that is gone, we are losing out big time on our heritage, ur child will never speak as good as u can, and they will pass on their substandard yoruba to the next generation until theres is no yoruba left, what can we do pls bring suggestions.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 1:42pm On Sep 24, 2007
buttyelele:

i studied linguistics in You.I and mother tongue was really promoted, am always impressed when our laguage is being promoted, some think the language is endangered, because it has not been passed from one generation to another, all the alo apagbe, the folklores, games we used to play in yoruba when we were younger is all gone, all the bat somi were were, the poems i.e adiye mi eyi ti mo ra, all that is gone, we are losing out big time on our heritage, your child will never speak as good as u can, and they will pass on their substandard yoruba to the next generation until theres is no yoruba left, what can we do please bring suggestions.

Suggestion: Bi o tile je wipe oro isiri ati onilaakaye ni o ti ko sile, iba dara ki o tumo gbogbo ohun ti o ko si oke yi si ede yoruba, bi iwo na ba bere pelu apere rere ko ti buru ju.Oyinbo tabi ede geesi ko ni aagbon okun oro yi wa fun
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 7:56pm On Sep 24, 2007
Hello! grin

Se daada ni mo ba gbobo yin, bo tile je wipe o ti se die ti mo ti wa si ori okun yii, mo lero wipe en gbadun ara yin?
Nana, Ika6, Segoye2, Baale, Ikomi, etc. . . . . . se gbogbo yin ni e si wa lori okun yi?
Maa tun ma kan si yin l8r, odabo naa.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 1:06am On Sep 25, 2007
alo ooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooo,
o dun pa po po pa po po po pa po po po praaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaa,
kini o?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 5:21am On Sep 25, 2007
iya aje:

alo ooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooo,
o dun pa po po pa po po po pa po po po praaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaa,
kini o?

iso (fart) ni o, lati idi nla iya aje grin grin grin

se mo gbaa abi mio gbaa?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 6:06am On Sep 25, 2007
iya aje:

alo ooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooo,
o dun pa po po pa po po po pa po po po praaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaa,
kini o?

ibon ni o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bolorunfem(f): 9:03am On Sep 25, 2007
E ku afere yi o, gbogbo omo kaaro o jiire, se alafia ni mo ba yin, se oode o so? Mo ki yin pe e ku ojo meta, Ayanjide, Richylaw, Ika mefa (Olugbodi ko niyen? ), iya aje, debosky, gbogbo eyin to ku patapata ni mo ki o. Se gbogbo yin nbubble? Ni se ni mo sare lo si oko etile ni ko je ki e ri gburo mi. Se e si mo pe ero ayara bi asa ko de abule grin grin. Eyin ti oke okun lohun, se otutu o po? Gbogbo wa ni a o ko ere oko dele o.
E heen, ta lo ba wa gburo Segoye2 o? O dagbere pe oun fe rin irin ajo, mo lero pe o ye ko ti pada. Ti e ba pade re lori okun miran yato si eleyi, e ba mi so pe mo beere re o. Mo riyin na, o digba kan na
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by buttyelele: 12:24pm On Sep 25, 2007
Suggestion: Bi o tile je wipe oro isiri ati onilaakaye ni o ti ko sile, iba dara ki o tumo gbogbo ohun ti o ko si oke yi si ede yoruba, bi iwo na ba bere pelu apere rere ko ti buru ju.Oyinbo tabi ede geesi ko ni aagbon okun oro yi wa fun



apere temi ko ni o se pataki, ti ko ba se opolopo awon eniyan ti ko le so ede abinibi won, papa ju lo, ede yoruba. A le so yoruba di ola, oto oro ni pe opolopo awon eniyan ni gbogbo nkan ti a ko si nairalandi yi ko ye, ko se nipa kiko orin shina peters tabi sunny ade ni afin gbo yoruba. iwo na mu akole gidi wa ka si jiroro lori re.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 3:18am On Sep 26, 2007
eniba she ha!

enu e aya o!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 7:01pm On Sep 26, 2007
tafari:

ibon ni o.
o si o,gbogbo yin e kan niko lori grin
debosky:

iso (fart) ni o, lati idi nla iya aje grin grin grin

se mo gbaa abi mio gbaa?
o gba o,
e patewo fun omo ita agbalagba,o ti pe to ti nfi iso soge larin awujo wa ni nairaland grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 2:55pm On Oct 02, 2007
buttyelele:

apere temi ko ni o se pataki, ti ko ba se opolopo awon eniyan ti ko le so ede abinibi won, papa ju lo, ede yoruba. A le so yoruba di ola, oto oro ni pe opolopo awon eniyan ni gbogbo nkan ti a ko si nairalandi yi ko ye, ko se nipa kiko orin shina peters tabi sunny ade ni afin gbo yoruba. iwo na mu akole gidi wa ka si jiroro lori re.

Ohun ti mo n so ni wipe ki o ye ra fun ede geesi ni ori okun yi gegebi eyi ti o koko fi gbe eronu re kale ninu oro ti o fi sowo si ori okun ni akoko.
Nipa akole ti o d'amoran ko buru rara gege bi aba sugbon mo mo wipe asiko le e ma si fun o lati ka ohun gbogbo to wa lori okun yi lati oju ewe kini, iwo o ba ti ri akitiyan lati se bi o se n fe ( bo tile je wipe ara n fu mi wipe awodi re kan pa aso esin da ni). Opo igba ni a ti daba akole, opo igba ni awon ti o ni arojinle na ti gbe koko yi yewo , sugbon niwon igba ti oronro ba ti n fo po mo eran adun re a ma soro ri.
Opo eniyan ni abara meji lori okun yoruba yi, won ni oruko ti won fi n hu iwa buburu, won si ni eyi ti won fi n fi oye inu won han. Sugbon niwon igba ti nomba idanimo(IP Address) wa fun ero ayarabiasa ti onikaluku, awon aseto n je ki a da iru won mo.
Emi gegebi enikan , yala ni igba kan tabi omiran mo ti mu aba akole orisirisi wa , ko si si eyi ti o mu ogbon dani ti enikeni da laba ti n ko da si. Opon oro ni o wa ni iwaju iwo na yi, da ifa tire na sile ko je ki a gbo ohun to ba wi nipa akole.

Gbogbo ile, eku ojo meta e si tun ku ko le da o. Bolorunfem e seun o eku ibeere mi. Emi na o ti gburo Segoye2 o, o da mi loju wipe ko le e wa larowoto ki o ma kan si ori okun ti o fi owo ara re da sile. E je ki a mu suuru ka si ma woye titi ti yio fi de.

(1) (2) (3) ... (115) (116) (117) (118) (119) (120) (121) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 41
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.