Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,198,731 members, 7,969,125 topics. Date: Monday, 07 October 2024 at 08:17 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (381697 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (124) (125) (126) (127) (128) (129) (130) ... (167) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kolaoloye(m): 1:58pm On Mar 11, 2008 |
Ojogbon, E SEUN ti e gba mi towo-tese. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by metodman(m): 2:03pm On Mar 11, 2008 |
E kabo oooooo , Ni Oluro gbogbo Ode (Hunters) ti ile yi at ni oruko baale ati Olori ati Asiwaju, a ki yin kabo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 3:11pm On Mar 11, 2008 |
Hello! Olori Desola,Ose. . .O ku iranti. . . Bawo ni gbogbo eyin omo oduduwa? S'alafia ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrFerlie(m): 3:39pm On Mar 11, 2008 |
kola oloye: A ki dupe ara eni. e ma jina siwa ninu ilu yii o metodman: olu ode metodman, gbogbo awon ode tokun nko? nje mo le ri eran oya(grasscuter) ati etu (antelope) ra ni owo yin? nana: arabinrin nana, alaafia ni awa oooooooooooo. e ku ojo meta |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kolaoloye(m): 5:04pm On Mar 12, 2008 |
E KAAASAN NILE O. Bawo ni ise oni o? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrFerlie(m): 9:14am On Mar 14, 2008 |
E kaaro oooooooooooooooooo omo ooduaaaaaa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by metodman(m): 1:57pm On Mar 14, 2008 |
Asiwaju, ko si eran oya lasiko yi o, Baale awon Oya ku, gbogbo oya nigbo lo nse idaro baba won, Sugbon, laipe yi, awa ode nlo si oko ode fun ose kan ni igbo nairaland, Mo fi da yin loju wipe, e o ri eran oya ra nigba yen, |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by metodman(m): 2:00pm On Mar 14, 2008 |
Asiwaju, ko si eran oya lasiko yi o, Baale awon Oya ku, gbogbo oya nigbo lo nse idaro baba won, Sugbon, laipe yi, awa ode nlo si oko ode fun ose kan ni igbo nairaland, Mo fi da yin loju wipe, e o ri eran oya ra nigba yen, E ma binu si wa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrFerlie(m): 8:36am On Mar 17, 2008 |
olu ode metodman A jibi? gbogbo ile nko? Oodua agbe wa oooooooooooo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by metodman(m): 6:51am On Mar 18, 2008 |
Asiwaju, E karo o, |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by opuro(m): 11:02am On Mar 18, 2008 |
eku ijo melo kan o eyin omo odua awon abenilori ti be ettegate lori o koda won yin ibon fun osereka adupe pe opuro si wa kampe! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Fileki(f): 7:26pm On Mar 22, 2008 |
a ku odun ojo ibi, Mohammad ta se koja, a si ku odun ajinde bakana. se alaafia sa ni gbogbo wa wa, nitori n ko gburo awon eniyan lo titi. ire gbogbo ko ma wa wa o Kabiyesi, ODe metodman, Dr ferlie, Aya Oloye desolar, Otunba Debson, gbogbo eniyan pata ni mo ki o. ilu yi ko ni baje o Ase. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dominique(f): 2:13pm On Mar 23, 2008 |
amin o aku odun aku iyedun awon omo leyin kristi ni nairaland emi a se opolopo odun layo ati alaafia o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 2:20pm On Mar 23, 2008 |
dominique:amin o. . .same to you. . .Olorun afi ojo odun wa di ojo ayo ati ojo ore |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debson(m): 5:17pm On Mar 24, 2008 |
Mo ki gbogbo ara ilu pe "Eku odun o" Emi a she opo odun laye o! Baale, (oko ilu) kara o le baba. Mo ki gbogbo oloye ilu pata lai ku enikan. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kolaoloye(m): 8:40am On Mar 25, 2008 |
Mo ki gbogbo omo Oodua ku abo lehin odun Ajinde. Se alafia ni gbogbo ile wa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dominique(f): 11:21am On Mar 25, 2008 |
e se o , alaafia ni gbogbo ile wa, adupe lowo olorun, |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by djcrucifix(m): 3:07pm On Mar 25, 2008 |
oruko mi ni oluwamayowa, omodun meji din ni ogun nimi, omo eko latile ni wa, a de ron yin nise, |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluehorizo(m): 3:18pm On Mar 25, 2008 |
Mo ki dede omo Oduduwa ti'le to'ko. Igab yi a tu wa lara lola Oluwa. Dede omo Lisabi Agbomgbo Akala,mo ki yin ooo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kolaoloye(m): 3:51pm On Mar 25, 2008 |
@bluehorizo, Se pe omo egba re ye? nko de mo li a pade lori apero yen. Se o ko binu. Oruko re yi ne ko je kara fu mi,oruko nla yi gaju. Adura dede wa re ma gba o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 4:22pm On Mar 25, 2008 |
ba wo ni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluehorizo(m): 4:33pm On Mar 25, 2008 |
kola oloye: Baba Oloye,n ko binu rara. Se dada li dede ile wa? Apa ibo si ni'le yin wa l'egba? Li to oruko yen (bluehorizon),won ko ko tan ni. I nu mi dun, ayo mi kun pe mo r'omo egba mo'lisabi lori apero yi. E ba mi kile . Egba a gbe wa ooooooooooo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluehorizo(m): 11:30am On Mar 26, 2008 |
E kaaro dede Omo Oduduwa. A jiire bi? Aa da fun dede wa. Adura wa a gba. oju o ni ti'wa. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by metodman(m): 9:00am On Mar 27, 2008 |
enle be ye oooooo, mo ki baale (kaara o le baba) ati gbogbo aroro shasha ilu yi ooooo, Omo egba lemi na sugbon mi o gbo ede yen daada Emi omo Ake majo Eru ni sinni, eko kin sin niyan Omo Ake lemi, oko wa , wani odeda |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kolaoloye(m): 9:15am On Mar 27, 2008 |
Oruwo mi ti dara,awon eniyan mi po libi E kaaro o,se daada re gbogbo wa ji? E je ka ma se jeje o.Egba a gbe wa o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by metodman(m): 9:22am On Mar 27, 2008 |
nibo ni egba ni eyin ti wa oo ? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 9:59am On Mar 28, 2008 |
E ku ojumo lori itakun yi o, se gbogbo nkan n lo deede, OODUA a gbe wa o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by gbolah1(m): 12:35pm On Mar 28, 2008 |
Asamo ni emi fe so nitemi, to di ifa fun eniyan to tori anlosi ofa, to ta ara ile re lofa, koranti pe bi ofa ko ba se lomo, a ranti mode moe ejekawatunso |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Jiboo(m): 12:43pm On Mar 28, 2008 |
e yin temi, ki lon sele l abule wa naija, e je kia so wo po lati gbe Naija dide si inu imole aiye ati iran lowo olorun wa. e je kia ma se dada nitori pe ikan ti wan pe ni HIV/AIDS wa ninu aiye ti an gbe, mo si fe ka ma ba arawa ja nitori pe nkan na la jo wa. O da bo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:55pm On Mar 28, 2008 |
Mo ki gbogbo ara ilu o. Gbogbo awon oloye, eyin otokunlu, eyin abenugo oro, gbogbo borokini apede lenu bi eni je suya, koda gbogbo opuro to ri bi won se n be ni lori lagbala ijoba ni mo ki patapata o. A o ni te o a o ni run o a o ni d'ibaje o Pese niiro koko lagbala, aye wa a ma ro wa lorun ni o Ero pese ni t'igbin, a o ni je ika abamo ninu irora o. Ki Ilu yi le tu ba , ki o si le ma tu'se na ni a n ba kiirii o Dr Ferlie, e ku akitiyan, Metodman oluode, a rin pa n t'ogun o Asiwaju, abobajiro, arole gbogbo yin ni mo dupe lowo yin e ku imule dani o Ayanjide, adehun re ni wipe o o kan si mi laafin , n o ri o o se ko si nkan. JIBOO: Ibi pelebe bayi ni a ti n mu olele je o, ojo-ojo kan n bo ti ohun ti o to, n bo wa di opo. Nipa ti arun kogboogun ti n je kurugbe, ki alawurabi ki o gba omo niyan ni o. Sugbon bi a ba wo daadaaa a o ri wipe afowofa omo eda ni o. IKORA ENI NI IJANU SI NI ONA ABAYO. IRE Baale of Yoruba Thread, Nairaland Richylaw |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by metodman(m): 8:05am On Mar 29, 2008 |
baale, kara o le o. Eku ojumo, e pe pe pe pe pe pe pe pe pe bi pepe nti pe, Asiwaju dokita, Olori, Erelu ati gbogbo borokini mo ki yin oooo ILU YI KO NI DARU NIGBA TIWA OOOOO ASE! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 5:31pm On Mar 29, 2008 |
wish i could speak it fluently |
(1) (2) (3) ... (124) (125) (126) (127) (128) (129) (130) ... (167)
Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady
Viewing this topic: 1 guest(s)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 30 |