Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,198,454 members, 7,968,248 topics. Date: Sunday, 06 October 2024 at 09:59 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (132) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (381659 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (129) (130) (131) (132) (133) (134) (135) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 7:36pm On Jun 02, 2008
Hello House,

I really missed you all. Am finally moving back to Nigeria to setup my office and business. I will tell you more on it later.

Baale, Eku ise ilu wa ooo. Iyawo mi, ku ise ribi ribi ti on se oo. I nu mi dun nigba ti mo ri awon aworan ile ati ibi ise ti oti bari yen. ko si aya miran ti o dabi tire. Mo ni fe e gan ni (I love you).

Mo n bo.

Segoye
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by coldwater(m): 9:16pm On Jun 02, 2008
toyinrayo:

Omo Ekiti ( 100%) ni mi jare. . .
Ilawe ekiti, ni bo niye?
me, Ado/ Ikun ekiti wink

ekiti kete. bawo ni? se acada nlo.? se e ngburo awon ara ile o . ao ko ere oko dele grin grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluehorizo(m): 7:22am On Jun 03, 2008
Ojumo ti mo Ojumo ti mo mi ni le yi ooo

Ojumo ti mo,mo rire oooooooo

Eye Adaba Eye Adaba

Eye ti n fo loke wa ba le mi ooo

Ojumo ti mo,mo rire ooo


Ki ire ma ba gbogbo wa gba gbe. Ki alaafia Olorun ki o joba ninu aye olulukulu wa. Iba oo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kolaoloye(m): 10:42am On Jun 03, 2008
E ku owuro,gbogbo ile. Se daada ni a ji?

bluehorizo:

Ki ire ma ba gbogbo wa gba gbe. Ki alaafia Olorun ki o joba ninu aye olulukulu wa. Iba oo
Alale ile yi yoo gbe o (ase)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by replenish(f): 12:41pm On Jun 03, 2008
Eku owuro eyin omo yoruba gbogbo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 6:38pm On Jun 03, 2008
coldwater:

ekiti kete. bawo ni? se acada nlo.? se e ngburo awon ara ile o . ao ko ere oko dele grin grin grin grin
lmao
oko nibo? grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kolaoloye(m): 9:25am On Jun 04, 2008
toyinrayo:

lmao
oko nibo? grin
Oko ni isale tabi oke oyan oya
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 11:34pm On Jun 06, 2008
kola oloye:

Oko ni isale tabi oke oyan oya
why do you ppl turn every discussion to sex? are you sex deprived? undecided
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluehorizo(m): 2:41am On Jun 07, 2008
E n le ni be yen ooo. Se alaafia ni o. Mo ki gbogbo wa pe a o ko ire oko dele oo. Amin ase.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Emkayotis(m): 3:24am On Jun 07, 2008
Ekale eyin omo Oduduwa.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kolaoloye(m): 10:43am On Jun 09, 2008
E KAAARO O GBOGBO ILE. E SI KU POPO-SISI ASIKO YI,OODUA YO GBE WA O amin
@toyinrayo,
Kaka ki o soro ni ede yoruba,o wa da oyinbo bole bi opeere.
Alaye nipa oro 'oko':
Ti eniyan ba kuro ni ilu abinibi re lo si ilu miran fun oro aje,ibi ti o wa yen ni a npe ni oko tabi idale
awon miran a maa so nipa oke okun tabi oke oya. Gbogbo awon nkan wonyi ni a npe ni oko.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluehorizo(m): 4:41pm On Jun 10, 2008
E n le ni be yen oo. Se daadaa la ba'le? Ki alawura oba oke gbo adura gbogbo wa ooo. Mo ri yin na.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by lalaboi(m): 6:45pm On Jun 10, 2008
evrybody somo! kile n duro wo?? c'mon somo!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluehorizo(m): 10:13am On Jun 12, 2008
Good morning sir, adupe pe mo gbo'yinbo oooo

Oyinbo mu tii, baba mi n m'eko

Oyinbo n mu beer, baba mi n m'oguro


Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by akym(m): 5:56pm On Jun 12, 2008
Eweso ni le ooo,se alafia ni dede ara ile waa? sii mo un koja lo kim kan sofo kin mi kii dede ara ile oo.
Ede ku amumora ilu waa ilu NAIJIRIA oo. Eledumare OBA-OKE ako gbogbo wa yo o.
E ku ilede BABA-IBADAN oo. Iwaju roun ko ju sii adara EYIN ronu fi le ni baje. AMIN.


ABOMI REE O.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by coldwater(m): 11:19pm On Jun 12, 2008
eyin omo OODUA.

A KU ASEYIN DE BABA WA OLOOGBE OLOYE LAMIDI ARIYIBI ADEDIBU

EYIN BABA A DARA O.

A O MA FI ETO ISINKUN TO YIN NI ETI NI AI PE.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 11:21pm On Jun 12, 2008
ti eniyan rere ba ku, awon ara ma korin

'ile lo lo tarara, baba lo le oh, ile lo lo tarara'

sugbon nigba ti Adedibu soda si apa keji aye orin ti awon aye nko ni

'ina lo lo tarara, baba ti lo jo na oh, ina lo lo tarara' cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MyTempID: 7:36am On Jun 13, 2008
Don't you think they're being a little hypocritical?  I know not too much about the man so I can't really say much. The loss of a human life, in general, is grave.  I'm sure he has family, children, and friends who are pained by the loss.

My heart goes to them and I hope God gives them the might to cope with the loss.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kolaoloye(m): 9:02am On Jun 13, 2008
MyTempID:

Don't you think they're being a little hypocritical?  I know not too much about the man so I can't really say much. The loss of a human life, in general, is grave.  I'm sure he has family, children, and friends who are pained by the loss.

My heart goes to them and I hope God gives them the might to cope with the loss.
E jowo talo ni opeere?

LEHIN IKU ADEDIBU,ILU IBADAN A ROJU (amin) Ile wa a dara o (ase)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluehorizo(m): 10:43pm On Jun 13, 2008
E jowo talo ni opeere?[/size]

Mi o le rerin oo grin grin grin



LEHIN IKU ADEDIBU,ILU IBADAN A ROJU (amin) Ile wa a dara o (ase)

Baba yen gbi yanju gaann ni. O ku ibi ti Akala fe gbe gba bayi. Gbogbo awon ti won n te ofin loju ni'te kute daran. Ti won ba won bayi. Okan awon ara ilu Ibadan se bale bayi ni. Sugbon,ki ile to pa osika,ohun rere ati baje. sad sad sad
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Dangello(m): 10:49pm On Jun 13, 2008
abi o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MyTempID: 10:56pm On Jun 13, 2008
All I was saying is, have some compassion for the dead. If that makes me an 'opeere', whatever. I presume if it were your dad you wouldn't be so jubilant.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tinakoya(f): 11:00pm On Jun 13, 2008
MyTempID:

All I was saying is, have some compassion for the dead. If that makes me an 'opeere', whatever. I presume if it were your dad you wouldn't be so jubilant.

E jowo yoruba ni a nso ti ibiyi, e je ka gbe ede wa laruge, abi ewo ni ti geesi.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 3:12am On Jun 14, 2008
Nje a ko tie ni wa ona late le awon elede geesi yi si igbo na abi kini ka ti pe e? Won wa ko awon baba wa leru laye ojo wun, a gba ara wa kuro loko eru tan a da iyara ijiroro sile ni ede abinibi wa sibe sibe naa, awon kan si tun n gbe ede geesi ohun wa si ibi. E lo so ara yin o eyin on geesi, ede abinibi ti wa ni a n gbe laruge nibi o, Emi ni tiyin ni tooto: Ojulowo Omo Yewa lati ipinle Ogun ni Orile-ede Naijiria ni ile Afirika (alawo dudu)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MyTempID: 3:39am On Jun 14, 2008
Hey, hey, hey take it easy with the yorubanics man. I'm not attempting to pilot the away from the Yoruba speaking medium. I was only responding to a few things I observed about the death of Mr. Adedibu.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 9:36pm On Jun 14, 2008
debosky:

ti eniyan rere ba ku, awon ara ma korin

'ile lo lo tarara, baba lo le oh, ile lo lo tarara'

sugbon nigba ti Adedibu soda si apa keji aye orin ti awon aye nko ni

'ina lo lo tarara, baba ti lo jo na oh, ina lo lo tarara' cheesy

debo, you try o. . .but which site did you copy and paste that? grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by NegroNtns(m): 9:41pm On Jun 14, 2008
Ogbeni Debo,

Itunu ama ba e oo.  Oje eni kan t' ol' oyaya.  Ni gbati mo ka orin olongbe Adedibu, mo rerin titi gbogbo pari ni ndun mi.

Kosi nko taba wi jupe ki baba gbe s' afefe rere.  Eni ba s' alaisi, ni dada laman soro re.

Ire ooo
Ogbeni Dudu
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 9:48pm On Jun 14, 2008
Ogbeni Dudu

eni ti ba se rere nigba ti o ba wa l'aiye ni a maa n'soro rere ti o ba so da si apa keji

sugbon awon ti won ba se buburu si awon omo l'akeji won, ko si bi a se ma korin rere ni pa won.

idi ni pe a nilo late fi awon oniwa buruku se apeere (example) fun awon eniyan ti o si wa l'aiye, ki awon naa ba le wuwa rere.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 9:58pm On Jun 14, 2008
debo. . omo dudu, omo pupa rodorodo bi ororo pupa grin
omo aguntan tin gboron simile nu
tin bati kpe e. . gboron simi lenu
debo!! debo!!

idi ti mofi kpe eni wipe mofe ran e nise
mofe kola si odo iya basiru cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 10:03pm On Jun 14, 2008
Iya basiru nikan ni? Iya sikira nko? tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 10:04pm On Jun 14, 2008
ahhh. . okudie kin gbagbe!
ose n omo mi da da!

lo si odo iya sikira ati iya shakira nah. . .
ose n jare wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by NegroNtns(m): 10:05pm On Jun 14, 2008
Ara' kurin, Oro agba lo so yen oo!

Omoluabi (Omo ti Noah bi - descending from a moral background) o gbodo se jagidi jagan.  Awon agba won ani,  ori Ade, ori ola. Eyi ti Adedibu fi se ori o pansaga.  Abo ree lan ri yi.  Ko si enin soro re nire.  Babaloke ko towa s' ona ara.  

Ara' birin 4HER, gesi (english) poju.  Se dada ni o?

(1) (2) (3) ... (129) (130) (131) (132) (133) (134) (135) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 33
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.