Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,223,062 members, 8,054,005 topics. Date: Wednesday, 15 January 2025 at 09:51 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ogun Ti Afi Nwe Osi Kuro Lara , Ti Kofini Bani Wo Inu Odun Tuntun (3349 Views)
Ogun Ti Afi Nri Owo Ni Irorun / Ogun Ti Afi Ngbe Aye Ni Irorun Ati Ogun Korikosun To Gbona Gan / Ogun Ti Akoba Fe Ki Okunrin Tabi Obinrin Loju Miran Leyin Eni (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Ogun Ti Afi Nwe Osi Kuro Lara , Ti Kofini Bani Wo Inu Odun Tuntun by Laniretiawoagba: 2:01pm On Dec 26, 2018 |
ewe peregun ati egbo ree, ewe tude ati egbo ree ao fi ako okuta tele inu ikoko , ao ko a won ewe ati egbo yen lelori, ao buu omi tootoo wee sii, ao gbe ka INA , toba ti hoo oti jinna niyen, ao so kale ,ao yoo sinu ike omi iwee, ao gbe sibi kan,ewe ati egbo yii toba seku lao figun ose dudu kekere, ao lemon aso pupa , tori oun lama fise kahin kahin ree, ao ge aso pupa teere merin ao so Mon APA ati ESE waa, ao mafi ose yen wee pelu agbo yen, pelu wiwi bayi pee, Aso pupa kiiba oku woo saare, idamu wahala airije airimu airina airilo koma bami WO inu odun tuntun, 08037492173 |
(1) (Reply)
Do You Have The Right To Accuse Me Of Being Westernized? / If Women Have No Rights! A Questionnaire / Was Hausa Language Extracted From Arabic ?
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2025 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7 |