Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,217,479 members, 8,034,343 topics. Date: Saturday, 21 December 2024 at 04:57 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Tani Jesu Nse? - Jesu Ni Oluwa Ti Nyan Iranse Ati Eleri (551 Views)
Tani Jesu Nse? - Jesu Ni Olorun / Tani Jesu Nse - Jesu Ni Eni Ti A Fi Ami Ororo Yan / Jesu Ni Ajinde Ati Iye (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Tani Jesu Nse? - Jesu Ni Oluwa Ti Nyan Iranse Ati Eleri by Primate7: 10:52pm On Mar 13, 2019 |
TANI JESU NSE? JESU NI OLUWA TI NYAN IRANSE ATI ELERI. ISE AWON APOSTELI ORI KERINDINLOGBO ESE KEDOGUN TITI DE IKETADINLOGUN SO WIPE: 15. Emi si wipe, Iwo tani, Oluwa? Oluwa si wipe, Emi ni Jesu ti iwo nse inunibini si. 16 Sugbon dide, ki o si fi ese re tele: nitori eyi ni mo se farahan o lati yan o ni iranse ati eleri, fun ohun wonni ti iwo ti ri, ati ohun wonni ti emi o fi ara han fun o; 17 Emi o ma gba o lowo awon enia, ati lowo awon Keferi, ti emi ran o si nisisiyi, LATI INU BIBELI MIMO (13/03/2019) |
(1) (Reply)
Breaking: See What COZA Pastor Biodun Fatoyinbo Is Offering / Historical Watchtower Development Of Jehovah’s Witnesses Disfellowship / Nigerians Reacts To Video Of Pastor Sleeping With Wife And Daughter Of Churc
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6 |