Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,188,310 members, 7,934,233 topics. Date: Wednesday, 28 August 2024 at 09:21 PM

Ẹdẹ - Literature - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Literature / Ẹdẹ (345 Views)

(2) (3) (4)

(1) (Reply)

Ẹdẹ by shakir0802: 6:06pm On Jun 24, 2021
Èrò tó ń lọ ìlú Ẹdẹ
Èrò tó ń lọ ìlú Ede ọmọ ajilala ọ̀sọ́ ẹ bá mi kí Oloye Dèjì Adérẹ̀mí pé wọn kú Agba ó, Ọlọ́fà Iná ni gbogbo aráyé mọ yín sí ọpọ kò tiẹ̀ mọ pe Olóyè ilu niyi n'ilu Isẹnbaye Ẹdẹ ìlú tí ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn ńláńlá ti jáde wa lati ọjọ to tí pẹẹ.
Àmọ́ ẹyin Agba na lẹ wípé "ó pẹ́ láyé ojú rẹ koni ribi ọkàn lo fọwọ́ mú"
Àbí nigbati irú ẹgbẹ́ ọmọ ọmọ Baba Oloye bá ń sọ fún bàbá Ọlọ́fà Iná pé "Baba ẹ bọlẹ nbẹ" ṣe a rí pé ó burú jáì, àmọ́ agba mọ ń gba nkan mọ́ra ni.
Nínú àwọn àgbà osere to gbọ́ èdè Yorùbá yanjú ni Olóyè Dèjì Adérẹ̀mí (Ọlọ́fà Iná) wa kódà èmi Aare Laji Abbas gan mú nínú omi ọgbọ́n Baba dada yí nítorí tí bàbá yí bá ń sọ̀rọ̀ ọ̀rọ̀ kan òwe kan ni, kò fi bẹ dájú pé àwọn tó gbọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá yanjú bí Oloye Dèjì Adérẹ̀mí Ọlọ́fà Iná sí pọ to nkan nilẹ Yorùbá mọ.
Àmọ́ nigbati ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àti Ọsun kùnà láti ń ṣe nkan ribiribi láti gbé orúkọ Baba yí ga pelu bubu ọlá fún ẹni tí ọlá yẹ ewo ni Iyabo Ojo koni rí Baba yí fín si.
Àmọ́ baba Oloye Agba tí kò bínú lọmọ rẹ ń pọ, ìṣù ẹni lọ ń tí ọwọ ẹni bọ epo.

Re: Ẹdẹ by parkervero(m): 6:53pm On Jun 24, 2021
Omo aji lala osho Omo aji fojo gbogbo dara bi igbin

1 Like

(1) (Reply)

Beautiful Day To Die Young (Short story by Danny Walker) / THE LIFE NO ONE EVER KNEW***FULL READ ✒✒✒ / Hilarious But Sad

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.