Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,193,616 members, 7,951,554 topics. Date: Tuesday, 17 September 2024 at 06:16 PM

Omi Iye Naa (CAC Living Water) 18th October 2021 - Religion - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Omi Iye Naa (CAC Living Water) 18th October 2021 (301 Views)

Omi Iye Naa (CAC Living Water) October 15, 2021 [yoruba] / Jesu Ni Ajinde Ati Iye / Ifa Naa Ki Bayi Wipe: Òkàn Sá (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Omi Iye Naa (CAC Living Water) 18th October 2021 by ChristianFeeds: 10:59am On Oct 18, 2021
Akori: Mase Wipe 'ko Le Seese Nisinsin Yii (1)

Ka Danieli 6:1-5, 10-16

Akosori: Nigba naa ni awon okunrin wonyii wi pe, awa ki yoo le ri esun kan si Danieli bikose pe a ba ri I si I nipase ofin Olorun re (Danieli 6:5)

ITUPALE

O to lati soro nipa jije mimo nipa Ibalopo ati titona dagba ni ona ti o ye ni awon ile ajeji. E je ki a soro nipa ilowosi ninu ise ijoba ati iselu ni ile ajeji tabi ibugbe to jina si ile eni gan! Danieli ni koko itokasi wa.

Danieli ati awon ore re Heberu meta je ara awon omodekunrin, koda lati idile oba ti won ba ara won ni Babiloni (Igbekun), sugbon ti a mu won wonu sise ise fun oba ni ona iyanu ati pelu eto atorunwa. Ipa ati okiki omodekunrin eru yii n po gidigidi debi pe oba fi I se olori awon olori. Eyi gan-an ni o sokunfa owu jije ati ikorira lati odo awon yooku ti won ko le so/tokasi orisun aseyori ati idide re, eredi ti won fi gbimo po lati fi mu un niyii. Won fe da a lekun lati mase sin Yahweh mo, eni tii se Orisun agbara/okun re.

https://www.thechristianfeeds.com/2021/10/omi-iye-naa-cac-living-water-mase-wipe.html[left][/left]

(1) (Reply)

Osinbajo, Ada-george, Dickson Eulogise Diri At Bayelsa Thanksgiving / Are Christians Against Alcohol? / Nigerian Pastors And Conflicting "Prophecies"

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 8
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.