Stats: 3,169,749 members, 7,875,877 topics. Date: Sunday, 30 June 2024 at 12:30 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Cac Hymn 329 Please Try To Read It (453 Views)
What's Your Favorite Hymn? / Story Behind The Hymn, "When I Survey The Wondrous Cross" / When You Try To Take A Selfie In Church (Photo) (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Cac Hymn 329 Please Try To Read It by Odebayo4010(m): 10:46am On Apr 09, 2023 |
Jesu ye titi aye, Eru iku ko ba mi mo; Jesu ye; nitorina Isa oku ko n'ipa mo — Aleluya. 2. Jesu ye, lat' oni lo, Iku je ona si iye; Eyi y'o je 'tunu wa 'Gbat' akoko iku ba de — Aleluya. 3. Jesu ye; fun wa lo ku, Nje Tire, ni a o ma se; A o f okan funfun sin, A o f'ogo f'Olugbala — Aleluya. 4. Jesu ye; eyi daju, Iku at'ipa okunkun Ki yo le ya ni kuro Ninu ife nla ti Jesu — Aleluya. 5. Jesu ye; gbogbo 'joba L'orun, li aye, di Tire; E je ki a ma tele, Ki a le joba pelu Re— Aleluya. Amin 1 Like
|
(1) (Reply)
“we Are Not Living Well” – Family Of Late Deborah Samuel Cry Out One Year After / Dreams And Talk / Why Do Theists Quote Scriptures For Atheists?
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6 |