Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,182,389 members, 7,917,236 topics. Date: Saturday, 10 August 2024 at 08:36 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán (3544 Views)
Àwọn Èso Ati Irúgbìn Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Awòrán / Transportation In Yoruba Land (àwọn Ọ̀nà Tí À Ń Gbà Rin Ìrìn Àjò) / Ònkà - The ABC Of Yorùbá Numerals (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (Reply) (Go Down)
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:24pm On Nov 14, 2023 |
Tọnátọná Alẹ́ — Firefly 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:30pm On Nov 14, 2023 |
Gúlúsọ/Kúlúsọ — antlion larva Popular Song: Gúlúsọ, Gulúso Abiamọ Gúlúsọ Gúlúsọ, Gúlúsọ Abiamọ Gúlúsọ 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:37pm On Nov 14, 2023 |
Yínmiyínmi/Yígbẹ̀yigbẹ̀/Ogidi/Ogidimo/ — Popular Proverb: 1. A kìí bá yínmiyínmi du'mi, A kìí bá Àtẹ̀lẹ̀sẹ́ du Ọ̀nà 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:44pm On Nov 14, 2023 |
Ayítalẹ́ — Popular Saying: 1. Ikú ọmọ L'o un pa Ayítalẹ́ Does anyone have a picture of this animal? I can't seem to find it, And to be honest, I have never seen it before! And what is the English name? |
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:47pm On Nov 14, 2023 |
Àiná Ọlọrun — Popular song: Àiná saré tete ogun un bọ̀ Àiná saré tete ogun ùn bọ̀ I can't find the picture for this too and the English name! |
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:52pm On Nov 14, 2023 |
Àrígiṣẹ́gi — Woodcarrier
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:53pm On Nov 14, 2023 |
Tata — Grasshopper
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 2:17pm On Nov 14, 2023 |
Ìdin — Maggot
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 2:35pm On Nov 14, 2023 |
Dákódákó/Damọlóko — Mantis
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 2:39pm On Nov 14, 2023 |
Lámilámi — Dragonfly Popular Saying: 1. Àlọ Lámilámi L'aa ri, Ẹnìkan kìí ri àbọ̀ rẹ̀
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 3:13pm On Nov 14, 2023 |
Ọká — Gaboon Viper Popular Saying: 1. Ọmọ Inú ọká Ni ùn Ṣe ikú p'ọká
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 3:18pm On Nov 14, 2023 |
Paramọ́lẹ̀ — Puff adder/Night adder
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:38pm On Nov 14, 2023 |
Òjòlá/Òṣùmàrè — Python
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:44pm On Nov 14, 2023 |
Erè — Boa Constrictor
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:59pm On Nov 14, 2023 |
Olúfà — Anaconda
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:04pm On Nov 14, 2023 |
Ṣèbé — Spitting Cobra 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:17pm On Nov 14, 2023 |
Isán — A species of snake, But I can't find the picture on the internet and the English name too! |
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:19pm On Nov 14, 2023 |
Nìnì — A specie of snake, I can't find a picture on the internet and, I don't know the English name! |
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:21pm On Nov 14, 2023 |
Béwérẹ́/Abéwérẹ́ — Jameson's Mamba 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:35pm On Nov 14, 2023 |
Àgbàfúùfú/Gbàgbàfúùfú — Rattlesnake 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:36pm On Nov 14, 2023 |
Àgbadú — Black mamba 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:52pm On Nov 14, 2023 |
Ọ̀ṣa — A specie of snake, I can't find a picture on the internet, and I don't know he English name Will be updated as soon as I get it |
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 6:01pm On Nov 14, 2023 |
Mọ́námọ́ná — Ball python 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 7:42pm On Nov 14, 2023 |
Ọgbá/Gbaragogo — A specie of snake, I can't find a picture on the internet, and I don't know he English name Will be updated as soon as I get it |
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 7:51pm On Nov 14, 2023 |
Ọ̀ghọ́ta — Rhinoceros Viper/Bitis nasicornis A specie of Viper 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:00pm On Nov 14, 2023 |
Abìrùṣoró — Boomslang 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:08pm On Nov 14, 2023 |
Ọ̀ọ́rú/Ọ̀wọ̀rú — Forest cobra 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:13pm On Nov 14, 2023 |
Ọ̀wùn — Black-necked Spitting Cobra 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:23pm On Nov 14, 2023 |
Komo — Boaedon NB: I don't know how it's pronounced! 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:40pm On Nov 14, 2023 |
Ọ̀kùn — Millipede 1 Like 1 Share
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:52pm On Nov 14, 2023 |
Tanísankọ — Centipede 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 9:16pm On Nov 14, 2023 |
Ọ̀pọ̀lọ́ — Toad 1 Like
|
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (Reply)
Meet Kogi Twins Who Married One Wife / What Tribe In Nigeria Is Described As Most Promiscous? / Igbo Forum At www.igbovoice.com Where Igbo people of Nigeria world wide meet
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 14 |