Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,192,920 members, 7,949,186 topics. Date: Saturday, 14 September 2024 at 09:23 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Business / The Most Powerful Native Doctor In Nigerian (149 Views)
Native Doctor Storms His Bank To Demand Access To His Money (pics/video) / Lady Invites A Native-Doctor To Fight Bank For Wrongly Debiting Her (Video) / Dangote Makes The List Of The 2018 Most Powerful People In The World - See Full (2) (3) (4)
(1) (Reply)
The Most Powerful Native Doctor In Nigerian by arisekola11111: 2:31pm On Mar 23 |
À kìí rí ìdí òkun A kìí rí ìdí ọ̀sà Ayé kò ní rí ìdí wa o Nítorípé Ifá kan ló wí lọ́jọ́ Kínní wípé: Olúkòbínú l'orúkọ tí à á pe Ifá Ọlọ́mọ àjíyọ̀sínú ni orúkọ tí à á pe Odù Òjíníkùtùkùtù-rẹ́rìnín-la-ìlú-já l'orúkọ tí à á pe oṣù para Òòyọ ló ní tí ẹ bá rí wa kí ẹ máa yọ́nú sí wa Ẹ̀kúkú ló ní tí ẹ bá rí wa kí ẹ máa kó burúkú inú yín dànù Nítorí ẹnìkan kìí fi oyin s'ẹnu sín'tọ́ Ìlú kìí gbá ara wọn jọ bá iyọ̀ ṣ'ọ̀tá Ayé kò ní gbógun tì wa o Gbogbo ohun tí a bá ńfẹ́ ní ti rere ni ayé yóò máa fẹ́ fún wa láṣẹ Èdùmàrè Translation... The secrets of the ocean remain a mystery The secrets of the lagoon are unknowable Humans will not discover your secrets Because it is one Ifá verse that says: Olúkòbínú (the Chief without malice) isthe name we call Ifá Ọlọ́mọ àjíyọ̀sínú (a good hearted person) is the name we call Odù Òjíníkùtùkùtù-rẹ́rìnín-la-ìlú-já (someone who wakes early in the morning smiling across the town) is the name we call oṣù para It is Òòyọ who says if you see us,you should be happy with us It is Ẹ̀kúkú who says if you see us, you should discard the evil in you Because nobody holds honey in his mouth and spits in disgust A whole town does not gather together and make enmity with the salt People will not declare war on us People will not refuse our words Whatever our wishes are, provided they are good will receive the blessings of the society by the power of Èdùmàrè - Àṣẹ For more information you can call on this number+2348074260464 WhatsApp +2348074260464
|
(1) (Reply)
Benin City Mall Almost Completed / Herbert Wigwe: The Brain Behind Gtb And Access Bank Success / Top MOD LIGHTING Reviews: Is MOD Good, Bad Or Inbetween?
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 8 |